raw_text
stringlengths 2
128k
|
---|
martina ohadugha nigerian footballer martina ohadugha jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5 óṣu may ni ọdun 1991 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun river angels
|
ngozi eucharia uche ngozi eucharia uche jẹ ọkan lara agbabọọlu obinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 18 óṣu june ni ọdun 1973 arabinrin naa jẹ agbabọọlu lobinrin tẹlẹ ri ti o si jẹ ólóri coach tẹlẹ ri fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu
|
ann chiejine nigerian footballer ann chiejine jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ keji óṣu february ni ọdun 1974 agbabọọlu naa jẹ goalkeeper fun team bọọlu apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria
|
josephine chukwunonye nigerian footballer josephine chukwunonye jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 19 óṣu march ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fum swedish damallsvenskan club kungsbacka dff gẹgẹbi defender
|
nkechi egbe nigerian former football forward nkechi egbe jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin tẹlẹ rí fún órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní ọjọ́ karún óṣu kejì ni ọdun 1978 agbábọ́ọ̀lu náà ṣeré tẹlẹ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin lórí bọ́ọ̀lú gẹgẹ bí ipò iwájú orward
|
desire oparanozie nigerian footballer desire oparanozie jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ́ ede naigiria ti a bini 17 óṣu december ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun super league awọn obinrin ilẹ chineese ati team apapọ ilẹ naigiria
|
ini-abasi umotong nigerian footballer ini-abasi umotong jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lóbìnrin ti órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 15óṣu karùn ní ọdún 1994 agbábọ́ọ̀lú àlà f'ẹsẹ gbá náà ṣeré fún club lewes àti team àpapọ nàìjíríà
|
evelyn nwabuoku nigerian footballer evelyn nwabuoku jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lóbìnrin tí órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 14 oṣù kọkànlá ní ọdún 1985 agbábọ́ọ̀lù àlà gbá fẹsẹ̀ náà ṣeré fún en avant de guingamp ti french division 1 fèminine àti team àpapọ àwọn obìnrin lórí bọ́ọ̀lù
|
ugo njoku nigerian footballer ugo njoku jẹ́ agbábọ́ọ̀lú lóbìnrin órilẹ èdè nàìjíríà tí a bíní 27 óṣu kọkàǹlá ní ọdún 1994 arábìnrin náà ṣeré fún croix savoie ambilly gẹgẹ bí defender
|
johnny drille john ighodaro tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù keje ọdún 1990 tí gbogbo èèyàn mọ sì johnny drille jẹ́ akọrin àti òǹkọrin tí nàìjíríà iṣẹ́ orin rẹ̀ di ohun mímọ̀ nígbà tí ó tún orin diʼja tí àkọlé rẹ jẹ awww kọ wọ́n tí gba gẹ́gẹ́ bí ara àwọn olórin mavin records ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ a bí a sì tọ́ johnny drille ni ìpínlẹ̀ edo nàìjíríà bàbá rẹ̀ jẹ́ ọ̀gá ilẹ̀ - ẹ̀kọ́ àti àlùfáà ò ní ọmọ ìyá mẹ́rin drill bẹ̀rẹ̀ ọrin kíkọ ni ilẹ̀ ìjọosìn bàbà rẹ̀ láti ọmọọ kékeré ètò ẹ̀kọ́ ó lọ sí yunifásitì tí benin beninn níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ èdè gẹ̀ẹ́sì àti litiréṣọ̀ ìṣe tó yàn láàyò drille bẹ̀rẹ̀ ìṣe orin íkọ ni ilẹ̀ ìjọsìn ó jé ọkàn lára àwọn olùdíje àgbéjáde kẹfà tí project fame west africa ni 2013 ni 2015 ó sʼàgbéjáde ẹ̀dà orin di'ja' tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ awww eyí tí ó sì pe àkíyèsí olùdarí mavin's tí don jazzy orin àkọ́kọ́ tí ó dá kọ ní wait for me tí ó sì gbé jáde ní 2015 wọ́n yàn fún best alternative song ńi the headies 2016 ó kẹ́gbẹ́ pẹ̀lú niniola èyí tí ó jẹ ọ̀kan lára olùdíje àgbéjáde kẹfà ti wọn jọ kọ start all over ní oṣù kejì ọdún 2017 ó buwọ́ lu ìṣe orin kíkọ pẹ̀lú mavin records ní oṣù kẹsàn-án 2021 ó sʼàgbéjáde àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ èyí tí ó ní tíràkì mẹ́rìnlá tí àkọ́lé rẹ sì jẹ n 'before we fall asleep' ti o pe àwọn ọlọ́rin tí ó sì tún jé ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà ayra starr ladipoe lagos community choir donrecords chylde kwitte cilsoul and the classic afro rb group styl plus lábẹ́ the label mavin records ìgbésí ayé johnny fẹ́ adarí orin tí orúkọ rẹ ǹjẹ́ rima tahini
|
perpetua nkwocha nigerian footballer perpetua nkwocha jẹ ọkan lára àwọn agbábọ́ọ̀lú-ẹlẹ́sẹ̀ lóbìnrin tí a bíní ọjọ́ kẹta oṣù kínní odún 1976 arábìnrin náà ṣeré tẹ́lẹ̀ rí fún swedish club sunnanå sk àtipé agbábọ́ọ̀lú náà jẹ́ captain tẹ́lẹ̀ rí fún team àpapọ àwọn obìnrin ilẹ̀ nàìjíríà lórí bọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀
|
nkiru okosieme nkiru doris nk okosieme tí wọ́n bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹ̀ta 1972 ti jẹ́ adarí egbẹ́ bọ́ọ̀lù-afẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti nàìjíríà super falcons tẹ́lè rí ó sì tún ti gbá agbede méjì pápá-bọ́ọ̀lù fún egbẹ́ agbábọ́ọ̀lù gbogbo àwọn obìnrin nàìjíríà tí ó ti hàn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú àgbááyé ní ẹ̀mẹẹ̀rìn 1991 1995 1999 àti 2003 àti orísiríṣi ìdíje bọ́ọ̀lù-afẹsègbá àwọn obìnrin ilẹ̀ áfríkà pẹ̀lú ìdíje àwọn eré-ìdárayá ìgbà-òòrùn ti ọdọdún mẹ́rinmẹ́rin wọ́n fún okosieme ní orúkọ ìnagijẹ olóri-obìnrin fún ìṣe rẹ̀ láti ma rí àwọn góòlù tí ó ṣe pàtàkì pẹ̀lú orí rẹ̀ iṣẹ́ àyanṣe rẹ̀ okosieme jẹ́ adarí nàìjíríà ní eré àkọ́kọ́ tí wọ́n gbá ní ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú àgbááyé ti ọdún1991 nígbà yìí ó ṣì jẹ́ ọ̀dọ́ kékeré ó gbá gbogbo ìṣéjú 90 tí ó sọ wọ́n di olùborí nínú àwọn eré mẹ́ta ìyẹn ìgbà tó ṣì wà pẹ̀lú ẹgbẹ́ sc imo ní ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú àgbááyé ti 1999 okosieme ń gbá bọ́ọ̀lù fún rivers angels kí ifigbagbága náà tó bẹ̀rẹ̀ ó sọ pé a ò kì í ṣe ẹni tí ẹ lè fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn mọ́ o gbá góòlù mẹ́ta nínú ẹ̀mẹẹ̀rin tí wọ́n gbá bọ́ọ̀lù ní ọdún náà títí nàìjíríà fi kan ẹgbẹ́ mẹ́ẹ̀rin sí ìparí kí wọ́n tó pàdánù 4-3 fún brasil okosieme gbádùn gbígbá bọ́ọ̀lù ní amẹ́ríkà tó jẹ́ pé ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbé-bọ́ọ̀lù usl w-league àti charlotte lady eagles ó sìdara pọ̀ mọ́ ilé-ẹkọ́ gíga níb i tí ó ti ń gbá bọ́ọ̀lù-afisẹ̀gbá ti fásiti ẹgbẹ́ agbá bọ́ọ̀lù obìnrin tí ó dára jù lọ nígbà náà ni w-league jẹ́ ní gbogbo us ní 2001 nk jẹ́ ẹni kejì tó ní góòlù jù ní ncaa div ii ó ti gba agbábọ́ọ̀lù tó dára jù peach belt conference ti ọdún kan rí àti ti ẹgbẹ́ all-regional fún ọdún mẹ́rìn ó tún fìgbà kan rí jẹ́ nscaa all-american okosieme ti yege nínú ìdíje bọ́ọ̀lù-afẹsègbá àwọn obìnrin ilẹ̀ áfríkà pẹ̀lú àwọn akẹgbé rẹ̀ super falcons ní ìgbà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí ń se 1998 2000 àti 2002 arákùnrin okesieme jẹ́ ndubuisi okosieme tí ń ṣe agbábọ́ọ̀lù ilẹ̀-òkèrè
|
maureen mmadu maureen nkeiruka mmadu wọ́n bi ní ọjọ́ kèje oṣù karùn-ún 1975 jẹ́ olùtọ́nisọ́nà bọ́ọ̀lù-afẹsẹ̀gbá àti pé agbábọ́ọ̀lù agbedeméjì pápá-ìgbábọ́ọ̀lù ni tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù ó ń ṣojú avaldsnes il lọ́wọ́lọ́wọ́ ọ̀kan lára ẹgbé bọ́ọ̀lù ìpín àkọ́kọ́ tó pinlẹ̀ sí etíkun ìwọ̀-oòrun norway ó tún ti gbá bọ́ọ̀lù fún oríṣiríṣi àwọn ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù obìnrin tó dára jù lọ ìyẹn toppserien ti norway àti fún linköpings fc pẹ̀lú qbik ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù obìnrin damallsvenskan ti sweden iṣẹ́ àyànṣe rẹ̀ mmadu ti gbá bọ́ọ̀lù fún klepp il ọ̀kan lára ẹgbẹ́ toppserien ti norway bẹ́ẹ̀ ó tún ti gbá bọ́ọ̀lù fún kolbotn ní oslo norway fún àkókò ti 2010 tí ó sì jẹ́ wí pé pèlú ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ wọ́n gbé ipò kẹ̀ta ni toppserien liìgì ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kejì 2012 ó gbá bọ́ọ̀lù fún avaldsnes il ní ifigbagbága tí kò pẹ̀lú ti àkókò náà ní oslo iṣẹ́ rẹ̀ ní ilẹ̀ òkèrè ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹgbẹ́ agbọ́ọ̀lù obìnrin ilẹ̀ nàìjíríà ó sì ti hàn ní ọgọ́rùn-ún ìgbà nínú àwọn eré bọ́ọ̀lù wọn ó sì tún ti hàn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti gbogbo àwọn ìlú àgbááyé ó sì tún hàn nínú ìdíje àwọn eré-ìdárayá ìgbà-òòrùn ti ọdọdún mẹ́rinmẹ́rin ní 2000 àti 2004
|
phoebe ebimiekumo nigerian footballer phoebe ebimiekumo tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kìíní ọdún 1974 jẹ́ obìnrin àgbábọ́ọ̀lù orílé èdè nàìjíríà tó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí dìfẹ́ńdà fún nàìjíríà ó wà lára àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n wà ní àjọyọ̀ ìdíje fífà tí ọdún 1991 àti 1995 1991 fifa women's world cup àti 1995 fifa women's world cup aṣeyọri àwọn obìnrin láàgbáyé ní ọdún 1991 ati 1995
|
eberechi opara nigerian footballer eberechi opara jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 6 óṣu march ni ọdun 1976 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria lori bọọlu
|
chi-chi igbo danish nigerian footballer chi-chi igbo jẹ agbabọọlu orilẹ́ ede naigiria ti a bini 1 óṣu may ni ọdun 1986 chi-chi jẹ elere super falcons tẹleri arabinrin naa ṣere gẹgẹbi ipo forward fun fortuna hjørring
|
richard ofori goalkeeper richard ofori ti a bi ni ọjọ kini oṣu kọkanla ọdun 1993 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede ghana kan ti o ṣere fun orlando pirates ti south africa premier division ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede ghana gẹgẹ bi gooli ologba ọmọ ghana ofori lo akoko pupọ pẹlu westland fc ẹgbẹ pipin keji ni accra ṣaaju ki o darapọ mọ wa allstars ti wa ghana o ti n ni asopọ nigbagbogbo pẹlu awọn gbigbe si south africa tabi yuroopu lẹhin ti o se iṣẹ iyìn rẹ tun ga julọ ni ajumọṣe premier ghana o si lọ ni idanwo pẹlu ilu cape town ni ipari ọdun 2016 won tun dibo gege bii oluṣọ ti o dara julọ ni akoko 2015 ati pe o jẹ ohun elo ninu gbigba gbogbo-stars ti akọle akọkọ wọn lailai ni ọdun 2016 lẹẹkansi won tun dibo gege bii oluṣọ ti o dara julọ maritzburg united ofori lọ si premier soccer league club maritzburg united fun adehun ọdun mẹta ni ọdun 2018 ni ọjọ 20 oṣu kẹwa ọdun 2020 ofori fowo si iwe adehun ọdun mẹta pẹlu orlando pirates o mu'le ninu ifẹsẹwọnsẹ orlando pirates ni idije mtn 8 o bere ni goolu ninu ifẹsẹwọnsẹ ikẹhin bi pirates ti gba ife ẹyẹ naa ti wọn si pari idije na lati to òpin aini ife eye ni ọdun mẹfa wọn na bloemfontein celtic 21 lati gba ife ẹyẹ naa ofori gba àwọn ifẹsẹwọnsẹ ni 2013 fifa u-20 world cup o tun se ifarahan ninu ifẹsẹwọnsẹ ipo kẹta wọn ko le mi awon re ninu ifẹsẹwọnsẹ pẹlu iraq lẹhinna o farahan fun ghana u23 ti o gba ninu awon ifesewonse ere afirika 2015 a koko pe e si egbe agba fun idije ifesewonse asiwaju orile-ede afirika 2016 nibi ti o ti gba ifẹsẹwọnsẹ mejeeji pẹlu ivory coast lẹhinna olukọni agba avram grant pe fun 2017 africa cup of nations oun ni igbakeji olori ẹgbẹ agbabọọlu orilẹede ghana awọn ọlá wa gbogbo stars
|
fortune makaringe fortune makaringe ti a bi ni ọjọ ketala osu karun ọdun 1993 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba alamọdaju ti orilẹ-ede south africa ti o ngba aarin fun ẹgbẹ agbabọọlusouth africa premier division orlando pirates o tun gba bọọlu fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede south africa oun gba bọọlu tẹlẹ fun maritzburg united ti a bi ni johannesburg makaringe bẹrẹ iṣẹ rẹ ni moroka swallows ṣaaju ki o to darapọ mọ maritzburg united makaringe fowo si iwe adehun fun orlando pirates ni igba ooru 2019 makaringe gba bọọlu akọkọ rẹ fun south africa ni ọjọ keta oṣu okudu odun 2018 ni 0-0 ninu ifẹsẹwọnsẹ pẹlu madagascar botilẹjẹpe south africa tẹsiwaju lati padanu ifẹsẹwọnsẹ 4-3 lori awọn ijiya o jẹ ikan l'ara ẹgbẹ agbabọọlu mejidinlọgbọn akọkọ ti south africa fun idije ife ẹyẹ ilẹ afirika 2019 ṣugbọn ko jẹ ara àwọn ti ẹgbẹ agbabọọlu 23 ikẹhin wọn
|
lyle lakay lyle lakay ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kẹjo ọdun 1991 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba orilẹ-ede south africa ti oun gba bọọlu afẹsẹgba fun mamelodi sundowns ni ajumọṣe bọọlu afẹsẹgba premier ise egbẹ agbabọọlu o jẹ ọmo ti ile-ẹkọ ọdọ supersport united o ni igbega si ẹgbẹ agbabọọlu akọkọ ni 2009 ṣugbọn o lo akoko re ni ọdun 200910 pẹlu national first division fun ẹgbẹ agbabọọlu fc cape town fun akoko 201011 o pada si supersport united lẹhin ọrọ ayalo miiran pẹlu fc cape town lakay darapọ mọ bloemfontein celtic ni ọdun 2012 o nireti lati forukọsilẹ fun ẹgbẹ inawo nla ti pretoria mamelodi sundowns fc lakoko window gbigbe oṣu kini ọdun 2014 ni ọjọ 14 oṣu kọkanla ọdun 2013 agbabọọlu naa ti sọ pe “bẹẹni mo de loni ni tshwane ṣugbọn emi yoo bẹrẹ ikẹkọ pẹlu sundowns ni ọla friday mo nireti pe ohun gbogbo yoo dara ” ni 2011 wọn pe si ẹgbẹ agbabọọlu to orilẹ-ede south africa u-20 fun 2011 african youth championship
|
nathaniel bassey nigerian gospel musician nathaniel bassey jẹ́ olórin nàìjíríà olùdarí ìjọ a-fọn-fèrè àti a-kọ-orin ẹ̀mí tí ó gbajú-gbajà fún àwọn orin rẹ̀ imela oníṣẹ́ ìyanu àti ọlọ́wọ́gbọgbọrọ ó ń lọ the redeemed christian church of god ó sì ń darí ìjọ the oasis èkó ìjọ àwọn ọ̀dọ́ ti rccg kings court ní vi ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí bassey ní èkó nàìjíríà ní 1981 ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa international relations and politics ní university of lagos kí ó tó lọ sí london láti lọ kọ́ nípa ìṣèlú lẹ́yìn náà ní ìdàkejì ẹ̀wẹ̀ ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa orin ní ilé-ẹ̀kọ́ ìgbà ẹ̀rùn middlesex university iṣẹ́ orin nathaniel bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ ní ilé-ìjọsìn níbi tí ó ti dara pọ̀ mọ́ rhodes orchestra tí ó sì fun fèrè tírọ́ḿpẹ̀tì fún ọdún méjì a-fọn-fèrè tírọ́ḿpẹ̀tì lásán ni tẹ́lẹ̀ títí di ìgbà tí ó ṣe àtinúdá orin níbi ìkíni sí stella obasanjo ìyàwó olóògbé ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí olusegun obasanjo ní 2018 bassey jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oníṣẹ́-ọnà tí ó wà lókè ní àpéjọpọ̀ àwọn kìrìsìtẹ́ẹ́nì nàìjíríà - the experience àwo rẹ̀ àkọ́kọ́ elohim ni wọ́n ṣe àgbàsílẹ̀ rẹ̀ tí wọ́n sì sọ ọ́ di odindi ní cape town south africa ní ọdún 2008 wọ́n ti ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i iṣẹ́ ẹ̀mí àti àràmàndà pẹ̀lú orin tí ó gbájú gbajà jù nínú rẹ̀ someone's knocking at the door orin tí ó ń lọ lẹ́sọ̀lẹ́sọ̀ tí àwọn ènìyàn sì ń nífẹ̀ẹ́ sí lọ́wọ́lọ́wọ́ nílé àti lókè òkun nathaniel bẹ̀rẹ̀ #hallelujahchallenge ní june 2017 níbi tí òun àti àwọn onígbàgbọ́ mìíràn ti máa ń sin ọlọ́run fún wákàtí kan láti 1200 am sí 100 am ó máa ń ṣe àfihàn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ní ojú ìran instagram ó sì máa ń pe àwọn mìíràn láti dara pọ̀ mọ ní ó kéré sí oṣù kan ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti ní ó pọ̀ ju ìwò 600000 lọ #hallelujahchallenge fún 2020 ni wọ́n ṣe láti 4 sí 24 february ní 2021 wọ́n ṣe challenge náà láti 1 sí 21 february
|
celestina onyeka nigerian footballer celestina onyeka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 15 óṣu july ni ọdun 1984 agbabọọlu naa ṣere fun pelican stars gẹgẹbi defender
|
akudo sabi nigerian footballer akudo sabi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 17 óṣu november ni ọdun 1986 arabinrin naa ṣere fun bayelsa queens gẹgẹbi defender
|
cecilia nku cecilia ngibo nku ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹwa ọdun 1992 jẹ agbabọọlu naijiria ti o gba fun egbe agbabọọlu rivers angels ti idije awọn obinrin naijiria nku gba bọọlu akọkọ rẹ ni ìdíje agbaye ni ọdun 2010 lakoko ti o nṣere fun nigeria ni 2010 fifa u-20 world cup women arabinrin naa wa lara ikọ agbabọọlu orilẹede naijiria ti o bori ninu idije idije awọn obinrin ile afirika ti ọdun 2014 ni orile-ede namibia ni oṣu karun ọdun 2015 ni a pe nku lati gba bọọlu fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede naijiria ninu idije ife agbaye awọn obirin ti 2015 fifa
|
ngozi ebere nigerian footballer ngozi ebere jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5 óṣu august ni ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi defender fun club norwegia arna-bjørnar
|
ibubeleye whyte nigerian footballer ibubeleye whyte agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 9 óṣu january ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi goalkeeper fun rivers angels ti o si kopa ninu ere idije awọn obinrin ilẹ naigiria
|
efioanwan ekpo nigerian footballer efioanwan ekpo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 25 óṣu january ni ọdun 1984 agbabọọlu naa jẹ ọkan lara ọmọ ẹgbẹ awọn obinrin apapọ lori bọọlu
|
binta masi garba nigerian politician binta masi garba wọ́n bí i lọ́jọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1967 jẹ́ gbajúmọ̀ oselu pàràkòyí oníṣòwò àti àti aṣàkóso tí ó jẹ́ aṣòfin-àgbà tí ó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò apá àríwá ní ìpínlẹ̀ adamawa láti ọdún 2025 ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́-òṣèlú all progressives congress apc bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ alága ìpínlẹ̀ fún gbajúmọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú tí àjọ independent national electoral commission fọwọ́ sí lórílẹ̀ èdè nàìjíríà lọ́dún 1999 sí 2011 binta jẹ́ ọmọ aṣojúṣòfin house of representatives ní ẹ̀mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ó jẹ́ ọmọbìnrin àkọ́kọ́ tí ó ṣojú ẹkùn ìdìbò ìjọba àpapọ̀ méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣojúṣòfin lọ́dún 2009 wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí igbá-kejì fún àjọ commonwealth women parliamentarians cwp lábẹ́ àjọ commonwealth parliamentary association cpa ni orílẹ̀ èdè cameroon bákan náà ó jẹ́ obìnrin kan ṣoṣo tí ó ṣojú ìpínlẹ̀ adamawa ní àpérò national conference ní abuja
|
mr real okafor uchenna victor tí gbogbo ayé mọ̀ sí mr real jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè nàìjíríà tí ó wá láti ìpínlẹ̀ èkó ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé ẹ̀ mr real tí a tún mọ̀ sí real self ni a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹjọ ní ìpínlẹ̀ èkó ní orílẹ̀-èdè nàìjíríà sí àwọn òbí tí ó wá láti ìlú okija ìpínlẹ̀ anámbra ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó gbé orin legbegbe jáde ó tọwọ́ bọ̀wé fún ṣíṣe ọ̀wọ́ orin pẹ̀lú sony music entertainment africa ní ọdún 2018
|
mercy achieng kenyan footballer born 1992 mercy achieng jẹ agbọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12 óṣu august ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens ati team apapọ ilẹ kenya
|
wendy achieng kenyan footballer wendy achieng jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 12 óṣu september ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
|
mwanalima adam kenyan footballer mwanalima adam jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 4 óṣu september ni ọdun 1997 agbabọọlu naa ṣere fun hakkarigücü spor ni super league awọn obinrin ilẹ turkey gẹgẹbi forward
|
lilian adera kenyan footballer lilian adera jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7 may ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin ilẹ kenya
|
stella ahono kenyan footballer stella ahono jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti o ṣere fun zetech sparks fc gẹgẹbi goalkeeper
|
mercy airo kenyan footballer mercy airo jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 20 óṣu october ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun kisumu all starlets fc gẹgẹbi forward
|
victorien adebayor adebayor zakari adje ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kọkanla ọdun 1996 jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede niger ti o gba fun ẹgbẹ agbabọọlu niger premier league usgn ti o wa la'win lati ọdọ danish 1st division club hb køge ni ọdun 2016 adebayor ni awọn idanwo pẹlu awọn ẹgbẹ kan ni ligue 1 fc lorient ati as monaco ṣugbọn won ko funni ni adehun ni ẹgbẹ mejeeji ni ọjọ kakandinlogbon oṣu kẹjọ 2018 vejle boldklub ni denmark kede iforukọsilẹ ti adebayor lati inter allies lori adehun awin titi di ọjọ ogbon ni osu okudu 2019 sibẹsibẹ lẹhin oṣu kan ẹgbẹ naa kede pe wọn fẹ lati fopin si adehun awin naa nitori adebayor ko wa ibi igbaboolu lehin ti wọn ti ṣe adehun ati wipe ẹgbẹ naa ko ni anfani lati kan si agbabọọlu naa sibẹsibẹ o pada si orilẹ-ede denmark ni oṣu kẹwa ọdun 2020 nigbati o fowo si iwe adehun pẹlu danish 1st division club hb køge eyiti o jẹ egbẹ bọọlu afẹsẹgba danish ti o wa ni ilu herfølge ati eekeji ni ilu køge mejeeji ni agbegbe køge bibẹẹkọ ni ọjọ 4 oṣu kẹta ni odun 2021 ẹgbẹ naa jẹrisi pe adebayor ti lo lawin si legon cities nitori o fẹ lati sunmọ idile rẹ nitori awọn idi ti ara ẹni ni ọjọ 10 oṣu kẹsan ọdun 2021 adebayor gba si adehun alawin ọdun kan pẹlu enppi sc ti orilẹ-ede egypt ise okeere o jẹ agbaboolu giga julọ ni niger pẹlu ami ayo mejidinlogun ninu ifẹsẹwọnsẹ mẹtalelogoji
|
boushaki boushaki lárúbáwá le tọka si
|
bernardo manuel bernardo manuel ti a bi ni o osu ketadinlogbon ni oṣu kejila ọdun 1954 jẹ asare olona-jinjin ara orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje mita 5000 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1980
|
antónio dos santos athlete antónio dias dos santos ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹsan ọdun 1964 jẹ olufo gigun ti orilẹ-ede angola ati jumper olopometa ni ìdíje ere 1987 central african o gba ami-eye goolu ni fo olopometa ati ami ẹyẹ fadaka ni ti ifo gigun ni ipari idije naa ni 1988 ti afirika o gba ami-eye goolu ni fo olopometa o tun dije ninu fifo olopometa ni olimpiiki igba ooru ọdun 1988 ati idije inu ile 1991 agbaye ati olimpiiki igba ooru 1992 lai de ipele ti o pari o tun dije ni fifo gigun ni 1987 world championships ati 1991 world indoor championships lai de opin fifo olopometa ti ara re ti o dara julọ jẹ mita 1643 ti o waye ni ọdun 1988
|
marcos daniel swimmer marcos daniel ti a bi ni ọjọ kini oṣu kẹjọ ọdun 1961 jẹ oluwe omi fun orilẹ-ede angola o dije ninu awọn ìdíje meji ni olimpiiki igba ooru 1980
|
mario ervedosa mario ervedosa ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn oṣu kaarun ọdun 1998 jẹ oluwe odo orilẹ-ede angola o dije ninu idije 50 mita igbaya ọkunrin ninu idije aquatics world 2017
|
vivaldo fernandes vivaldo fernandes ti a bi ni ọjọ kewa osu okudu ọdun 1971 jẹ oluwe odo orile-ede angola o dije ninu idije olufayawe 100 mita awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988
|
gaspar fragata gaspar fragata ti a bi ní ọjọ kerin oṣu keji ọdun 1972 jẹ oluwe odo fun orilẹ-edeangola o dije ninu iwe onigbaya 100 mita awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988 awọn itọkasi fç
|
daniel francisco daniel francisco ti a bi ni ọjọ kẹjo ọsu keji ọdun 2000 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje oni labalaba mita 50 ti awọn ọkunrin ni idije aquatics world 2017 ni ọdun 2019 o ṣe aṣoju angola ni ere afirika 2019 ti o waye ni rabat morocco
|
jorge gomes swimmer jorge gomes ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kini ọdun 1972 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angola o dije ninu ìdíje ọkunrin 100 mita labalaba ni olimpiiki igba ooru 1988 ti o pari nikẹhin ni ipo 51st
|
salvador gordo salvador vieira gordo ti a bi ni ọjọ keje oṣu kini ọdun 2003 jẹ oluwe-odo fun orilẹ-ede angolan o dije fun angola ni olimpiiki igba ooru 2020 ni ipele labalaba 100m ti awọn ọkunrin o pari ni ipo 54th lapapọ pẹlu akoko 5596 ninu ooru rẹ o ti pinnu lati wa pelu iwẹ odo wiwẹ ni university of tampa ni orilẹ-ede amẹrika
|
luis matias luis matias ti a bi ni ọjọ kakandinlogbon osu kẹsán odun 1986 ni luanda jẹ oluwe odo angola kan ti o ṣoju angola ni olimpiiki igba ooru 2004 ni ipele labalaba 100 mita awọn ọkunrin lakoko o bori ipele ooru akoko pẹlu akoko 5892 o pari ni ipo 58th ninu awọn aaye 60 ati pe ko ni ilọsiwaju
|
pedro pinotes pedro miguel pinotes tí a bí ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹsàn-án ọdún 1989 jẹ́ olùwè-odò orílẹ̀-èdè angola tí ó díje nínú ìdíje 400m ti àwọn ọkùnrin ni òlíḿpíkì ìgbà ooru 2012 ó parí ní ipò 30th lápapọ̀ nínú ìdíje ooru ní ìdíje oníkálùkù ti àwọn ọkùnrin 400 àti ó sì tún kùnà láti dé òpin-ìparí ní òlíḿpíkì ìgbà ooru 2016 ní rio de janeiro ó díje nínú ìdíje 400 m àwọn ọkùnrin ó parí ní ipò 25th ni ìdíje ooru àti pé kò lọ sí ologbele-ìparí
|
dário antónio dário antónio marcelino ti a bi ni ọjọ kejilelogun oṣu kẹwa ọdun 1992 jẹ ẹlẹṣin orilẹ-ede angola ti o gun lọwọlọwọ fun ẹgbẹ uci continental baisicasalpetro de luanda
|
igor silva cyclist igor alberto secundino silva tí a bí ni ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹwàá ọdún 1984 jẹ́ ẹlẹ́ṣin-ije ní òpópónà ní orílẹ̀-èdè angola tí ó gùn lọ́wọ́lọ́wọ́ fún ẹgbẹ́ uci continental baisicasalpetro de luanda
|
esse akida kenyan footballer esse akida jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 18 óṣu november ni ọdun 1992 agbabọọlu naa lọwọ ṣere fun poak ni ilẹ greece o wa lara awọn ọmọ ẹgbẹ harambee starlets
|
samantha akinyi kenyan footballer samantha akinyi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 6 óṣu january ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun awọn ọdọmọbinrin makolander fc
|
vivian akinyi kenyan footballer vivian akinyi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 20 óṣu may ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper
|
lucy akoth kenyan footballer lucy akoth jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 12 óṣu december ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun mathare united fc gẹgẹbi defender
|
lydia akoth kenyan footballer lydia akoth jẹ̀ agbabọọlu lobinrin orilẹ ede kenya ti a bini 22 óṣu september ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi midfielder
|
ann aluoch kenyan football player and manager ann aluoch jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kẹnya ti a bini 5 óṣu january ni ọdun 1990 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
|
rosemary aluoch kenyan footballer rosemary aluoch jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 7 óṣu may ni ọdun 1976 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper ti o si ku si ilu kasarani ni ọjọ kẹrin óṣu october ọdun 2020 àṣeyọri rosemary ṣere fun team awọn obinrin ilẹ kenya lati 1995 si 2014 ni ọdun 2015 agbabọọlu naa di ọkan lara awọ̀n staff gẹgẹbi coach goalkeeper
|
elizabeth ambogo kenyan footballer elizabeth ambogo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 28 óṣu july to waye ni ọdun 1990 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
|
sheril angachi kenyan footballer sheril angachi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọjọ akọkọ óṣu january ni ọdun 2000 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun gaspo youth fc àṣeyọri sheril kopa ninu nations cup awọn obinrin ilẹ́ afirica to waye ni ọdun 2018
|
carolyne anyango kenyan footballer carolyne anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 27 óṣu february ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder
|
doris anyango kenyan footballer doris anyango jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 19 óṣu november ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ́bi defender
|
fagrie lakay fagrie lakay ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon oṣu karun ọdun 1997 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba fun orilẹ-ede south africa ti oun gba siwaju fun ẹgbẹ agbabọọlu premier league egypt pyramids fc ati ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede south africa career statistics ti a bi ni manenberg lakay bẹrẹ bọọlu afẹsẹgba fun real stars ẹgbẹ kan ti baba rẹ jẹ lẹhinna o rii ipolowo kan fun awọn idanwo santos ati pe baba rẹ mu u lọ sibẹ lakay gba bọọlu akoko rẹ fun santos ni national first division ni 20 oṣu kẹwa ọdun 2012 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn pẹlu fc cape town o bẹrẹ ati pe o gba abala akọkọ bi santos ṣe gba omo ayo ninu ìfesewonse naa 00 lẹhinna o gba ominayo akoko re wọlé ninu ifẹsẹwọnsẹ rẹ ni ọjọ kaarun osu keji ọdun 2014 pelu ile-ẹkọ giga maluti fet ninu eyiti o gba wọlé ni iṣẹju 39th rẹ fun santos ni o gbe won siwaju pelu 20 sibẹsibẹ fet college pada wa lati gba ifẹsẹwọnsẹ naa si ómí 22 ile oke're lakay ti ṣere fun south africa ni ipele ẹgbẹ awon ti o wa labẹ-17 ati labẹ-20 lakay gba ami ayo wọle ninu ifẹsẹwọnsẹ igbaradi fun santos pelu agbabọọlu orilẹede naa ti o na dumisani msibi ẹlẹgbẹ rẹ ti àwọn ti abẹ 20 ni goolu lati 40m ṣaaju ifẹsẹwọnsẹ south africa pẹlu orilẹ-ede nigeria ni cape town o gba ifẹsẹwọnsẹ agbá akọkọ rẹ fun orilẹ-ede south africa ni ọjọ ogbon oṣu kọkanla ọdun 2014 nigbati orilẹ-ede naa gba ifẹsẹwọnsẹ pẹlu orilẹ-ede ivory coast o wa bi aropo ni iṣẹju 75th fun themba zwane bi orilẹ-ede south africa ti bori pelu 20 nipa ṣiṣe iṣafihan akọkọ rẹ lakay ni ọdun 17 oṣu 5 ọjọ 30 o gba ipo naa lowo rivaldo coetzee o se fi itanbalẹ gẹgẹ bi eniti o mere julo l'ojo ori lati wọ aṣọ orilẹ-ede ni ọdun 17 oṣu 11 ọjọ 25 coetzee gba itan naa lowo balogun iko bafana tẹlẹ aaron mokoena ti o jẹ omo ọdun 18 oṣu meji ọjọ 26 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn pẹlu egbe agbabọọlu orilẹede botswana ni ọdun 1999
|
ayoko ayokunle olushola ayoko ayokunle olushola jẹ agbẹjọro ti a mọ daradara ni orilẹ-ede naijiria onisọwe idaraya pẹlu awọn ọdun ti iriri akojọpọ ọpọlọpọ awọn ile-iṣẹ ni ibamu ilana imọran ofin iṣakoso adehun iṣẹ ajọ / iṣowo iṣakoso ẹjọ iṣakoso ile-iṣẹ ilana ile-iṣẹ ati adaṣe ibamu nipa abi ọgbẹni ayoko ayokunle olushola ni july 12 1982 o je omo agbegbe akoko south west local government ni ipinle ondo state eko ayokunle losi ilewe alakobere army children school pelu ile iwe girama amuwo odofin secondary school ni ipinle lagos state ayokunle tesi iwaju losi ile iwe giga ti ilu ibadan ayokunle gba oye llb hons lati yunifasiti ti ilu ibadan iṣẹ ayokunle ayoko jẹ akowe pẹlu iriri ọpọlọpọ awọn ile-iṣẹ ni iṣakoso ajọṣepọ imọran ofin ilana akọwe ile-iṣẹ kikọ ofin ibamu ewu ati iṣakoso awọn orisun eniyan o jẹ akowe ile-iṣẹ tẹlẹ si fbn insurance limited fbn general insurance limited lẹhinna awọn oniranlọwọ ti fbn holdings plc ati sanlam south africa ati fbn insurance brokers limited ṣaaju ki o darapọ mọ berger paints nigeria plc ni 2018 gẹgẹbi akowe ile-iṣẹ / oludamoran ofin o jẹ olugba ti 2019 40 labẹ 40 aami eye ofin naijiria nipasẹ esq iwe irohin lagos aami-ẹri ijọba agbaye 100 modern ti ọdun 2020 nipasẹ alagbara corporation new york ati ẹka ofin 2022 ti forty under forty africa awards ghana nipasẹ xodus communications limited o jẹ oludamọran iṣakoso ifọwọsi cmc oluyanju ijẹwọgbigba ijẹrisi cca ẹlẹgbẹ ti institute of management consultants fimc ati ti ile-ẹkọ giga ti isuna ati isakoso agbaye gafm amẹrika o jẹ ọmọ ẹgbẹ igbimọ ti gerson lehrman group glg new york oludari kan pẹlu kaizen academy nàìjíríà limited ọmọ ẹgbẹ ti nigeria bar association nba ati international bar association iba ayokunle tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti society for corporate governance nigeria scgn institute of directors nàìjíríà iod nibi ti o ti ṣe iranlọwọ fun awọn ikẹkọ fun alakoso agba awọn alakoso c-suite ati awọn oludari
|
veli mothwa veli mothwa ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kejí ọdun 1991 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba fun orilẹ-ede south africa kan ti o n gba bọọlu bi gooli fun ẹgbẹ south africa premier division amazulu ati ẹgbẹ orilẹ-ede south africa o gba boolu akọbi rẹ fun orilẹ-ede south africa ni ọjọ kefa oṣu keje odun 2021 ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn ni 2021 cosafa cup pelu orilẹ-ede botswana south africa gba idije naa ati pe mothwa ni a yan gẹgẹ bi goọli ti o dara julọ bi o ṣe mi awon ninu ifẹsẹwọnsẹ marun ti o ṣe pẹlu ifẹsẹwọnsẹ abala asekagba pelu orilẹ-ede senegal
|
mercyline anyango kenyan footballer mercyline anyango jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 30 óṣu april ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens gẹgẹbi midfielder
|
neddy atieno kenyan footballer neddy atieno jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 8 óṣu july ni ọdun 1992 arabinrin naa ṣere fun ulinzi gẹgẹbi forward
|
cheris avilia kenyan footballer cheris avilia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 11 óṣu december ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere fun spedag
|
lilian awuor kenyan footballer lilian awuor jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 13 óṣu june ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun harambee starlets
|
janet bundi kenyan footballer janet bundi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 15 óṣu december ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens gẹgẹbi defender
|
sharon bushenei kenyan footballer sharon bushenei jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 7 óṣu june nì ọdun 1988 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward
|
vivian corazone kenyan footballer vivian corazone jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 2 óṣu october ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun gaspo youth gẹgẹbi midfielder
|
lamia essaadi lamia essaadi ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹwa ọdun 1979 jẹ agba tẹnisi lati orilẹ-ede morocco essaadi ni ipo wta ti o gaa pẹlu ami 469 ni alailẹgbẹ ti o gba ni ọjọ ogbon oṣu kẹrin ọdun 2001 ati 398 ni ilọpomeji ti o gba ni ọjọ kẹsán oṣu kọkanla ọdun 1998 o ti gba ipo kini ni ti ẹyọkan ni circuit awọn obirin itf ifihan akọkọ re wa ni wta tour ni 2008 grand prix sar la princesse lalla meryem ti nṣere fun orile-ede morocco ni cup fed essaadi ni iṣẹgunipadanu ti 30
|
terry engesha kenyan footballer terry engesha jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 15 óṣu february ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun south korean club red angels wfc
|
ruth ingosi kenyan footballer ruth ingosi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 19 óṣu december ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere cypriot club lakatamia fc gẹgẹbi defender
|
wincate kaari kenyan footballer wincate kaari jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 13 óṣu november ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi defender
|
mr eazi ọjọ́ kankàn-dín-lógún oṣù agẹmọ ọdún 1991 ní wọn bí oluwatosin ajibade tí orúkọ ìnàgijẹ rẹ̀ ń jẹ́ mr eazi olórin ilẹ̀ nàìjíríà ni bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ òǹkọrin àti oníṣòwò ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó dá orin banku iyẹn àpapọ̀ ohùn orin ghana àti ilè nàìjíríà mr eazi kó lọ sí kumasi ní orílẹ-èdè ghana ní ọdún 2008 ó sì wọlé sí knust níbi tí o tí ń gba àwọn òsèré láti wá ṣeré ní ìnáwó iléèwé ó fi ìfẹ́ hàn sí orin kíkọ nígbà tí ó ṣe orin rẹ̀ my life
|
yusuf maart moegamat yusuf maart ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu keje odun 1995 jẹ agbabọọlu south africa ti o n gba iwaju fun ẹgbẹ south africa premier division sekhukhune united ati ẹgbẹ orilẹ-ede south africa ise egbẹ agbabọọlu orlando pirates maart ni a bi ni cape town o si dagba ni atlantis orlando pirates ṣe akiyesi rẹ ni ọdun 2016 lẹhin ti won yan gẹgẹ bi eniti o dara julo ninu idije sab u-21 ti ọdun yẹn o kọkọ darapọ mọ ẹgbẹ ifiṣura ẹgbẹ ṣugbọn o gba ifẹsẹwọnsẹ akọkọ rẹ ni ọjọ 12 oṣu kẹta ọdun 2017 bi aropo ninu iṣẹgun 31 wọn lori ec bees ni ife nedbank o ṣe akọbi ajumọṣe rẹ nigbamii ni akoko yẹn bi aropo ni ijatil 21 si lamontville golden arrows ni ọjọ 27 may 2017 maart lo akoko 2018-19 l' awin pẹlu cape umoya united nibiti o ti gba goolu wọle leeksn ninu ifẹsẹwọnsẹ merindinlogun awon egbe agbabọọlu aajalelokun fi sile ko ma lo ni igba ooru 2020 sekhukhune united maart darapọ mọ sekhukhune united ti national first division lẹhin igba ti egbe agbabọọlu pirates ti yonda re o ṣe ipa pataki ninu igbega ẹgbẹ naa si south africa premier division ni akoko yẹn o gba goolu meta wọle ninu ifẹsẹwọnsẹ 28 liigi ise okeere a pe maart si ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede south africa fun 2021 cosafa cup o gba goolu akọkọ rẹ wọle ni ọjọ 16 oṣu keje 2021 ninu ibori ifẹsẹwọnsẹ ologbele-ipari cosafa pelu mozambique o si ṣere ni ipari bi maart ṣe bori idije naa ni atẹle iṣẹgun ifiyaje 65 lori senegal o gba ifẹsẹwọnsẹ 6 o gba goolu kan so wọlé lakoko 2021 cosafa cup
|
jules bessan jules yao bessan ti a bi ni ọjọ kerinla oṣu kẹrin odun1979 je oluwe-odo ti orilẹ-ede beninese o se oju orilẹ-ede re ni idije 2016 summer olympics ni 50 mita elere o gbe ipo 77th pẹlu asiko 2732 iseju aaya ko yanjun si ipele ti o kangun si asekagba bessan si ni eniti ami eye orilẹ-ede benin ninu 50 mita elere ati 50 mita ọyan
|
alois dansou aloïs dansou ojoibi 1982 je olowe olimpiiki lati ilu benin o we fun orilẹ-ede benin ni amon ìdíje wonyi
|
christophe pognon christophe pognon ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kẹwa ọdun 1977 ni cotonou jẹ oṣere tẹnisi tẹlẹ lati benin pognon ṣe aṣoju orilẹ-ede abinibi rẹ ni olimpiiki igba otutu 2000 ni sydney australia nibiti o ti ṣẹgun ni ipele akọkọ nipasẹ gustavo kuerten brazil eni ti o ni ọwọ ọtun de ami iyasọtọ atp ti o ga julọ ni ipo ni ọjọ 27 oṣu kẹjọ ọdun 2001 nigbati o di nọmba 804 ni agbaye pognon ṣe alabapin ninu ìdíje davis cup fun orilẹ-ede benin lati 19942003 ti o fi ami 1417 kan silẹ niti elẹyọkan ati itan 11 ni eleeyanmeji
|
aloÿs nizigama aloÿs nizigama ti a bi ni ọjọ kejidinlogun osu okudu ọdun 1966 jẹ asare olona jinjin ọmọ ilu orilẹ-ede burundi ti o ti fẹhinti ti o iṣe re je ti mita 5000 ati 10000 ninu iṣẹ rẹ nizigama sa ere-ije ni iṣẹju 21 ati iṣẹju-aaya-28 ni 10000 mita ni ipo keji si haile gebrselassie pẹlu akoko 23
|
nosa omoregie ojúewé yìí jẹ mọ́ nípa the nigerian recording artiste fún other uses ẹ wo nosa omoregie nosa omoregie tí a mọ̀ mọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i nosa jẹ́ oníṣẹ́-ọnànàìjíríà olórin a-kọ-orin àti eléré ó wà lábẹ́ warner music group african partner lọ́wọ́lọ́wọ́ chocolate city ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé nosa omoregie tí wọ́n mọ̀ ní ṣókí gẹ́gẹ́ bí i nosa ni wọ́n bí ní 26 oṣù kejì ọdún 1981 ó jẹ́ ọmọ ìlú benin city ìpínlẹ̀ edo ẹ̀kọ́ ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ní yunifásítì benin uniben ìpínlẹ̀ edo iṣẹ́ orísun ayọ̀ nosa gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí ó ń dàgbà wà nínú orin àti lílọ sí ilé ìjọsìn níbi tí ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àmúlò àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ tí ń gbèrú ó bẹ̀rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ akọrin ọmọdé ní ilé ìjọsìn àwọn olórin ẹ̀mí bí i fred hammond àti kim burrell sì ni wọ́n jẹ́ ẹṣin iwájú tí ó ń wò sáré àti àwọn ẹgbẹ́ olórin r n b boyz ii men ó ní láti nífẹ̀ẹ́ orin jazz àti orin soul àti lẹ́yìn náà orin rock nígbà tí ó yá fún rírọrùn tí ó rọrùn ó tún jẹ́ aṣàwòkọ́ṣe ńlá afro-highlife pàápàá orin láti ọwọ́ sonny okosun christy essien-igbokwe king sunny adé àti onyeka onwenu fún ìdí èyí ó mú láti inú ọ̀pọ̀ èròǹgbà ọmọdé fún iṣẹ́ láti di onímọ̀ ẹ̀rọ jagunjagun agbábọ́ọ̀lù sí dídi aṣàgbéjáde orin àti olórin èròǹgbà nosa pẹ̀lú iṣẹ́ orin rẹ̀ ni láti dí àlàfo irúfẹ́ orin nígbà tí ó ń rí i dájú pé abala orin ẹ̀mí rẹ̀ wà ní ipele iwájú pátápátá gẹ́gẹ́ bí àwọn irúfẹ́ orin mìíràn èyí ni pé irúfẹ́ àpapọ̀ tí ó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ tí ó ń ṣe àtinúdá orin ẹ̀mí lórí ìlù high-life ẹsẹ high-life pẹ̀lú ègbè tí ó jọ mọ́ rock-y tàbí kíkọ orin 'àdàmọ̀dì' òyìnbó pẹ̀lú àdídùn r n b nígbà tí ó bá ń ṣe ìwàásù iṣẹ́ amóríwú tàbí amọ́kànyá sí àwọn olùgbọ́ rẹ̀ wọ́n ṣe àgbéjáde àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ open doors ní 14 oṣù kẹta 2014 ó sì ṣe àtìlẹ́yìn rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹyọ orin always pray for you why you love me àti always on my mind àti bákan náà ní oṣù karùn-ún 2014 ó pawọ́pọ̀ pẹ̀lú nokia fún àgbéjáde orin rẹ̀ love is calling ní ọjọ́ 16 oṣù karùn-ún 2014 ìwé ìròyìn the punch sọ pé nosa tọwọ́bọ̀wé àdéhùn iṣẹ́ ìpolówó pẹ̀lú unilever ní ọjọ́ 26 oṣù kejì 2020 tí ó tún jẹ́ ọjọ́ ìbí rẹ̀ nosa bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀ salt music iṣẹ́ orin àti orin-ẹyọ tí ó gbé e jáde nosa lọ sí abẹ́ ilé-iṣẹ́ orin chocolate city ní 2012 ní 11 oṣù kọkànlá 2009 nosa ṣe àgbéjáde orin-ẹyọ rẹ̀ àkọ́kọ́ always pray for you lábẹ́ ilé-iṣẹ́ chocolate city always pray for you jẹ́ ẹyọ-orin nosa àkọ́kọ́
|
mary kinuthia kenyan footballer mary kinuthia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 19 óṣu february ni ọdun 1990 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi forward
|
annette kundu kenyan footballer annette kundu jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 17 óṣu december ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper
|
sylvia lumasia kenyan footballer sylvia lumasia jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ́ kenya ti o ṣere fun ile ẹkọ lori bọọlu ọdọmọbinrin kibera gẹgẹbi forward
|
enez mango kenyan footballer enez mango jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini ọjọ akọkọ óṣu july ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens fc gẹgẹbi left wing back
|
rachael muema kenyan association football player rachael muema jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 6 óṣu october ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun thika queens fc
|
doreen nabwire kenyan former footballer manager and executive doreen navwire jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 5 óṣu march ni ọdun 1987 arabinrin naa ṣere fun pec zwolle fc gẹgẹbi midfielder
|
christine nafula kenyan footballer christine nafula jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 10 óṣu november ni ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder
|
vivian nasaka kenyan footballer vivian nasaka jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 19 óṣu december ni ọdun 1999 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun vihiga queens fc
|
adebisi akanji nigerian artist adebisi akanji ibí 1930 jẹ́ òṣèré tí orílé èdè nàìjíríà bákan náà ó sí jẹ́ olóyè olúwo ògbóni tí ilé ìlédì kàrún ohùntótó èyí tí ó jẹ́ ògbóni tí ó jẹ́ gbóògì tí ìbílẹ̀ lodge tí ìlú òṣogbo ní ìpìnlẹ̀ ọṣun ní orílé èdè nàìjíríà ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ìwé kíkà ní gbà tí ó gbọ́njú ọ ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí amọlé bírìkì bricklayer lẹyìn èyí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbé èrè láti lè gbáradì fún ìdíje èyí tí ó sí gbé àwọn ẹranko tí ó dúró fún àṣà èyí tí ó wà fún ohùn oṣo fún inú ilé iṣé àkànjí jẹ́ ẹnití ó gbajúmò fún iṣé àgbẹ̀dẹ̀ àti àwọn iṣé èrè ọ sí tún tí ṣíṣe ni ilé iṣé aṣọ àwọn iṣé rẹ a máa sàlàyẹ́ àwọn ìsòrí àlọ ilé yorùbá yoruba people|yoruba ní ìbáṣepọ̀ pẹlú susanne wenger ó tí ṣíṣe fún ọdún mẹwàá ní ojúbo òṣun ní ìlú òṣogbo ní orílé èdè nàìjíríà òun yìí náà ló gbé àwọn eré mìíràn ní ibè
|
lorna nyarinda kenyan footballer lorna nyarinda jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 13 óṣu october ni ọdun 2000 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun vihiga queens fc
|
sunday jack akpan nigerian sculptor sunday jack akpan orúkọ ìbisọ rẹ ni ikot ide etukudo 1940 jẹ́ agbẹ̀gí kéré tí orílé èdè nàìjíríà tí wón ń pé ní èdè gèésì ni the contemporary african equivalent of the medieval artisan ó jẹ́ gbajúmò fún iṣé rẹ̀ iṣé ère èyí tí ó máa ń ló sìmẹ̀tì cement èyí tí ó máa ń fí ń gbé àwọn èrè ìbílè fún àwọn ẹni oyè àti àwọn èèyàn jàǹkàǹjàkàǹ àti àwọn ojú ìbòjú grave art lẹ́yìn náà ní yóò wá kún ọdà ọ tí ṣé àwọn iṣé ère lórísiríri èyí tí ó wà fún títà commercial arts àwọn bí àlùfáà ìjọsìn àti àwọn èèyàn jàǹkàǹ ní àwùjọ àwọn iṣé èrèle rẹ̀ wá ni ìfihàn ni venice biennale àti ní gbàgede centre pompidou ni paris àti àwọn gbàgede ìfihàn míìràn àwọn iṣé rè náà ni horniman museum ni london ==àwọn ìtọ́kasí=
|
jacky ogol kenyan footballer jacky ogol jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọjọ keji óṣu december ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder
|
emmanuel taiwo jegede emmanuel taiwo jegede ti a bi ni june 1943 jẹ akewi ọmọ orilẹede naijiria akọwe itan oluyaworan atẹwe ati alaworan ninu igi idẹ ati seramiki ìbéèrè ayé rẹ àti ẹkọ emmanuel taiwo je omo bibi ilu ayegbaju ekiti a yoruba-speaking agbegbe ti naijiria ọ kó isé eré mimọ lati owo pa akerejola ni ekiti lẹyìn tí ọ lọ sí yaba school of technology in lagos nibi ti ọ ti ko nipa edo sculptor osagie osifo ni ọdún 1963 o rin irin ajo lọ sí òkè òkun uk nibi ti o ti kawe willesden college of technology ati hammersmith college of arts studying the decorative arts interior design sculpture and bronze casting
|
olowe of ise olowe of ise yoruba ọlọ́wẹ̀ ti ìsẹ̀ c 1873c 1938 ní èrò àwọn òpìtàn iṣẹ́-ọnà tí wọ́n jẹ́ òyìnbó àti àwọn olùgbàsílẹ̀ iṣẹ́-ọnà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí ó ṣe pàtàkì jù ní sẹ́ntúrì 20 láàárín àwọn oníṣẹ́-ọnà ti àwọn ará yorùbá tí ó jẹ́ nàìjíríà òní áfíríkà ó jẹ́ agbẹ́gilére igi a-gbẹ́-ère àti ọ̀gá olùdásílẹ̀ nínú àrà ìṣelọ́ṣọ̀ọ́ áfíríkà tí a mọ̀ sí ojú-ọnà ọlọ̀wẹ̀ tí wọ́n mọ̀ láti ilẹ̀ sí olowere ni wón bí ní efon-alaiye ìlú kan tí wọ́n mọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gángán ibi àṣà ní ilẹ̀ yorùbá ṣùgbọ́n ó gbé púpọ̀ ayé rẹ̀ ní ìgboro ise wọ́n gbà á láti ìbẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìránṣẹ́ ní ààfin ọba arinjale oba ti ise ó jẹ́ ọ̀rọ̀ àríyànjiyàn bóyá iṣẹ́ iṣẹ́-ọnà rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ìkọ́ṣẹ́ tàbí ó dìde tààrà láti ẹ̀bùn rẹ̀ lásán òkìkí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i agbẹ́gilére hàn láti bẹ̀rẹ̀ ní ise lábẹ́ àtìlẹ́yìn arinjale ṣáájú kí ó tó tàn ká apá ìlà-oòrùn ilẹ̀ yorùbá wọ́n pé olowe lọ sí ilesa ikere akure idanre ogbagi àti àwọn ìlú yorùbá mìíràn tí ó wà ní àárín máìlì ọgọ́ta 9675 kilometers láti ṣe àwọn ohun èlò ilé ńlá gẹ́gẹ́ bí i àsè àti àgáraǹdì ohun èlò ara àti ètùtù fún àwọn ìdílé olówó ipò iyì olowe gẹ́gẹ́ bí i oníṣẹ́-ọnà jẹ́ gbígbàsílẹ̀ láti ọwọ́ àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ nínú ewì alohùn yorùbá tí a mọ̀ sí oríkì fún àpẹẹrẹ èyí example tí ọ̀kan lára àwọn ìyàwó rẹ̀ kọ tí wọ́n gbàsílẹ̀ ní 1988 òkìkí òke-òkun ní 1924 wọ́n ṣe àfihàn iṣẹ́-ọnà olowe ní òke-òkun fún ìgbà àkọ́kọ́ nígbà tí wọ́n yan àṣè olókè láti ààfin ọba ní ikere fún pàfílíọ́nù nàìjíríà ní british empire exhibition ní wembley london àwọn british museum ra iṣẹ́-ọnà yìí lẹ́yìn náà
|
felix idubor nigerian sculptor felix idubor 19281991 jẹ́ agbẹ́gilére nàìjíríà láti ìlú benin ìlú kan tí ó ní ìtàn tí ó lọ́ọ̀rìn nípa ìmọ̀ọ́ọ́ṣe iṣẹ́-ọnà ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ kékeré àwọn oníṣẹ́-ọnà ní àárín 1950 àti 1960 tí wọ́n ṣe igbéǹde ìdálẹ́kọ̀ọ́ mímọ̀ nípa iṣẹ́-ọnà ìṣe áfíríkà ní dídé àti ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀wọ́ ènìyàn àyíká wọ́n máa ń gbé e wò ní àwọn ìgbà kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí i ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ iṣẹ́-ọnà ìgbàlódé nàìjíríà ní 1966 ó ṣí ilé-ìṣàfihàn iṣẹ́-ọnà ìgbàlódé àkọ́kọ́ ní nàìjíríà sí òpópónà kakawa èkó ó yege gan-an nínú gbígbẹ́ àṣè ó sì ní àṣẹ láti máa gbẹ́ àṣè fún àwọn ilé-iṣẹ́ ńláńlá àti àwọn ènìyàn bí àpẹẹrẹ ilé ilé-ìfowópamọ́ cooperative ní ìbàdàn àti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní èkó ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbésí-ayé àti ẹ̀kọ́ wọ́n bí felix idubor sínú ìdílé àgbẹ̀ ní ìlú benin ó bẹ̀rẹ̀ sí gbẹ́gilére ní àti kékeré ṣùgbọ́n ó rí àwọn àtakò kan láti ọ̀dọ̀ bàbá rẹ̀ tí ó lérò pé gbígbẹ́ ilé rẹ kì í ṣe iṣẹ́ tí í mówó wọlé ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní benin ṣùgbọ́n ó gba ìsinmi nínú ìwé kíkà nígbà tóyá láti lè gbájúmọ́ ohun tí ó rò pé ó jẹ́ iṣẹ́ àdámọ́ rẹ̀ gbígbẹ̀gilére àkórí iṣẹ́-ọnà rẹ̀ àkọ́kọ́ tí ó yàn dálé àwọn ẹyẹ tí wọ́n gbẹ́ ní ọ̀pọ̀ ìgbà láti ara ìrókò igi tí ó pọ̀ ní benin ó tún lo àwọn igi láti ara ìrókò gẹ́gẹ́ bí i ohun èlò iṣẹ́ ní àwọn iṣẹ́ gbígbẹ́gilére ó sì yege nínú ọ̀nà tí ó yàn nígbà tí yóò fi pé ẹni ọdún ẹ̀tàdínlọgún wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ni ní edo college ní benin pẹ̀lú ìwọ̀nba ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àìgbẹ̀fẹ̀ ní òpin àárín 1950 ó jẹ́ ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ ní royal college of art london lẹ́yìn tí iṣẹ́ rẹ̀ gba ìyìn pàtàkì nígbà ìṣàfihàn kan tí ó wáyé papọ̀ pẹ̀lú ìrìn àjò queen elizabeth's sí nàìjíríà
|
irene ogutu kenyan footballer irene ogutu jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 14 óṣu june ni ọdun 1987 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender fun team apapọ awọn obinrin lori bọọlu
|
phoeby okech kenyan footballer phoeby okech jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 10 óṣu october ni ọdun 1994 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens fc gẹgẹ̀bi midfielder
|
judith osimbo kenyan footballer judith osimbo jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 8 óṣu august ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun awọn obinrin gaspo
|
nelly sawe kenyan footballer nelly sawe jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti oun ṣere fun thika queens fc gẹgẹbi defender
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.