raw_text
stringlengths 2
128k
|
---|
mohammed salah mohammed salah je agbààbọlu lokunrin ti orilẹ ede egipiti bakan naa ni osi je agbaboolu fun iko liverpool ti liigi ile-geesi ti a mosi premier league won bii ni ojo karundinlogun osu kefa odun 1992 oje ogbontarigi agbaboolu iwaju fun iko liverpool bakan naa ni captain fun iko orilede egipti oje agbaboolu ti a kole foworoseyin ni ile afrika ati ni agbaye lapapo
|
thierry ndikumwenayo thierry ndikumwenayo ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon osu keta odun 1997 je elere ije olona jinjin orile - ede burundi ni ọdun 2019 o dije ninu mita 10000 awọn ọkunrin ni idije awọn ere-idaraya agbaye ti 2019 ti o waye ni doha qatar ko pari ije re ni ọdun 2014 o gba ami-eye fadaka ni idije mita 3000 ti awọn ọmọkunrin ni olimpiiki igba ooru ọdun 2014 ti o waye ni nanjing china ni ọdun 2017 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 iaaf world cross country championship ti o waye ni kampala uganda o pari ni ipo 95th ni ọdun 2019 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 iaaf world cross country championships ti o waye ni aarhus denmark o pari ni ipo 9th ni ọdun 2019 o bori idije awọn ọkunrin ni cross internacional de la constitución ti o waye ni alcobendas spain
|
rodrigue kwizera rodrigue kwizera ti a bi ni ọjọ kewa oṣu kẹwa ọdun 1999 jẹ olusare-jinjinna ọmọ orilẹ-ede burundi kan ni ọdun 2019 o dije ni ìdíje awọn mita 10000 awọn ọkunrin ni idije awọn ere-idaraya agbaye ti 2019 ti o waye ni doha qatar o pari ni ipo 16th ni 2017 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 iaaf world cross country championship ti o waye ni kampala uganda o pari ni ipo 39th ni ọdun 2019 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 iaaf world cross country championships ti o waye ni aarhus denmark o pari ni ipo 11th ni ọdun 2019 o tun ṣe aṣoju burundi ni awọn ere afirika 2019 ti o waye ni rabat morocco o dije ninu awọn mita 5000 awọn ọkunrin o si pari ni ipo 16th
|
jean-paul gahimbaré jean-paul gahimbaré ti a bi ni ọjọ kejilelogun oṣu kejila ọdun 1970 jẹ elere-ije ọmọ ilu burundi kan ti o ṣe amọja ni ere-ije gigun ati ṣiṣe jijin gahimbaré dije ni olimpiiki igba ooru 2004 ni athens nigbati o wọ ere-ije ṣugbọn ko pari ere-ije naa
|
onesphore nzikwinkunda onesphore nzikwinkunda ti a bi ni ọjọ kewa osu okudu ọdun 1997 jẹ elere ije jinjinna ọmọ orilẹ-ede burundi ti o nsa ni mita 5k ati 10k ni ọdun 2019 o dije ninu mita 10000 awọn ọkunrin ni idije awọn ere-idaraya agbaye ti 2019 ti o waye ni doha qatar o pari ni ipo 18th ni ọdun 2017 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 iaaf world cross country championship ti o waye ni kampala uganda o pari ni ipo 14th ni ọdun 2019 o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 iaaf world cross country championships ti o waye ni aarhus denmark o tun pari ni ipo 14th ni ọdun 2019 o tun ṣe aṣoju orilẹ-ede burundi ni awọn ere afirika 2019 ati pe o pari ni ipo 6th ninu mita 10000 ọkunrin
|
tharcisse gashaka tharcisse gashaka ti a bi ni ọjọ kejidinlogun oṣu kejila ọdun 1962 jẹ elere-ije ọmọ orilẹ-ede burundi kan ti o ṣe ni ere-ije ati ere ona jinjin gashaka dije ninu idije ere- ije fun orilẹ-ede burundi ni olimpiiki akọkọ ti orilẹ-ede wọn ni olimpiiki igba ooru 1996 ni atlanta nibiti o ti pari 90th pẹlu akoko 23255 ni ọdun 1997 gashaka gba ami-ẹri fadaka kan ni ere idaraya ni 1997 jeux de la francophonie ni awọn mita 10000
|
joslin bipfubusa joslin sharif bipfubusa ti a bi ni ọjọ kewa oṣu kẹwa ọdun 1984 jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede burundi oun na ni alabojuto burundi lọwọlọwọ iṣẹ iṣakoso bipfubusa ṣakoso burundi lakoko idije bangabandhu 2020 ni atẹle ise adaṣe ti o ti ṣakoso aigle noir ati ẹgbẹ burundi labẹ-20
|
olivier niyungeko alain olivier niyungeko ti a bi ni ọjọ kewa oṣu kẹwa ọdun 1970 jẹ olukọni bọọlu lati orilẹ-ede burundi ẹniti o jẹ oluṣakoso kẹhin ti burundi lakoko akoko 201213 niyungeko dari egbe agbabọọlu flambeau de l'est si akọle premier league burundi akọkọ wọn ọdun mẹta lẹhin idasile ni ọdun 2016 niyungeko ni wọn yan gẹgẹ bi oluṣakoso burundi ti o rọpo ahcene aït-abdelmalek
|
jentrix shikangwa kenyan footballer jentrix shikangwa jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 27 óṣu november ni ọdun 2001 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward fun fatih karagümrük sk
|
dorcas shikobe kenyan footballer dorcas shikobe jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 4 óṣu april ni ọdun 1989 arabinrin naa ṣere gẹgẹ defender fun lakatamia fc
|
cynthia shilwatso kenyan footballer cynthia shilwatso jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 23 óṣu july ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun edf logroño b
|
dorcas shiveka kenyan footballer dorcas shiveka jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti oun ṣere gẹgẹbi defender fun thika queens fc
|
topista situma kenyan footballer topista situma jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti oun ṣere gẹgẹbi forward fun vihiga queens fc
|
elizabeth wambui kenyan footballer elizabeth wambui jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun awọn obinrin gaspo fc
|
merceline wayodi kenyan footballer merceline wayodi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 5 óṣu july ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun vihiga queens fc gẹgẹbi midfielder
|
belly-cresus ganira belly-cresus ganira ti a bi ni ọjọ karundinlogbon oṣu kẹta ọdun 2000 jẹ oluwe omi omo orilẹ-ede burundi o dije ninu idije ere idaraya 100m ti awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 2020 akoko rẹ ti iseju aaya 5433 ko to lati gbe de ipari
|
hamadou evelé hamadou evelé ti a bi ni ọjọ karundinlogun oṣu kẹwa ọdun 1949 jẹ elere idaraya ara kamẹru o dije ninu ifo giga ti ọkunrin ni awọn olimpiiki igba ooru 1972
|
fernand djoumessi fernand djoumessi temfack ti a bi ni ọjọ karun oṣu kẹsán 1989 jẹ elere-ije ifo fifo giga ti ilu kamẹrika o gba ami-eye idẹ ni 2010 african championship o se ipo kẹrin ni ipari idije 2011 gbogbo-afrika games ipo kẹrin naa ni 2013 jeux de la francophonie ipo keje ni 2014 commonwealth games 2014 tun gba ami eye fadaka ni 2014 african championships o si pari ni ipo keje ni 2014 continental cup ti ẹni ti o dara julọ jẹ awọn mita 228 ti o waye ni okudu 2014 ni bühl
|
esau adenji esau adenji ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kini ọdun 1944 jẹ olusareona gigun- fun orilẹ-ede kamẹru o dije ni mita 5000 ni olimpiiki igba ooru 1968 ati olimpiiki igba ooru 1972
|
esaie fongang esaie fongang ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn oṣu kẹjọ ọdun 1943 jẹ olusare aarin ti orilẹ-ede kamẹru o dije ninu mita 1500 ti awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1972
|
paul kuété paul kuété ti a bi ni ogun 'jo oṣu kejila ọdun 1972 jẹ olusare ona gigun ara orilẹ-ede kamẹru o dije ninu ere -ije awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1992
|
jean-pierre abossolo-ze jean-pierre abossolo-ze ti a bi ni ọjọ kejidinlogun oṣu kejila ọdun 1956 jẹ asare orilẹ-ede kamẹru o dije ninu isọdọtun mita 4 × 400 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1984
|
idrissa adam idrissa adam ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn osu kejila ọdun 1984 je elere-ije orile-ede cameroon ti o dije ninu 100 mita and 200 mita ijade agbaye akọkọ rẹ wa ninu idije ere idaraya junior ti afirika ni ọdun 2003 nibiti o ti gbe ipo karun ni 100mita o gba ami-eye akọkọ ipele continental rẹ ni ọdun ti ọ tele o gba ami- eyẹ idẹ ni 4 × 100 mita ni ere idaraya afirika ni ọdun 2004 ni ẹgbẹ kanna pẹlu joseph batangdon o jẹ ọdun mẹrin ki o to gba ami-eye pataki miiran ni ere idaraya afirika ni ọdun 2008 oun ati batangdon tun gba idẹ pada fun cameroon o gbe ipo kẹrin ni ere idaraya yẹn ni 2009 jeux de la francophonie o ṣe aṣoju fun orilẹ-ede cameroon ni 100 ati 200 m ninu àwọn ìdíje mejeeji wonyi 2010 african championships in athletics ati 2010 commonwealth games sugbon ko ni ilọsiwaju kọja ipele akoko o fi ara rẹ mulẹ bi olusare ni 2011 gbogbo awon ere idaraya afirika nibiti o ti ṣe itan titun bale fun orilẹ-ede kamẹru pelu 1014 iṣẹju-aaya ni 100 m ologbele-ipari o tun wa pari si ipo kẹfa ati pe o jẹ olubori iyalẹnu ti 200 m goolu medal saaju ben youssef meité
|
jean tarcisius batamboc jean tarcisius batamboc ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kewa ọdun 1987 elere ije orilẹ-ede cameroon ti oun sa 100 mita o dije ninu ìdíje 2011 all-africa games 2012 african championships 2014 african championships ati 2015 african games lai k'ogo ja ipele ipalemo o tun didje ni 2017 world championships ti o fi wa ni ikehin ni ipalemo ìdíje naa gẹgẹbi ara ti ẹgbẹ agbapada mita 4 × 100 ti orilẹ-ede kamẹru o pari ni ipo kaarun ninu idije afirika 2012 ati ipo kẹfa ni idije afirika 2014
|
melody gabriella abreu severino diẹ mọ bi melody je olorin omo orile-ede brazil
|
emmanuel bitanga emmanuel bitanga ọjọ karun osu kọkànlá ọdun 1953 ọjọ kesan oṣu kejila odun 2008 je omo orile-ede cameroon sprinter o dije ninu mita 200 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1984
|
emmanuel eseme emmanuel aobwede eseme ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu kejo ọdun 1993 je elere ije orile-ede cameroon o dije ninu mita 200 awọn ọkunrin ni idije ere-idaraya agbaye ti 2019 ti o waye ni doha qatar o ko pe lati dije ninu ologbele-ipari ni ọdun kanna o tun dije ninu mita 200 ọkunrin ati ìdíje 4 × 100 awọn ọkunrin ni awọn ere afirika laisi gbigba ami-eye kankan ninu ìdíje mejeeji o ṣe aṣoju orilẹ-ede cameroon ni olimpiiki igba ooru 2020 ni tokyo japan ni mita 200 ti awon ọkunrin
|
gaston malam gaston malam ti a bi ni ọjọ kẹjo ọsu keje ọdun 1952 je omo orile-ede cameroon o dije ninu ìdíje mita 100 ti awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1972
|
mama moluh mama moluh ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon oṣu kẹta ọdun 1958 jẹ asare orilẹ-ede kamẹru o dije ninu ìdíje mita 400 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1984
|
benjamin sirimou benjamin sirimou ti a bi ni ọjọ kankandinlogun osu kaarun ọdun 1969 je orile-ede cameroon ni idije 1996 afirika o gba ami-ẹri fadaka ni mita 100 o tun dije ni awọn ere-idije agbaye ni ọdun 1995 ati 1997 ati ni 4 x 100 m relay ni idije ti ọdun 1996 ati 2000 olimpiiki igba ooru laisi de ipari
|
ernestina abambila ghanaian footballer ernestina abambila jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede ghana ti a bini 30 óṣu december ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun uks sms lódz gẹgẹbi midfielder
|
hamdya abass hamdya abass tí a bí ní ọjọ́ kinni oṣù kẹjọ ọdún 1982 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin àgbáyé ti ilẹ̀ ghana kan tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí asọ́lé ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède ghana ó wà lára àwọn tí ó kópa pẹ̀lú 2007 fifa women's world cup nípa ikọ̀ ẹgbẹ́ ó ṣeré fún ghatel ladies ní ghana
|
mukarama abdulai ghanaian association football player mukarama abdulai jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 16 óṣu october ni ọdun 2002 arabinrin naa ṣere fun deportivo alavés gloriosas gẹgẹbi striker
|
juliet acheampong ghanaian footballer juliet acheampong jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 11 óṣu july ni ọdun 1991 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹ̀bi midfielder fun ånge if
|
azume adams azuma adams tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 1997 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède ghana kan tí ó ń ṣeré gẹ́gẹ́ bíi asọ́lé ó ti farahàn nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ méjì fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ti orílẹ̀-ède ghana ti ẹgbẹ́ under-17 ó wà lára wọn ní bi fifa u-17 women's world cup ti ọdún 2012 fifa u-17 women's world cup ti ọdún 2014 àti fifa u-20 world cup ti ọdún 2016
|
grace adams ghanaian footballer grace adams jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ keji óṣu november ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin berry fc gẹgẹbi midfielder
|
elizabeth addo ghanaian footballer born 1993 elizabeth addo jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu september ni ọ̀dun 1993 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward fun djurgårdens if
|
issa-aimé nthépé issa-aimé nthépé ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon okudu ọdun 1973 ni douala jẹ elere ije faranse kan ti o ṣa ni mita 100 o yipada orilẹ-ede lati orilẹ-ede ibi rẹ cameroon ni ọdun 1999 ni 2002 european championships o pari ni ipo karun ni mita 100 ati kẹrin ni 4 x 100 mita yii o de ipele keji si asekagba ti ere idaraya agbaye 2003 o pari ni ipo keje pẹlu ẹgbẹ agbapada faranse ni 2006 iaaf world cup awọn akoko ti o dara julọ ti ara re jẹ awọn aaya 1011 ni 100 m ati 2058 aaya ni 200 m mejeeji ṣaṣeyọri ni igba ooru ti ọdun 2002
|
ernest tché-noubossie ernest tché-noubossie ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon osu keji odun 1956 je elere-ije omo orile-ede cameroon o dije ninu mita 400 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988
|
david njitock david njitock ti a bi ni ọjọ ketadinlogun osu okudu ọdun 1942 jẹ asare ọmọ orile-ede kamẹru o dije ninu mita 100 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1964
|
emmanuel ngom priso emmanuel ngom priso ti a bi ni ọjọ keedogun oṣu kejila ọdun 1984 jẹ elere idaraya faranse kan ti o je omo orilẹ-ede kamẹrika ti o ṣe elere idaraya ni ipele sprinting pupọ julọ ninu aṣeyọri rẹ wa ni iṣipopada mita 4 x 100
|
barnabé messomo barnabé messomo ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon osu kejo odun 1956 je elere-ije omo orile-ede cameroon kan o dije ninu mita 100 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1984
|
claude toukéné-guébogo claude toukéné-guébogo ti a bi ni ọjọ karundinlogbon oṣu keji ọdun 1975 je elere ije lati orile-ede kameroon o dije ninu isọdọtun mita 4 × 100 awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1996
|
charly ndjoume charly ndjoume ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu kọkanla ọdun 1986 jẹ oluwe odo omo orilẹ-ede kamẹru o dije ninu ere idaraya 50 mita awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 2020
|
cole shade sule cole shade sule ti a bi ni ọjọ karun ni oṣu kọkanla ọdun 1980 jẹ oluwe ómí tẹlẹri lati orilẹ-ede kamẹru ti o je elere idaraya ni isọri-sprint sule yege fun 50 m freestyle awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 2004 ni athens nipa gbigba ogbontarigi ami eye kan lati fina ni akoko iwoleti 2596 o koju awọn oluwẹiwẹ meje miiran ninu ooru mẹta pẹlu chris hackel eni omo ọdun merindinlogun ti orilẹ-ede mauritius o sare si ipo keji kere ju 017 ti iṣẹju kan lẹhin olubori hackel ni 2616 sule kuna lati lọ siwaju si ipele semifinals bi o ti gbe erinlelogota ninu 86 odo ninu ìdíje igbaradi fun ìdíje
|
paul edingue ekane paul edingue ekane ti a bi ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹsan ọdun 1990 jẹ oluwẹiwẹ ara orilẹ-ede kamẹru ti o je ogbontarigi ni ọfẹ o dije ninu ipele 50 m ni awọn olimpiiki igba ooru 2012 o gbe ipo kẹfa ninu ooru rẹ ati nitori naa ko ṣe deede fun ologbele-ipari ti ipele naa ekane jẹ ọkan ninu awọn elere idaraya meje ti orilẹ-ede kamẹru ti o ṣa kuro abule olympic lakoko olimpiiki ti o fa akiyesi pe wọn yoo gbiyanju lati ṣalọ si united kingdom
|
alain brigion tobe alain brigion tobe ti a bi ni ọjọ kefa oṣu kọkanla ọdun 1986 jẹ oluwẹwẹ ara orilẹ-ede kamẹru ti o je ogbontarigi ninu ipele isọdi-ije tobe ṣe aṣoju orilẹ-ede kameru ni olimpiiki igba ooru 2008 ni ilu beijing o si dije fun ipele 50 m ti awọn ọkunrin o ṣẹgun ìdíje ooru karun ni ipele naa pẹlu akoko ti iseju aaya 2453 ti pari ọgọtalekan ninu ipo gbogbogbo
|
jean-rené akono jean rené akono ti a bi ni 1967-- 4 1967 jẹ agbabọọlu afowogba ati olukọni ọmọ orilẹ-ede cameroon o jẹ ara ti ẹgbẹ agbabọọlu folliboolu ti orilẹ-ede cameroon ni ogorun ere idaraya pẹlu iṣẹgun 1989 ni idije afirika o ṣere fun amacam ni gẹgẹ bi ẹgbẹ rẹ akono di olukọni ti ẹgbẹ bọọlu afowogba ti orilẹ-ede cameroon o ṣe olukẹkọ ẹgbẹ obinrin ni olimpiiki igba ooru 2016
|
serge edongo serge edongo ti a bi ni ọjọ ketadinlogun oṣu karun ọdun 1982 o jẹ agbabọọlu afowogba ti orilẹ-ede kamẹru o ti feyinti lọwọlọwọ ipo rẹ lori aaye jẹ idakeji hitter ati lẹhin ti o fihenti iṣẹ rẹ o tun si n kekọ edongo ti ṣiṣẹ tẹlẹ fun awọn ẹgbẹ ni cameroon gabon tunisia qatar bahrain spain france o gba awọn ami-ẹri ti ara ẹni gẹgẹbi oṣere ti o dara julọ ti odun ni ilu kamẹru ati gabon ipo keta ti o dara julọ ni cairo egypt edongo ti kọkọ je oludari tẹlẹ fun egbe àwọn omọ obinrin ti ẹgbẹ villers cotterets vb n3 2010/2013 n2 reims metropole vb 2014/2017 o ti n ṣere fun orile-ede cameroon lati ọdun 1999
|
brice batchaya brice vivien batchaya ketchanke ti a bi ni ọjọ kerindinlogun oṣu kẹjo ọdun 1985 jẹ agbẹru wiwuwo ara orilẹ-ede kamẹru batchaya ṣe aṣoju orilẹ-ede cameroon ni olimpiiki igba ooru 2008 ni ilu beijing nibiti o ti dije fun kilasi iwuwo iwuwo ina ti awọn ọkunrin 85 kg batchaya gbe ipo kẹrinla ninu ipele yii bi o ti gbe 153 ni aṣeyọri kg ninu jija-gba ẹeyankan o si gbe iwon 180kg soke ni apa meji ejika-si-oke ti o mọ ati ari fun apapọ 333 kg
|
frederic fokejou frederic fokejou tefot ti a bi ni ọjọ keta oṣu kejila ọdun 1979 ni bafoussam orile edè cameroon jẹ agbẹru iwuwo ara orilẹ-ede kamẹru o dije ni olimpiiki igba ooru 2012 ni iṣẹlẹ +105 kg
|
alphonse hercule matam alphonse hercule matam ti a bi ni ọjọ kini oṣu kẹrin ọdun 1973 jẹ agbẹru iwuwo ara orilẹ-ede kamẹru o dije ninu ipele iwuwo ina ti awọn ọkunrin nn olimpiiki igba ooru 1992
|
njuh venatius njuh venatius ti a bi ni 1988-- 13 1988 je omo orile-ede cameroon ti o n gbe eru wiwo okunrin ti o nfigagba ninu eya 69 kg ati ti o nsoju orilẹ-ede cameroon ni awọn idije agbaye o dije ni ere-idije agbaye laipẹ o jẹ aṣaju-idije iwuwo agbaye 2010
|
vivian adjei ghanaian association football player vivian adjei jẹ agbabọọ̀lu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 14 óṣu january ni ọdun 2000 agbabọọlu naa ṣere fun thunder queen fc gẹgẹbi ipo forward
|
cynthia adobea ghanaian footballer cynthia adobea jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu august ni ọdun 1990 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
|
agnes aduako ghanaian footballer agnes aduako jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 25 óṣu december ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi fun forward
|
princella adubea ghanaian footballer princella adubea jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ̀ ghana ti a bini 27 óṣu december ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere fun racing de santander gẹgẹbi ipo forward
|
anita amenuku anita amenuku tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù keje ọdún 1985 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ará ilẹ̀ ghana kan tí mú ipò iwájú lórí pápá ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède ghana ó wà lára àwọn tí ó kópa níbi fifa women's world cup ti ọdún 2007 lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún ghatel ladies ní ghana ó kọ́kọ́ fara hàn lórí pápá fún ghana lòdì sí australia ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹẹ̀sán ọdún 2007
|
anita amankwa ghanaian footballer anita amankwa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ keji óṣu september ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward
|
gladys amfobea ghanaian footballer gladys amfobea jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu july ni ọdun 1998 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender
|
olivia amoako ghanaian footballer olivia amoako jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 30 óṣu september ni ọdun 1985 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin ghatel gẹgẹ̀bi defender
|
karim abdel gawad karim abdel gawad ti a bi ni ọgbon'jọ oṣu keje ọdun 1991 ni alexandria jẹ agbabọọlu elegede ti o ti ṣe aṣoju orilẹ-ede egypt o de ipo kinni iṣẹ-giga ti agbaye 1 ni oṣu karun ọdun 2017 ni oṣu kọkanla ọdun 2016 o gba 2016 world open squash championship ni cairo ni orilẹ-ede egipti nigbati o dujoko ramy ashour o di ara orilẹ-ede egipti kẹta lati gba asiwaju agbaye lẹhin amr shabana ati ramy ashour
|
petit minkoumba petit david minkoumba ti a bi ni ọjọ ketadinlogbon oṣu keji ọdun 1989 jẹ agbẹru wuwo ara orilẹ-ede kamẹru o dije ni olimpiiki igba ooru 2016 ni rio de janeiro ni 94 kg ti awọn ọkunrin o dije ni ere-idije agbaye laipẹ lọwọlọwọ ni ìdíje fun aṣaju-idije eruwuwo agbaye 2009 ni oṣu kẹrin ọdun 2018 o jẹ ọkan ninu awọn elere idaraya mẹjọ ti orilẹ-ede cameroon ti won ko ri mo ere agbaye 2018
|
basilea amoa-tetteh ghanaian footballer basilea amoa-tetteh jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 7 óṣu march ni ọdun 1984 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward
|
simon ngamba simon isidore ngamba ti a bi ni 1982-- 24 1982 je ara orilẹ-ede kamẹru ọkunrin ti o nfigagba ninu ẹka eruwuwo 62 kg gbigbe ati aṣoju orilẹ-ede cameroon ni idije agbaye o dije ni ere-idije agbaye ati laipẹ ni aṣaju-idije iwuwo agbaye 2009 o kopa ninu ere agbaye 2010 ni ipele 62 kg
|
faustina ampah ghanaian defender faustina ampah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 30 óṣu november ni ọdun 1996 agbabọọlu naa ṣere fun fc minsk gẹgẹbi defender
|
théodore nkwayed théodore nkwayed ojoibi 6 march 1967 je omo ilu kamẹru o dije ninu ìdíje gbigbe irinwuwo awọn ọkunrin ni olimpiiki igba ooru 1988
|
mahamat idriss mahamat idriss ne koundja ouya ọjọketadinlogun keje ọdun 1942 ọjọ keta oṣu kẹwa ọdun 1987 jẹ olufoifo giga ti ti orilẹ-ede chad a bi ni fort-lamy chad faranse equatorial africa iṣẹ-ṣiṣe ṣaaju ominira orilẹ-ede chad ni ọjọ kankanla oṣu kẹjọ ọdun 1960 o dije fun orile edè faranse ti o bori aṣaju orilẹ-ede faranse ni ọdun 1960 ati 1961 o tun pari ni ipo kejila ni ere olimpiiki 1960 lakoko ti o nsoju orilẹ-ede faranse fun chad o pari ni ipo kẹsan ni ere olimpiiki 1964 o tun jẹ ipo ti o dara julọ ti orilẹ-ede chad lailai ni ere ìdíje olympic lori track and field news ni ipo agbaye lododun idriss gbe ipo kẹsan ni ọdun 1961 kẹwa ni ọdun 1964 ati kẹjọ ni ọdun 1966 fifo ti ara ẹni ti o dara julọ jẹ mita 217 ti o waye ni oṣu kẹrin ọdun 1966 ni fort-lamy eyi tun jẹ ami eyé ti orilẹ-ede chad botilẹjẹpe o ti dọgba pelu paul ngadjadoum ati mathias ngadjadoum ni ọdun 1993 ati 1996 lẹsẹsẹ
|
ahmed senoussi ahmed senoussi ti a bi ni oṣu kini ọjọ 22 ọdun 1946 jẹ olufo giga ti orilẹ-ede chad tẹlẹ o pari ni ipo kejila ni ipari fifo giga ni ere olimpiiki 1968 o tun dije ninu ere olimpiiki 1972 laisi dey ipari
|
paul ngadjadoum paul ngadjadoum ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kẹwa ọdun 1957 jẹ ọmọ orilẹ-ede chad olufoifo tẹlẹri ti o dije ni olimpiiki igba ooru 1988
|
made kuti omorinmade kuti tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1995 tí a mọ̀ látàrí iṣẹ́ rẹ̀ sí made kuti jẹ́ olórin orílẹ̀-èdèoǹkọ̀rin àti onímọ̀ nípa ẹ̀rọ-ìkọrin ó ṣe àgbéjáde orin àkọ́kọ̀-gbé-síta rẹ̀ forward ní ọdún 2021
|
christ koumadje jean marc christ koumadje ti a bi ni ọjọ keje oṣu keje 1996 jẹ agbabọọlu inu agbọn alamọdaju kan fun alba berlin ti bundesliga bọọlu inu agbọn ile-iwe giga koumadje gba bọọlu inu agbọn ile-iwe giga ni ile- ẹkọ giga montverde ni montverde florida nibiti o ti jẹ ẹlẹgbẹ pẹlu ben simmons iṣẹ ile-ẹkọ giga koumadje gba bọọlu inu agbọn kọlẹji ni ipinle florida lakoko akoko agba rẹ ni fsu koumadje ṣe aropin aaye 66 fun ere atungba 56 fun ere bulọọki 14 fun ere ati ni iṣẹju 155 dun fun ere kan iṣẹ ọjọgbọn delaware blue coats 20192020 lẹhin ti won ko riyan mo ara awon yiyan fun 2019 nba o fowo si iwe pẹlu philadelphia 76ers won ge nigba ibudó ikẹkọ ati pe a fi kun si iwe akọọlẹ ibudó ikẹkọ ati ṣi ti alaalẹ ti delaware blue coats alafaramo nba g league ti 76ers koumadje ni ami mọkàndínlogun atungba mewa ati bulọọki marun ninu ifẹsẹwọnsẹ 114-107 pelu raptors 905 ni ọjọ kerinla oṣu kejila nl ọjọ kẹrin oṣu kinni ọdun 2020 koumadje ṣe igbẹle ilọpo-mẹta ni ibori won ni 111-88 lori long island nets ti o ti fi ami mejila sile atungba 16 ati igbasile oluranlowo bulọọki mejila kan ninu ere mewa to kẹhin ti akoko ti won ge kuru 201920 g koumadje ṣe ida aarin aaye 118 atungba 128 ati bulọọki 58 fun ere kan jiju 66 lati aaye naa o gba ami eye fun nba g league defensive player ti odun movistar estudiantes 2020 ni ọjọ kankanlelogun oṣu kẹsan ọdun 2020 movistar estudiantes kede pe wọn ti fowo si iwe pelu koumadje avtodor saratov 20202021 ni oṣu kejila ọgun'jo ọdun 2020 o ti fowo si iwe pẹlu avtodor ti vtb united league alba berlin 2021-bayi ni ọjọ karundinlogbon oṣu keji ọdun 2021 alba berlin kede pe wọn ti fowo si iwe pẹlu koumadje titi di opin akoko 2022-23
|
richard moguena richard moguena ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kẹsan ọdun 1986 jẹ oṣere bọọlu inu agbọn alamọdaju ọmọ orilẹ-ede chad lọwọlọwọ o ngba fun as africana ti d1 chad o ṣe aṣoju ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede chad ni 2011 fiba africa championship ni antananarivo madagascar nibiti o ti jẹ atungba ti o dara julọ ti ẹgbẹ rẹ ati eniti o mo bọọlu ofe ju
|
abderamane mbaindiguim abderamane mbaindiguim ti a bi ni ọjọ kinni oṣu kẹta ọdun 1982 jẹ agbá bọọlu inu agbọn alamọdaju ti orilẹ-ede chad lọwọlọwọ o nṣere fun csm constantine sports club ti algerian basketball championship mbaindiguim jẹ ọkan ninu awọn agba bọọlu inu agbọn olokiki julọ ni orilẹ-ede chad o gba awọn iṣẹju pupọ julọ ati awọn aaye pupọ julọ fun ẹgbẹ bọọlu inu agbọn orilẹ-ede chad ni 2011 fiba africa championship ni antananarivo madagascar abderamane mbaindiguim gba bọọlu inu agbọn fun awọn ẹgbẹ wọnyi
|
noureddine aman hassan noureddine aman hassan ti a bi ni ọjọ keje oṣu karun ọdun 1943 jẹ afẹṣẹja kan ti o dije ni kariaye fun egypt hassan ṣe aṣoju chad ni 1972 summer olympics ni munich ni light-heavyweight kilasi ni ipele akoko ti o doju ko ara orilẹ-ede yugoslavia mate parlov won da duro ni ipele keji mate parlov si tẹsiwaju lati gba ami-ẹri goolu
|
casimir betel casimir betel ti a bi ni ọjọ ogun oṣu kẹjo ọdun 1997 jẹ elere idaraya taekwondo ti orilẹ-ede chad kan o gba ami-eye idẹ kan ninu idije ere afirika 2019 ni ẹka awọn ọkunrin -58 kg
|
sakor rodet sakor rodet ti a bi ni ọjọ keta oṣu kẹjo ọdun 1967 jẹ judoka kan ti o dije kariaye fun orile-ede chad rodet ṣe aṣoju orilẹ-ede chad ni olimpiiki igba irẹdanu ewe 1992 ni ilu barcelona ni ẹka idaji-iwọn iwuwo 60-66 kg o padanu ni ipele akokọ si jorge steffano lati orilẹ-ede urugue nitorina ko ni ilọsiwaju
|
m'bairo abakar m'bairo abakar ti a bi ni ọjọ ketala osu kinni ọdun 1961 jẹ judoka kan ti o dije ni kariaye fun orilẹ-ede chad abakar ṣe aṣoju orilẹ-ede chad ni olimpiiki igba ooru 1992 ni ilu barcelona ninu -arin iwuwo -78 kg ẹka o gba a bye ni akọkọ yika sugbon ti won padanu si jason morris ni ipele keji nitorina o ko siwaju siwaju sii
|
ismail essam ismail essam ti a bi ni ọjọ karun oṣu kejo ọdun 1967 jẹ elere idaraya ati ojogbon lati orilẹ-ede egipti ó ń díje nínú tafàtafà essam dije ni olimpiiki igba ooru 2000 ati 2004 ni tafàtafà ẹni kọọkan ti awọn ọkunrin o ti ṣẹgun ninu ipele akọkọ ti imunikuro ni igba mejeeji gbigbe ipo 56th lapapọ ni 2000 ati 62nd ni 2004
|
ahmed el-nemr ahmed el-nemr ti a bi ni ọjọ kankanlelogun oṣu ọkànlá odun 1978 ni cairo ni orilẹ-ede egipti jẹ tafàtafà ara orilẹ-ede egipti o dije ninu iṣẹlẹ kọọkan ni london 2012 summer olympics ati rio 2016 olimpiiki igba otutu
|
ibrahim sabry ibrahim sabry jẹ tafàtafà ara orilẹ-ede egipti ti o kopa ni olimpiiki igba ooru ọdun 2010 ni orilẹ-ede singapore o gba ami-eye goolu ni iṣẹlẹ ti awọn ọmọkunrin ni ibi ti o ti bori rick van den oever ti netherlands ni ipari
|
abdulrazak gurnah abdulrazak gurnah frsl tí a bí ní ogúnjọ́ oṣù kejìlá ọdún 1948 jẹ onkọ̀wé nofẹli àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀ èdè tanzania tí o fi ìlú gẹ̀ẹ́sì united kingdom ṣe ibùgbé tí ó sì ní íwé àṣẹ gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ìlú gẹ̀ẹ́sì a bí i ní ni sultanate ti zanzibar ó sì gbéra lo sí ìlú geesi ní odun 1960 gege bi i asa asala fun emi ara eni ní àkókò rògbòdìyàn ní ìlú zanzibar lára àwon iwe re ti o ti ko ni párádísè 1994 èyí tí ó jé asayan fun ebun booker ati whitbread desertion 2005 ati by the sea 2001 eyi ti won ti koko se asayan re fun booker ti won si tun se asayan re fun ebun iwe ti i iwe iroyin los angeles los angeles times book prize gurnah ni o gba ami eye ti nobel prize ni litireso ni ọdun 2021 “fun aibikita ati irẹwẹsi aanu rẹ ti awọn ipa ti ijọba amunisin ati awọn ayanmọ ti asasala ni agbegbe gulf laarin awọn aṣa ati awọn continenti” o jẹ ọjọgbọn ti o peregede julo ninu imo geesi ati awon litireso fun ti postcolonial ni ile-eko giga yunifasiti ti kent ibere igbesi aye re ati ẹkọ a bi abdulrazak gurnah ni ogunjo osu kejìlá odún 1948 ni sultanate ti zanzibar eyiti o jẹ apakan ti tanzania loni o kuro ni erekusu nígbà tí ó di omo odún méjìdínlógún lehin ìgbàtí won gba ìjoba lowo gbajúmo lárúbáwá tí ó n se ìjoba ní àkókò rògbòdìyàn tí ó bé síle ni zanzibar iyika ni odún 1968 ni gurnah dé sí ile geesi gegebi i asáàsálà èyà lárúbáwá ni gurnah je tí bàbá àti àbúrò bàbá re je onísòwò tí wọ́n ṣí wá láti yemen gegebi gurnah ti sọ wípé mo wá sí ile geesi nigbati awọn ọrọ wọnyi gẹgẹbi olùwábi ààbò ko jẹ bakanna - awọn opo ènìyàn n tiraka tí won si n sare kuro ní awon ìpínle oníjàgídíjàgan o kọkọ kọ ẹkọ ni ile-ẹkọ giga christ church canterbury ile- eko tí o je wípé ilé-eko giga yunifasiti ilu london ni o ma n fun awon akeko ti o ba jade nibe ni iwe-eri ní àkókò náà leyin èyín ni ó lo sí ilé-ìwé gíga yunifásítì ti kent níbití ó ti gba oyé ìjìnle ti ojogbon phd pelu ìwé afowoko re ti akole re je criteria in the criticism of west african fiction ni ọdun 1982 iṣẹ-ṣiṣe láti odún 1980 sí odún 1983 gurnah se ise olúkoni ní ilé-eko gíga yunifásítì bayero tí ó wà ní kano ní orile-ede nàìjíríà leyinna ni o di ojogbon ninu eko geesi àti litiraso fun postcoloial ni ilé-eko gíga yunifásítì ti kent níbití ó ti se ise olùko títí ó fi feyinti ní odún 2017 ni bayi i ojogbon agba ninu eko geesi ati awon litiraso postcolonial ni ile-eko giga yunifásítì yi ni i se botilẹjẹpe awọn alariwisi se atewogba awon ìwé nofeli ti gurnah ko daradara sibe awon nofeli yi ko fibee ta daradara àti wípé won ko se ate jade awon nofeli yi ni ibòmíràn àfi i ìlú geesi nìkan lẹhin tí won ti fun ni ẹbun nobel fun litireso ni ọdun 2021 awọn olutewe jade ati awọn olutaja iwe tiraka lati le ba a dogba pelu igbega ti o de ba bibeere fun awon iwe re o je wípé leyin ti won kede ebun nobel yi ni gurnah gba awon ipe lati odo awon atewe jade lati orile-ede amerika lori nofeli re afterlives awọn iwe riverhead ngbero lati gbe e jade ni osu kejo odun 2022 riverhead tun gba awọn ẹtọ lori by the sea and desertion eyi ti i se meji ninu awon ise gurnah ti won ti jade lo fun tite jade kikọ pelu iṣẹ rẹ gege bi oluko ni ile-ẹkọ giga gurnah jẹ onkọwe ati eni o ma nko nofeli lorisirisi o ti ko ọpọlọpọ awọn itan kukuru awọn arosọ ati awọn nofeli mewaa nigba ti ede akọkọ rẹ jẹ swahili ede gẹẹsi ni o nlo gẹgẹbi ede ti o ma fi nko awo iwe re sibẹsibẹ gurnah lo die ninu awọn ede bi i swahili arabic ati german ninu pupọ awọn iwe rẹ ti o ti ko o so wipe oun ni lati pada so fun awon atewejade lati tesiwaju ise yii ati wipe won yio fe lati pe ki awon itokasi ati awon gbolohun oro lori ede swahili ati larubawa je ami italisi tabi anglicize ninu awon iwe re gurnah ti ṣofintoto awọn iṣe ninu iwe atẹjade ilu gẹẹsi ati amẹrika ti o fẹ lati “jẹ ki alejò dabi ajeji” nipa siṣamisi awọn ofin ati awọn gbolohun “ajeji” pẹlu awọn italics tabi nipa fifi wọn sinu iwe-itumọ gẹgẹbi omowe hamid dabashi se awon akosile pe gurnah jẹ pataki si ọna ti iriri awon ara ile asia ati awon ti nsi kiri ni ile afirika ati ni ilu okere ni ilọsiwaju ati iyipada ede gẹẹsi ati iwe-litiraso ti won si npe awon onkowe bi i gurnah diasporic exxilic tabi eyikeyi iru ọrọ alọlọ-ara-ẹni ti o fi otitọ pamọ pe gẹẹsi jẹ abinibi fun u paapaa ṣaaju ki o to lo si orile-ede alawo funfun england àwọn aláṣẹ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì ti gbé e wá sílé fún un”
|
barney
|
percy liza percy liza ojoibi 10 april 2000 ni chimbote jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede peru kan ti o ṣere fun sporting cristal ti peru premier division
|
rosemary ampem ghanaian footballer rosemary ampem jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 27 óṣu august ni ọdun 1992 agbabọọlu naa ṣere fun accra immigration gẹgẹbi defender
|
diana ankomah ghanaian footballer diana ankomah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 19 óṣu september ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere fun police accra gẹgẹbi forward
|
lydia ankrah ghanaian footballer lydia ankrah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu december ni ọdun 1973 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin post gẹgẹbi defender
|
akua anokyewaa ghanaian footballer akua anokyewaa jẹ agbabọọlu lobinrin ti a bini 15 óṣu october ni ọdun 1984 agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi forward
|
regina ansah ghanaian footballer regina ansah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 23 óṣu august ni ọdun 1974 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin bluna gẹgẹbi defender
|
regina antwi ghanaian association football player regina antwi jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 26 óṣu november ni ọdun 1995 agbabọọlu naa ṣere fun 1207 antalya spor gẹgẹbi defender
|
grace asantewaa ghanaian footballer grace asantewaa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghanan ti a bini 5 óṣu december ni ọdun 2000 agbabọọlu naa ṣere fun real betis gẹgẹbi defender
|
nana asantewaa ghanaian footballer nana asantewaa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 28 óṣu december ni ọdun 1993 agbabọọlu naa ṣere fun police accra gẹgẹbi goalkeeper
|
grace asare ghanaian footballer grace asare jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ gbana ti a bini 12 óṣu october ni ọdun 1989 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin reformers gẹgẹbi defender
|
philicity asuako ghanaian international footballer philicity asuako jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 25 óṣu december ni ọdun 1999 agbabọọlu naa ṣere fun thunder queens fc gẹgẹ̀bi defender
|
aramide sarumoh nigerian afro-soul singer and songwriter born 1985aramide sarumoh tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹfà ọdún 1985 tí a mọ̀ látàrí iṣẹ́ rẹ̀ sí aramide jẹ́ olórin àti óǹkọrin orílẹ̀-èdè nàìjíríà ó fi orin rẹ̀ iwo nikan gba àmì-ẹ̀yẹ iṣẹ́ ohùn tí ó dára jù lọ níbi ayẹyẹ headies ti ọdún 2015 aramide kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmò ìjìnlè nípa òṣèlú ní university of jos ní ọdún 2019 ilé-ẹ̀kọ́ the recording academy yan aramide sí ìgbìmò ìjọba ti ilé-ẹ̀kọ́ náà tí ó wà ní ilè washington dc
|
grace umelo grace umelo ti a bi ọjọ kewa osu keje ọdun 1978 jẹ elere-ije ọmọ orilẹ- ede naijiria ti fẹhinti ti o ṣe ere idaraya nii ti ifo gigun o gba awọn ami-ẹri pupọ ni ipele agbegbe ara rẹ ti o dara julọ ninu iṣẹlẹ jẹ mita 660 ti a ṣeto ni ilu eko ni ọdun 1999
|
yetunde odunuga yetunde odunuga ti a bi ni ọjọ kankandinlogun osu kọkànlá ọdun 1997 je afẹṣẹja orilẹede naijiria ti o gba ami ẹyẹ idẹ kan ni ere agbaye 2018 iṣẹ-ṣiṣe yetunde dije ni 2018 commonwealth games o gba ami idẹ ninu ìdíje middleweight pelu caroline veyre ni ọdun 2017 yetunde odunuga ti o je omo ologun ti nigerian army gba ami goolu ni ìdíje ti awon obinrin ni ipele women’s lightweight ninu ere ije african amateur boxing championships brazzaville congo
|
teke oruh teke oruh ti a bi ni ọjọ kẹjo ọsu kẹjo ọdun 1978 ni lagos ti inagijẹ re nje african prince jẹ afẹṣẹja agba lati orilẹ-ede nigeria oope oruh gba bronze ni 1999 gbogbo-ere afrika ise ọjọgbọn oruh ṣe akọṣẹ akọkọ rẹ ikọlu yika akọkọ ti gustavo robleto ni oṣu keje ọjọ 28 ọdun 2001 titi di oni igbasilẹ ọjọgbọn rẹ jẹ awọn bori 14 6 nipasẹ knockout ati pipadanu kan pẹlu iyaworan 1 lẹhin ti o ti ṣe afihan nipasẹ joey abell lori akoko ifihan
|
edem atovor ghanaian footballer edem atovor jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini 10 óṣu april ni ọdun 1994 arabinrin naa ṣere fun club israeli
|
yaa avoe ghanaian footballer yaa avoe jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ óṣu july ni ọdun 1982 agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin ash town gẹgẹbi defender
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.