_id
stringlengths 17
21
| url
stringlengths 32
377
| title
stringlengths 2
120
| text
stringlengths 100
2.76k
|
---|---|---|---|
20231101.yo_3442_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
sọ fún wa pé Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ni wọ́n bí i àti pé alágbára gidi ni, ó fi gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ kà fim ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà, ṣùgbọ́n nígbẹ̀hìn ó kú gẹ́gẹ́ bí alágbára, wọ́n sì sin ín gẹ́gẹ́ bí akíkanjú ọkùnrin. Wọ́n sọ ọ́ di òrìṣà kan pàtàkì ní ìlú gẹ́gẹ́ bí àwọn alágbára ayé ọjọ́un tí wọ́n ṣe gudugudu méje yààyàà mẹ́fà fún àwọn ènìyàn wọn, tí wọ́n kú tán tí wọ́n sì ti ipa bẹ́ẹ̀ sọ wọ́n di òriṣà àti ẹn ìbọ lóníì àwọn òrìṣà bí ògún, ọ̀ṣun, ṣàngó, ọbàtálá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ tí a ń gbọ́ orúkọ wọn jákèjádò ilẹ̀ Yorùbá lóde òní.
|
20231101.yo_3442_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Nígbà tí ó wà láyé, ó fẹ́ràn ìlù Àgàdá púpọ̀. Tí ogun bá sì wà, tí wọ́n bá ti ń lu ìlù náà, kí ó máa jà lọ láìwo ẹ̀nìyàn ni. Kò sì sí ìgbà tí wọ́n bá ń lu ìlù yí tí ogun bá wà tí kò ní ṣẹ́gun. Ìgbà tí ó sí kú, ìlù yí náà ni àwọn ọmọ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà máa ń lú tí ogun bá wà, ó sì di dandan kí àwọn áà borí irú ogun bẹ́ẹ̀.
|
20231101.yo_3442_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Orúkọ̀ míràn fún Àgàdá tún ni Dígunmọ́dò nítorí pé tí ogún bá ti ń bọ̀ láti wọ̀lú, ibi Ẹrẹ́jà ni ọkùnrin akíkanjú náà yóò ti lọ pàdé rẹ̀, kò sì ní jẹ́ kí ó wọ ìlú dé apá Ọ̀kèniṣà ti a ń pe ní orí ayé tí àwọn ènìyàn wà nígba náà. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pè é ní DÍGUNMÓDÒ –DÍ OGUN MỌ́ ODÒ. Títí di oní yìí, Ẹrẹ́jà náà ni wọ́n ti ń bọ ọ́ gẹ́gẹ́ bí ojúbọ rẹ̀.
|
20231101.yo_3442_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n ní “ẹjọ́ kì í ṣe tara ẹni ká má mọ̀ ọ́n dá” èyí ló jẹ́ kí n ronú dáadáa sí àwọn ìtàn méjì yí láti lè mọ eléyìí tí ó jẹ́ òótọ́ tí a sì lè fara mọ́. Gẹ́gẹ́ bí ìtán àtẹnudẹ́nu, àwọn olùsọ̀tàn ìtàn méjèèjì yí ló ń gbìyànjú láti sọ pé epó dun ẹ̀fọ́ wọn nítorí pé oníkálùkù ló ń gbé ìtàn tirẹ̀ lárugẹ. Ṣùgbọ́n ìgbà tí a wo ìsàlẹ̀ láti rí gùdùgbú ìgbá mo gba ìtàn tàkọ́kọ́ tí ó sọ pé ìlú Ilayè ni wọ́n ti mú un wá gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó jẹ́ òótọ́ jù lọ nítorí pé wọ́n máa ń ki òrìṣà náà bayìí pé
|
20231101.yo_3442_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
gbèjà Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà lákòókó ogun; ìrókò náà jẹ́ ọ̀kan. Akíkanjú ni òun náà tí kì í gbọ́ ẹkún ọmọ rẹ̀ kó má tatí were” ni tirẹ̀. Nígbà kan rí, a gbọ́ wí pé òrìṣà ìlú Ejíkú3 ni ìrókò jẹ́ ṣùgbọ́n ìgbà gbogbo ni ogún máa ń yọ ìlú yìí lẹ́nu tí wọ́n sí máa ń kó wọn lọ́mọ lọ. Nígẹ̀hìn, wọ́n wá ìrànlọ́wọ́ wá sí ọ̀dọ̀ Ọba Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà ò sì ràn wọnm lọ́wọ́ láti ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá wọn. Nígbà tí Èkíjú rójú ráyè tán ni wọ́n bá kúkú kó wá sí ilú Ìjẹ̀bú -Jẹ̀ṣà láti sá fún ogun àti pé ẹni tí ó ran ni lọ́wọ́ yìí tó sá tọ̀ ìgbà tí ìlú méjì yí di ọ̀kan ni òrìṣà tí ó ti jẹ́ tí Èjíkú tẹ́lẹ̀ bá di ti Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà nítorí pé ìgbà tí Èjíkú ń bọ̀ wá sí Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà, wọ́n gbé òrìṣà wọn yìí lọ́wọ́. Gbogbo ìgbà tí ogun bá dìde sí Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà náà ni ìrókò yí máa ń dìde láti sa gbogbo ipá ọwọ́ rẹ̀ láti gbèjà ìlú náà. Ológun gidi ni ìtàn sì sọ fún wa pé òun náà jẹ́ látàárọ ọjọ́ wá. Ṣé ẹni tí ó ṣe fún ni là ń ṣe é fún; èyí ni ìrókò náà ṣe máa ń gbé ọ̀rọ̀ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà karí tí nǹkan bá dé sí i láti fi ìwà ìmoore hàn tún ìlú náà. Ìdílé kan pàtàkì ni Èjíkú tí a ń sòrọ̀ rẹ̀ yí jẹ́ nílùú Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí, àwọn sì ni ìran tí ń sin tàbí bọ òrìṣà ìrókò yí. Olórí tàbí Ọba Èjíkú sì jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìwàrẹ̀fà mẹfà ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà lónìí.
|
20231101.yo_3442_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Lẹ́hìn ìgbà tí òrìṣà yí tit i ìlú Ìlayè dé Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà tí Ọba sì ti gbé e kalẹ̀ sí Ẹrẹ́jà, ló ti fi olùtọ́jù tì í. Ọbalórìṣà ni orúkọ rẹ̀ tí ó jẹ́ agbátẹrù òrìṣà náà.
|
20231101.yo_3442_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
“Ẹni tí ó ṣe fú ni là ń ṣe é fún” “ẹni tí a sì ṣe lóore tí kò mọ̀ ón bí a ṣe é ní ibi kò búrú”kí àwọn ọmọ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà má bà a jẹ́ abara – í móore - jẹ ni gbogbo wọn ṣe gba òrìṣà yí bí Ọlọ́run wọn tí wọ́n sì ń bọ́ ọ́ lọ́dọọdún.
|
20231101.yo_3442_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Àwọn tó ń bọ́ ọ́ pín sí mẹ́rin. Olórí àwòrò òrìṣà àgàdá ni Ọbalórìṣà tí ó jẹ́ agbàtẹrù òrìṣà náà. Aṣojú ọba Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà ló jẹ́ fún òrìṣà náà “Omi ni a sì ń tẹ̀ ká tó tẹ iyanrìn” bí ọbá bá fẹ́ bọ Àgàdá, ọbalórìṣà ni yóò rìí. Bí àwọn ọmọ ìlú ló fẹ́ bọ ọ́, Ọbalòrìṣà náà ni wọn yóò rí pẹ̀lú.
|
20231101.yo_3442_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Ìsọ̀ngbè ọbalórìṣà nínú bíbọ Àgàdá ni àwọn olórí ọmọ ìlú. Àwọn olórí-ọmọ yìí ló máa ń kó àwọn ọmọ ìlú lẹ́hìn lákòókó ọdún Àgàdá náà láti jó yí ìlú káákiri àti láti máa ṣàdúrà fún ìlọsíwájú ni gbobgo ìkóríta ìlú. Ọba ìlú náà ní ipa pàtàkì tirẹ̀ làti kó. Òun ló ń pèsè ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lódọọdún láti fí bọ òrìṣà náà èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú àdéhùn rẹ̀ ní ìgbà tó gba òrìṣà náà òun yóò máa fún un ní ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan lọ́dọọdún títí dòní ló sì ń ṣe ìràntí ìlérí rẹ̀ ọjọ́ kìíní.
|
20231101.yo_3442_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A0d%C3%A1%20n%C3%AD%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-J%E1%BA%B9%CC%80%E1%B9%A3%C3%A0
|
Àgàdá ní Ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà
|
Wàyí o, gbogbo ìlú ni wọ́n ka ọdún díde láti ṣe ọdún náà tọkùnrin tobìnrin, tọmọdé tàgbà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ Ìjẹ̀bú - Jẹ̀ṣà tí ó wà ní ìdálẹ̀ ni yóò wálé fún ọdún náà. Gbogbo ìlú ló sì máa ń dùn yùngbà tí wọ́n bá ń ṣe ọdún náà lọ́wọ́.
|
20231101.yo_3486_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Samuel%20Ladoke%20Akintola
|
Samuel Ladoke Akintola
|
Samuel Ladoke Akintola (July 6, 1906 - January 15, 1966) je oloselu omo orile ede Naijiria lati eya Yoruba ni apa ila oorun. A bi ni ojo kefa osu keje odun 1906 ni ilu Ogbomosho.
|
20231101.yo_3486_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Samuel%20Ladoke%20Akintola
|
Samuel Ladoke Akintola
|
Wọ́n bí Sámúẹ̀lì sínú ìdílé Akíntọ̀lá ní ìlú Ògbómọ̀ṣọ́, bàbá rẹ̀ ni Akíntọ̀lá Akínbọ́lá nígba tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Àkànkẹ́ Akíntọ̀lá. Bàbá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò tí ó jáde wá láti inú ẹbí oníṣòwò. Nígbà tí ó kéré jọjọ, àwọn ẹbí rẹ̀ kó lọ sí ìlú Minna tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Naija lónìí. Ó kàwé léréfèé nílé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ́rẹ̀ Church Missionary Society. Ní ọdún 1922, ó padà wá sí Ògbómọ̀ṣọ́ láti wá bá bàbá bàbá rẹ̀ gbé tí ó tún tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Oníyẹ̀tọmi ṣáájú kí ó tún tó tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ Kọlẹ́ẹ̀jì ti onítẹ̀bọmi ní ọdún 1925. Ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Akádẹmì Onítẹ̀bọmi láàrín ọdún 1930 sí 1942, lẹ́yìn èyí ni ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ àjọ tó mójú tó ìrìnà Rélùwéè ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Lásìkò yí, ó ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú H.O. Davies, tí ó jẹ́ agbẹjọ́rò àti olóṣèlú, ó tún dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú Nigerian Youth Movement níbi tí ó ti ṣàtìlẹyìn fún Ikoli láti di ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ tó ń ṣojú Ìpínlẹ̀ Èkò tako yíyàn tí wọ́n yan Samuel Akisanya, ẹni tí Nnamdi Azikiwe fara mọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí yóò dépò náà. Akíntọ́lá tún dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́, tí ó sì di olóòtú fún.iwé ìròyìn náà ní ọdún 1953 pẹ̀lú àtìlẹyìn Akinọlá Májà tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olówó ìwé-ìròyìn náà tí ó sì rọ́pò Ernest Ikoli gẹ́gẹ́ olóòtú. Akíntọ̀lá náà sì dá Ìwé-ìròyìn Yorùbá tí wọ́n ń fi èdè Yorùbá gbé kalẹ̀ ní ojojúmọ́. Ní ọdún 1945, ó tako ìgbésẹ̀ ìdaṣẹ́ sílẹ̀ tí ẹ́gbẹ́ òṣèlú NCNC tí Azikiwe àti Michael Imoudu, fẹ́ gùn lé, èyí sì mu kí ó di ọ̀dàlẹ̀ lójú àwọn olóṣèlú bíi Anthony Enahoro. Ní ọdún 1946, Akíntọ̀lá rí ìrànwọ́ ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ gbà láti kàwé ọ̀fẹ́ ní U.K, níbi tí ó ti parí ìmọ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ nípa ìmọ̀ òfin, tí ó sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí agbẹjọ́rò lórí òfin tí ó jẹ mọ́ ìlú. Ní ọdún 1952, òun àti Chris Ògúnbanjọ,olóyè Bọ̀dé Thomas àti Michael Ọdẹ́sànyà kóra jọ pọ̀ di ọ̀kan.
|
20231101.yo_3487_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20on%C3%AD%C3%ACp%C3%ADn
|
Nọ́mbà oníìpín
|
Ninu imo Mathematiki, nomba oniipin (rational number) ni nomba ti a le ko le gege be ipin nọ́mbà odidi meji. Nomba bi , to je pe b ki se odo.
|
20231101.yo_3487_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20on%C3%AD%C3%ACp%C3%ADn
|
Nọ́mbà oníìpín
|
A le ko awon nomba oniipin ni opolopo ona, fun apere , sugbon o d'ero julo nigbati a ati b ko ba ni nomba kanna ti a le fi pin won a fi 1.
|
20231101.yo_3488_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20t%C3%B3%E1%B9%A3%C3%B2ro
|
Nọ́mbà tóṣòro
|
to je pe a ati b won je Nọ́mbà Gidi, ti i si je ẹyọ tíkòsí pelu idamo bi i 2 = −1. Nọ́mbà gidi a ni a n pè ní apá gidi nọ́mbà tósòro, be sìni nọ́mbà gidi b jẹ́ apá tíkòsi´. A lè sọ pé àwón nọ́mbà gidi je nọ́mbà tósòro pelu apá tíkòsi´ tó jé òdo; eyun pé nọ́mbà gidi a jẹ́ bakanna mọ́ nọ́mbà tósòro a+0i
|
20231101.yo_3488_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20t%C3%B3%E1%B9%A3%C3%B2ro
|
Nọ́mbà tóṣòro
|
Fún àpẹrẹ, 3 + 2i jé nọ́mbà tósòro, pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2. Tí z = a + bi, apá gidi (a) ni a n se àmì rẹ̀ pẹ̀lú Re(z), tàbí ℜ(z), be sìni apá tíkòsi´ (b) ni a n se àmì rẹ̀ pẹ̀lú Im(z), tàbí ℑ(z)
|
20231101.yo_3488_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20t%C3%B3%E1%B9%A3%C3%B2ro
|
Nọ́mbà tóṣòro
|
Àwon nọ́mbà tósòro se ròpọ̀, yọkúrò, sọdipúpọ̀ tàbi sèpínpiń gẹ́gẹ́ bi a ti n se fun àwon nọ́mbà gidi, be ni wón sì ní ìdámọ̀ tó lẹ́wà mìíràn. Fún àpẹrẹ, nọ́mbà gidi nìkan kò ní ojúùtú fún ìdọ́gba aljebra alápọ̀ọ́nlépúpọ̀ (polynomial) pẹ̀lú nọ́mbà àfise gidi (coefficient), sùgbọ̀n àwọn nọ́mbà tósòro ní. (Eyi ni òpó àgbàrò aljebra) (fundamental theorem of algebra).
|
20231101.yo_3488_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%E1%BB%8D%CC%81mb%C3%A0%20t%C3%B3%E1%B9%A3%C3%B2ro
|
Nọ́mbà tóṣòro
|
Nínú ìmọ̀ isẹ́-ẹ̀rọ oníná (electrical engineering), níbi ti i ti dúró fún ìwọ́ iná (electric current) àmì tí a n lò fún ẹyọ tíkòsí i ni j, ari bayi pé nigba miran nọ́mbà tósòro se kọ lẹ̀ bayi, a + jb.
|
20231101.yo_3489_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Yakubu%20Gowon
|
Yakubu Gowon
|
Yakubu tí àpèjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Jack Dan-Yumma Gowon ni wọ́n bí ní kọkàndínlógún oṣù Kẹwàá, ọdún 1934 (19-10-1934) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti apá Àríwá. Gowon jẹ́ Ọ̀gágun ní Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ni ó sì tún jẹ̀ olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ódún 1966 dé 1971. Kásìkò ìjọba rẹ̀ náà ni ilẹ̀ Nàìjíríà ja ogun abẹ́lé láti 1966 sí 1971, lábẹ́ ogágun Odumegwu Ojukwu tí ó fẹ́ gba òmìnira lọ́wọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà.
|
20231101.yo_3504_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%C3%B9j%E1%BB%8D%20Ha%C3%BAs%C3%A1
|
Àwùjọ Haúsá
|
Àwọn òpìtàn bíi Basil (1981), gbìyànjú láti ṣàlàyé bí àwọn Hausa ti sẹ̀. Agbede méjì ni ó ti mú ìtàn sọ. Pàtàkì ohun tí ó sọ ni ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹ̀ ní ìlú kan tí ń jẹ́ Daura. A gbọ́ pé kanga kan ṣoṣo ló wà nínú ìlú yìí àti pé ejò kan wà ní inú kanga ọ̀hùn ti kì í jẹ́ kí àwọn ará ìlú pọnmi àyàfi tí ó bá jẹ́ ọjọ́ jímọ́ọ̀. Ìtàn ọ̀hún ṣàlàyé pé àjòjì kan tí ń jẹ Bayajidda wọ ìlú wá, ó pa ejò yìí. Ọba ìlú náà tí ó jẹ́ obìnrin sì di ìyàwó àjòjì ọ̀hún. Ṣe ẹní bá ni ẹrú ni ó ni ẹrù, ẹní fẹ́ ọba ti di ọba. Ìtàn sọ pé àwọn ọmọ mejé tí ọkùnrin ọ̀hún bí ni wọ́n dá àwọn ìsọ̀rí méje tí Hausa ní sílẹ̀. Wọ́n ní àwọn ọmọ méje ti àlè rẹ̀ bí ni wọ́n tẹ ìlú méje yòókù dó. Méje tó jẹ́ ojúlówó ni ‘Hausa Bakwai’ nígbà ti méje yòókù jẹ ‘Banza Bakwai’. Awọn Hausa Bakwai ni Biram, Daura, Katsina, Zaria, Kano, Rano ati Gobir. Àwọn méje yòókù ni Zamfara, Kebbi, Gwari, Yauri, Nupe, Yorùbá àti Kwararafa.
|
20231101.yo_3504_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%C3%B9j%E1%BB%8D%20Ha%C3%BAs%C3%A1
|
Àwùjọ Haúsá
|
Ìtàn ti Stride àti Ifeka (1982) sọ ni a fẹ́ mú lò nínú iṣẹ́ yìí. Ìtàn tó wà lókè yìí náà ni wọ́n sọ ṣùgbọ́n wọn ṣe àfikún díẹ̀. Wọn tọ́ka sí àkọsílẹ̀ kan tí ọjọ́ rẹ̀ ti pé jọjọ tí ń jẹ́ “Kano chronicles”. Wọ́n lo àkọsílẹ̀ yìí láti ṣàlàyé pé ọkùnrin kan tí ń jẹ Bàgódà ni ó kọ́kọ́ jọba ní ìlú Kano. Wọn ni nǹkan bí ẹgbẹ̀rún ọdún sẹ́yìn ni ọba ọ̀hún jẹ (A.D. 1000). Wọn ní àkókò yẹn ni ìgbà tí àwọn Hausa bẹ̀rẹ̀ sí kó ara wọn jọ sí abẹ́ àkóso ìlú síṣe.
|
20231101.yo_3504_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%C3%B9j%E1%BB%8D%20Ha%C3%BAs%C3%A1
|
Àwùjọ Haúsá
|
Àtúnsọ ìtàn tí wọ́n sọ gbà pé ọmọ Bayajida ni gbogbo Hausa ka ara wọn kún. Wọ́n ní Abuyazid gan-an ni orúkọ rẹ̀. Wọ́n ní ọmọ ọba ìlú ‘Baghdad’ ni. Wàhálà àna rẹ ló jẹ́ kó sá kúrò ní ìlú. Ó ṣe àtìpó díẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ìran Kànúrí (ìpínlẹ̀ Borno). Nígbà tí ó dé ibi kan tí ń jẹ́ ‘biram ta gabas’, O fi iyawo re sílẹ̀ nibẹ. Onítọ̀hún sì bí ọmọkùnrin kan síbẹ̀. Ní ìlú Gaya (Ìpínlẹ̀ Kano) ó ṣe alábàábàdé àwọn alágbẹ̀dẹ kan tí wọ́n jáfáfá púpọ̀, wọ́n bá a ṣe ọ̀kọ̀ kan. A gbọ́ pé ọ̀kọ̀ yìí ni ó lò láti fi pa ejò tí ń dààmú àwọn ará ìlú Daura tí ó sì fi bẹ́ẹ̀ di ọba wọn. Ìtàn yìí sọ fún wa pé Gwari ni orúkọ ẹrúbìnrin tí ó bi àwọn ọmọ méje tí wọ́n wà ní ìsọ̀rí kejì fún un.
|
20231101.yo_3504_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%C3%B9j%E1%BB%8D%20Ha%C3%BAs%C3%A1
|
Àwùjọ Haúsá
|
Ìtàn yìí tàn ìmọ́lẹ̀ díẹ̀ sí ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn Hausa, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pe iran Hausa ti tan kálẹ̀ kaakiri àgbáyé àwọn Hausa tí wọ́n jẹ́ onílé àti onílẹ̀ ni apá òkè ọya ni orílẹ̀èdè Nàìjíríà ni a ní lọ́kàn nínú iṣẹ́ yìí. Lára àwọn ìpínlẹ̀ ọ̀hún ni Sokoto, Katsina, Zamfara, Kebbi, Kano, Jigawa, Kaduna, Gombe àti Plateau.
|
20231101.yo_3512_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Orlando Owoh (oruko abiso: Stephen Oládipúpò Olaore Owomoyela, February 14, 1932 - November 4, 2008) jé olorin omo ile Naijiria. Omo ìlú Ifón lébàá òwò ní Ìpínlẹ̀ Òndó ni.
|
20231101.yo_3512_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Akínmúwàgún (2001:1-3) sàlàyé pé Orlando jáde ní ilé ìwé alákòóbèrè ó sì ń fi ojú sí eré àsíkò àti gbénàgbénà ti bàbá rè ń se. Ó darapò mó egbé omo ogun Nàìjíríà ní odún 1960, sùgbón kò lò ju odún kan péré tó fi kúro tó sì darapò mó egbé orí ìtàgé kan tí a mò sí Ògúnmólá National Concert Party’. Kò pé púpò ti òun pàápàá fi dá eré tirè sílè tí ó sì pé è ni Orlando Owoh And His Omimah Band’.
|
20231101.yo_3512_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Odún 1969 ni Orlando gbé ìyàwó. Léyìn ìgbeyàwó àkókó, ó ti fé ìyàwó mérin mìíràn. Orúko àwon ìyàwó rè láti orí ìyàwó àkókó ni Múìbátù Orímipé, Folásadé Àkísan, Mopélólá Ìsòlá, Deborah Akérédolú ati ìyábò Ańjoórìn. Lára awon omo rè ni Káyòdé, Abósèdé, Ségún, Dàpò àti Sèsan. (Akinmuwagun 2001:1-3). Ìwádìí fi hàn pé ó tilè bi òkan nínú àwon omo rè tí ń je Tòkunbò si ìlú Oba, a gbó wí pé isé èsé kíkàn ni òdómokùnrin òhún ń se.
|
20231101.yo_3512_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Nínú àlàyé Tádé Mákindé (2004:30) ó hàn gbangba pé Tòkunbò omo Orlando jogún èsè kíkàn ni. Ó sàlàyé pé Orlando féràn èsé kíkàn àti pé odidi odún meta ni ó fi je baálè àwon elésèé kíkàn nígbà èwe rè. Ó ní òré ni àbúrò òun àti gbajúgbajà olorin tí ń jé Sunny Ade.
|
20231101.yo_3512_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Alákíkanjú ni Orlando, nípa akitiyan rè ni a dá Egbé Ìtèsíwájú Ìlú Ifón sílè (Ifón Progressive Union) ní odún 1970. Léyìn to seré ní ìlú Òwò ní odún 1973 ni wón se ètò ífilólè láti kó gbòngàn (Town Hall). (Àkínmúwàgún 2001:1-3).
|
20231101.yo_3512_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Nínú ìfòròwánilénuwò tí Tádé Mákindé se, àwon òtító kan jeyo: Ekíní ni pé àìsàn rolápá-rolésè bá a jà, Olórun ló yo ó. Owó òtún re kò sì se é gbé gìtá dáradára mó. Bí ó tilè jé pé ó lè fi owò òtún òhún bo èníyàn lówó tàbí fi gbé omodé, kò se é mú síbí ìjeun dáradára. Gégé bi àlàyé Orlando:
|
20231101.yo_3512_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Àìsàn yìí kò mu ohùn re lo rárá èyí ni kò sì jé kí akùdé ba eré olósoosù tí ó máa ń se ni ilé ìtura Màjéńtà to wà ní Idimu Egbédá ní Èkó.
|
20231101.yo_3512_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Nínú ìfòròwánilénuwò yìí, Orlando ní òún ti di omoléyìn kírísítì, ó sì fi gbogbo ògo fún Olórun. Ó ní:
|
20231101.yo_3512_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Nígbà tí wón bi í nípa ohun tí àwon olólùfe re ń so kirì pé bí gbajúgbajà olórin àgbàyé – Michael Jackson ba kojú Orlando Owoh nínú eré síse ni Òwò yàtò si ìlú bí i Eko, Abuja tabi Port Harcourt, Orlando ni yóò borí, èsì rè ni pé,
|
20231101.yo_3512_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Kí ló tún kù o? Orlando fara mó Òwò ati àsà òwò títí ti àwon ènìyàn kan fi yí owó inú Owóméyèlá rè sí Òwò, ó ko ó lórin pé déédéé ara òun ni orúko méjééjì se. Wón fi oyè amúlùúdún dá Orlando lólá ni ìlú Ifón. Nígbà tí ó lo sere ní ìlú Tokyo tó wà ni Ilè Japan ní odún 1986, ìjoba fi Oyè gbédègbéyò (Commander of Language) dá a lólá.
|
20231101.yo_3512_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Pàtàkì ìsoro tó dojúko yàtò fún ti àìsàn tó ko lú ú ni èwòn tó lo ni odún 1985 látàrí pé ó ń se agbódegbà fún igbó títà.
|
20231101.yo_3512_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Ìwádìí fi hàn pé Orlando fé ni ibùjókòó ní Ilú òyìnbó àti láti dá Ilé-èkósé eré sílè bí Olórun bá yònda (Akínmúwàgún 2001:1-3). Ó sàlàyé pé òun fé kí àwon orin tí óun ti ko di kíká sórí fóńrán fídíò. Ó ní òun ti parí ètò pèlú Ilé ise `Gazola Nig. Ltd’ láti sètò títa àwon Isé òun sí orí CD pèlú títà rè (Makinde 2004:30).
|
20231101.yo_3512_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Ní gbogbo ònà, ó hàn gbangba pé Orlando ti di àgbà òjè nínú olórin, kì í se ní àdúgbò ìlú Òwò tàbí ile Yorùbá nikan bí kò se ni gbogbo Nàìjíríà (Uzo 2004:14).
|
20231101.yo_3512_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Orlando%20Owoh
|
Orlando Owoh
|
Nínú orin tí ó pe àkolé rè ní `Ifón Omimah’, ó sàlàyé pé omo ilu Òwò ni ìyá òun. Nínú orin tí ó ko fún Gbenga Adébóyè, ó jé kí á mò pé òun sì ni ìyá láye nítorí pé ó ni òun ti bá Gbénga Adébóyè sòrò pé yóò bá òun sin ìyá oun lójó tí ó bá relé ogbó.
|
20231101.yo_3538_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/L%E1%BB%8D%CC%81%E1%BB%8D%CC%81y%C3%A0%20%E1%BB%8Cm%E1%BB%8D%20Yor%C3%B9b%C3%A1
|
Lọ́ọ́yà Ọmọ Yorùbá
|
nì Májísíréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Sir Olumuyiwa Jibalaru. Ọdún 1938 ni ó di Majísíréètì yìí. Òun náà ni ọmọ Nàìjíríà kìíní tí yoo di adájọ́ ilé-ẹjọ́ kóòtù gíga (High Court of Judge). Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò di ‘Chief Justice’ ilẹ̀ Nàìjíríà ni Sir Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá. Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ-ọba Abẹ́òkúta ni.
|
20231101.yo_3538_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/L%E1%BB%8D%CC%81%E1%BB%8D%CC%81y%C3%A0%20%E1%BB%8Cm%E1%BB%8D%20Yor%C3%B9b%C3%A1
|
Lọ́ọ́yà Ọmọ Yorùbá
|
Lọ́yà obìnbìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
|
20231101.yo_3538_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/L%E1%BB%8D%CC%81%E1%BB%8D%CC%81y%C3%A0%20%E1%BB%8Cm%E1%BB%8D%20Yor%C3%B9b%C3%A1
|
Lọ́ọ́yà Ọmọ Yorùbá
|
Òbìnrin Nàìjíríà tí yóò gba oyè Senior Advocate of Nigeria’ nịmọ ọ tí ó jẹ́kọ́àkó Yorùbá nị̀mọ. ỌolankẹMrs Folake S
|
20231101.yo_3538_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/L%E1%BB%8D%CC%81%E1%BB%8D%CC%81y%C3%A0%20%E1%BB%8Cm%E1%BB%8D%20Yor%C3%B9b%C3%A1
|
Lọ́ọ́yà Ọmọ Yorùbá
|
‘Attorney-General’ tị tí yóò jẹkọ́ Nàìjíríà àkọ́mọ‘O Nàìjíríạ̀ilè ni Dr di ‘President of̣kọ́ Aáfíríkà tí yóò kọ́ ilẹ̀mọlawale Elias Òun ni ọTeshim O Yorùbá nịmọthe International Court of Justices’. O
|
20231101.yo_3543_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
6. Ẹrẹ̀kẹ̀sán:- Ó jẹ́ orukọ́ ọjá Ọba Àkúrẹ́. Ọjá yìí nìkan ni Ọba tí má se ọdún òlósùnta fún ọjọ́ méje.
|
20231101.yo_3543_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
7. Gbogí:- Ó jẹ ibi tí wọn tí sé orò omi yèyé láyé àtijọ́, ó sí tún jẹ́ aginjù tí àwọn ẹranko búburú má gbé.
|
20231101.yo_3543_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
9. Ìjọ̀kà:- Jẹ́ Ọ̀kan lárà àwọn orúkọ̀ ilẹ̀-iwé girama tí ó wá, ìdí níyí tí wọn fí pé orúkọ àdúgbò náà ní ìjọ̀kà
|
20231101.yo_3543_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
17. Ọjà osódí:- jẹ́ ibi tí àwọn àgbààgbà olóyé ìlú má gbé láyé àtijọ́ ibẹ sì ni wọn tí má ṣe ìpàdé fún ètó ìlú.
|
20231101.yo_3543_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
18. Alágbàká:- jẹ Ibi tí omi ÀKÚRẸ̀ tí pín sí yẹ́lẹ́yẹ́lẹ́, ibẹ̀ ní orirún omi tí sàn lọ si oríṣìíríṣìí ọ̀nà.
|
20231101.yo_3543_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%8Cl%C3%BA%20%C3%80k%C3%BAr%E1%BA%B9%CC%81
|
Àwọn Àdúgbò Ìlú Àkúrẹ́
|
30. Àrákàlẹ́:- Jẹ́ òkìtí Ibẹ̀ ni wọn ti rí àwọn ènìyàn tí ó dí òkìtì láyé àtijọ́. Ibẹ̀ sí ní wọn ti má jẹ́ oyè jù.
|
20231101.yo_3544_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
abbreviation (n); ìkékúrú: Abbreviation is useful when taking lecture notes. (ìkékúrú wúlò tí a bá ń ṣe àkọsílẹ̀ ìdánilẹ́kọ̀ọ́.
|
20231101.yo_3544_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
abdomen (n); ìkùn: The abdomen of the boy protruded because he over ate. (ikùn ọmọ náà rí róńdó nítorí pé ó jẹun yó jù).
|
20231101.yo_3544_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
aboard (adv); nínú okò ojú omi tàbí òfúrufú; The captain welcomes you aboard this plane. (Adarí ọkọ̀ òfúrufú kì i yín káàbọ̀ sínú ọkọ̀.
|
20231101.yo_3544_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
abolish (v); parẹ́: Government has abolished the tax on agricultural products. (Ìjọba ti dá owó orí lori ohun ọ̀gbùn dúró.
|
20231101.yo_3544_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
abroad (adv); ẹ̀yìn odi, òkè òkun: My brother is studying abroad. (Ẹ̀gbọ́n mi ọkùnrin ń kàwé lókè òkun).
|
20231101.yo_3544_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
abscess (n); ìkójọpọ̀ ọyún: The injection Joshua got from the nurse has formed abscess. (Abẹ́rẹ́ tí nọ́ọ̀sì fún Joshua ti di Ọyún).
|
20231101.yo_3544_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
absent (adj); kò sí, kò wá; He was absent from work last Tuesday. (Kò wá sí ibi iṣẹ́ ní ọjọ́ ìṣẹ́gun tó kọ́já).
|
20231101.yo_3544_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
absolute (adj); pátápátá; Amina has absolute freedom to choose a husband. (Amina ní òmìnìra pátápátá láti yan ọkọ).
|
20231101.yo_3544_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
acacia (n); ẹ̀yà igi kan: The old man rests under acacia tree. (Bàbá arúgbó náà ń gbatẹ́gùn lábẹ́ ogo kaṣíà).
|
20231101.yo_3544_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
acceptable (adj); ìtẹ́wọ́gbà: This work you have done is not acceptable, please do it again. (Iṣẹ́ tí o ṣe kò jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà. Jọ̀wọ́, lọ tun ṣe.
|
20231101.yo_3544_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
accommodate (v) fún láàyè: You could accommodate another student in your room (Ó le fún akẹ́kọ̀ọ́ mìíràn láàyè nínú yàrá rẹ).
|
20231101.yo_3544_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
accomplish (v) ṣe parí: I accomplished two hours work before dinner. (Mo parí iṣẹ́ wákàtí méjì kí oúnjẹ ọ̀sán tó tó).
|
20231101.yo_3544_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
accord (n); ọkàn naa; ifowosowopo: We are in accord about this matter. (A wà ní ọkàn naa nípa ọ̀rọ̀ yìí).
|
20231101.yo_3544_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
account (n) ìṣirò, ìròyìn: Edwin gave an exciting account of the football match. (Edwin ṣe ìròyìn ìdíje bọ́ọ̀lù orí pápá).
|
20231101.yo_3544_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
acknowledge (v) Jẹ́wọ́, gbà: They acknowledged Olu as the cleverest student. (Wọ́n gbà pé Olú ni akẹ́kọ̀ọ́ tó mọ̀wé jùlọ).
|
20231101.yo_3544_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
across (adj); rékọjá: My friend lives in the house across the street. (Ilé tó wà ní ìfòná títì ní ọ̀rẹ́ mi ń gbé).
|
20231101.yo_3544_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
active (adj) yára: My little brother is very active, he never sits still. (Àbúrò mi ọkùnrin yára púpọ̀ kì í wò sùù).
|
20231101.yo_3544_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
actor (n); Òṣèré ọkùnrin: Hubert Ogunde was a a famous actor. (Gbajúmọ̀ òṣèré ni Ògúndé ń ṣe láyé àtijọ́).
|
20231101.yo_3544_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
actress (n); òṣẹ̀ré obìnrin: Liz Benson is one of the Contemporary actress. (Ọ̀kan lára àwọn òṣèrébìnrin ìwòyí ni Liz Benson ń ṣe).
|
20231101.yo_3544_19
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
actual (adj); nítòótọ́, pàápàá, gan-an: He is the actual person that stole the goat. (Òun gan an ló jí ewúrẹ́ náà).
|
20231101.yo_3544_20
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
A.D. Lẹ́yìn ìkú Olúwa wa: This Church was built in 1950 A.D. (A kọ́ ìlé ìjọsìn yìí ní ẹgbẹ̀rún méjì ọdún ó dín díẹ̀ lẹ́yìn ikú Olúwa wa).
|
20231101.yo_3544_21
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adapt (v); bádọ́gba: mólára, wà fún: It is sometimes difficult to adapt to town life. (Ó máa ń ṣòrọ nígbà míràn kí ìgbé ayé ìgboro tó mómi lára).
|
20231101.yo_3544_22
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
add (v); fikún: There were seven eggs in the basket I added three, so now there are ten. (Ẹyindìyẹ méje ló wà nínú apẹ̀rẹ̀, mo fi mẹ́ta kún un, ní bá yìí ó ti di mẹ́wàá.
|
20231101.yo_3544_23
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
address (n); bá sọ̀rọ̀, kọ̀wé sí: Always address elders with respect. (Máa bá àwọn àgbà sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ọ̀wọ̀).
|
20231101.yo_3544_24
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adequate (adj); tó: There is an adequate amount of food for everyone. (Oúnjẹ tó tó wà fún gbogbo ènìyàn).
|
20231101.yo_3544_25
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
administrator (n); alákòóso: The Principla is the administrator of the school. (Ọ̀gá ilé ìwé ni alákòóso ìlé ìwé náà).
|
20231101.yo_3544_26
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adopt (v) sọdọmọ: The childless couple adopted a child at last. (Tọkọtaya tí wọ́n yàgàn náà ti fi ọmọ kan sọmọ nígbẹ̀yìn).
|
20231101.yo_3544_27
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adore (v); júbà; fẹ́ràn lọ́pọ̀lọpọ̀: The boy adores chocolate. (Ọmọkùnrin náà fẹ́ràn ìpápánu púpọ̀).
|
20231101.yo_3544_28
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adult (n); àgbà: Olu is now an adult. He can take decisions on his own. (Olú ti dàgbà báyìí. Ó lè dá romú, kí ó sì ṣe ìpinnu lórí ohun tí ó kàn án.
|
20231101.yo_3544_29
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
advance (v); ìlọsíwájú, àgbàsílẹ̀ owó. We are more advanced in techonology. (A ti lọ síwájú nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ).
|
20231101.yo_3544_30
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
advantage (n); àǹfààní: There are lots of advantages in doing good. (Àǹfààní púpọ̀ ló wà nínú síṣe rere).
|
20231101.yo_3544_31
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
adventure (n); ìdáwọ́lé: He went into a lot of adventures in order to learn more. (Ó dáwọ́lé oríṣìíríṣìí ń kan kí ó lè ní ìmọ̀ si).
|
20231101.yo_3544_32
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
advertise (v) kéde, polówó; The supermarket was advertising salt at a good price. (ilé ìtàjà náà ń polówó iyọ̀ ní owí pọ́ọ́kú).
|
20231101.yo_3544_33
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
advise (v); dárúmọ̀ràn, dámọ̀ràn; ìmọ̀ràn: She advised me to beware of dog. (Ó gbàmí nímọ̀ràn wípé kí n ṣọ́ra fún ajá).
|
20231101.yo_3544_34
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
aeroplane (n); bààbú, ọkọ ofurufu: There was a plane crash at Abuja. (Ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú ṣẹlẹ̀ ní Àbújá).
|
20231101.yo_3544_35
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
affect (v); mú lọ́kàn, kàn: This new rule will not affect me as lam leaving the school. (Òfin tuntun yìí kò kàn ní torí pé mò ń fi ilé ìwé náà sílẹ̀.
|
20231101.yo_3544_36
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
affectionate (adj); nífẹ̀ẹ́: Her mother writes her long, affectionate letters. (Ìyá rẹ̀ kọ lẹ́tà ìfẹ́ gígùn si).
|
20231101.yo_3544_37
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
afford (v); ní agbára láti ṣe ǹkan. My father says he can’t afford a car. (Bàbá mí ní àwọn kò ní agbára láti ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́).
|
20231101.yo_3544_38
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
afraid (adj); bẹ̀rù, fòyà, kọmimú: Olu says he’s not afraid of lion. (Olú sọ wí pé òun kò bẹ̀rù kìnìún).
|
20231101.yo_3544_39
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
after (prep); lẹ́yìn, tẹ̀lé: Tomorrow is the day after today. (Ọ̀la ni ó tẹ̀lẹ́ òní). Ọ̀sán (n) afternoon: Come again this afternoon. (Padà wá ní ọ̀sán yìí).
|
20231101.yo_3544_40
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
afterwards (adv); Nígbèyìn: We want to the film and afterwards we walked home together. (A lọ síbi sinimá, nígbẹ̀yìn a jọ rìn lọ sílé).
|
20231101.yo_3544_41
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
again (adv); ẹ̀wẹ̀, lẹ́ẹ̀kejì: I liked the book so much that I read it again. (Mo gbádùn ìwé náà tó bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ tó jẹ́ pé mo tún un kà).
|
20231101.yo_3544_42
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
agbádá (n) agbádá: The agbada he put on made him look twice his age. (Agbádá tí ó wọ̀ mú u dàbí àgbàlagbà).
|
20231101.yo_3544_43
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
agriculture (n); iṣẹ́ àgbẹ̀: Agriculture is important because we all have to eat. (Iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe pàtàkì nítorí wí pé gbogbo wa ni a máa jẹun).
|
20231101.yo_3544_44
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
ahead (adv); ní wájú: We shall have to cross that river ahead of us. (A máa rékojá odò tí ó wà ní wájú wa).
|
20231101.yo_3544_45
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
ahmadiyya(n); Ẹ̀yà èṣìn mùsùlùmí: Alhajì Yusuph is of Ahmadiyya Sect. (Ẹ̀yà Ahmadiyya ni Alhaji Yésúfù).
|
20231101.yo_3544_46
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
aid (n) ìrànlọ́wọ́: A dictionary is an aid to learning English. (Ìwé asọ̀tumọ̀ jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún kíkọ́ èdè gẹ̀ẹ́sì).
|
20231101.yo_3544_47
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%A8d%C3%A8%3A%20L%C3%A9t%C3%A0%20A
|
Atúmọ̀-èdè: Létà A
|
aim (v); Èrò, fojúsùn: He aimed to be the best football player in the school. (Ó gbèrò láti jẹ́ òṣèré orí pápá tí ó dára jùlọ ní ilé ìwé).
|
20231101.yo_3545_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Ckir%C3%A8
|
Àwọn àdúgbò ìlú Ìkirè
|
wà. Torí pé odo yìí wọn kì í sọ̀rọ̀ tí wọn ń pọn bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í jẹ́ kí ilẹ̀ mọ́ tí wọn á fi pọn ni wọ́n fí pè é ní “Láì kọ sìn.
|
20231101.yo_3545_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Ckir%C3%A8
|
Àwọn àdúgbò ìlú Ìkirè
|
fún àwọn tí wọn ń bí abiku, ní ìgbà àtijọ́ kí àwọn àbíkú wọ̀nyí lè maa dúró sayé ni wọn ń pè ní Ọmọ-ró = > Móro.
|
20231101.yo_3545_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Ckir%C3%A8
|
Àwọn àdúgbò ìlú Ìkirè
|
ará Abẹ́òkuta kan wá ń ta àmàlà níbẹ̀ wọn mọ̀ ọ́ bí ẹni mo owó wọn sì máa n fi júwe pé Ìyànà tí Obìnrin ẹ̀gbá ti ń ta àmàlà.
|
20231101.yo_3545_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Ckir%C3%A8
|
Àwọn àdúgbò ìlú Ìkirè
|
1. Ilé Atóbatélè : Ìwàdìí fi yé mi pé enití ó pilèsè ìlè yìí eni pàtàkì àti alákíkanjú tí ìsesí àti ìhùwàsí rè láàrin àwùjo fi ara jot í oba ìlú. Nígbàtí ó wà pàpà je oba, ibi tí ó fi se ibùgbé tèlè ni wón ńpè ní ilé Ató-Oba-télè lónìí. Ìwádìí tún fi yé mi pé wón máa ńki àwon omo bíbí ilé yìí báyìí. “Òrìsà-ńlá wùmí Atóbatélè. Omo ládèkàn, Omo Àmúlé lámùlé orí kò rerù, orí dada ponponran.
|
20231101.yo_3545_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Ckir%C3%A8
|
Àwọn àdúgbò ìlú Ìkirè
|
2. Ilé Arósùn: Ìwádìí fi yé mi pé enitó pèsè ilé yìí jé àgbè tó féràn láti máa gbin èfó òsùn tàbí ilá. Èyí ló fà á ti wón fi ńpe ilé yìí ní Arí-Òsùn-pa-ojà. Wón sì máa nkì wón ní “Arósùn pajà tilátilá omo oba adélé tejiteji
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.