_id
stringlengths 17
21
| url
stringlengths 32
377
| title
stringlengths 2
120
| text
stringlengths 100
2.76k
|
---|---|---|---|
20231101.yo_2858_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Sadiiki
|
Sadiiki
|
(4) Masa jẹ èyí tí ó gba Ominra tí ó ṣi kún fún orísi, mẹ́san láti ìwọ̀ Òòrùn Gúsù Chad àti Àrìíwá Cameroon. Ní àfikún Masana (212) Musey 120 èyí tí ó sún mọ́ ní Zumaya
|
20231101.yo_2860_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Semitic ni àwọn ènìyàn ka ju ti o ṣi ye wọn jù síbẹ̀ àwọn èdè kan wa ti wọn kò mọ rárá nipá ṣiṣe arópò extant ati extinet kan. Semitic ṣe ipatẹ adọọfa lorisiirisi. Nípa ìṣàkóṣo ti ìbílẹ̀ wọn ṣùgbọ́n dọsini kan àbọ̀ lo wà lábẹ́ ìṣàkóṣo àwọn Arabiki, ṣùgbọ́n àwọn kan rò wípé ko ba ojú mu lati ṣe bẹ.
|
20231101.yo_2860_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Àwọn Oludari kan gba pe Semitic a le ri orukọ wọn ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwọ Òòrun àti Guṣu lábẹ́ ipin ẹka ìdílé kan ṣùgbọ́n aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pẹ̀lú ẹ̀ka ìdílé Gúṣù. Arákùnrin tí Orúkọ rẹ̀ ń jẹ Hetzron (1972: 15-16)5 ṣe àríyànjiyàn lórí ipò
|
20231101.yo_2860_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
(1) Ẹka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jẹ́ ayé òlàjú tó ti kọjá lọ ti àwọn Assyrians àti Babylonians nígbà to ṣi jẹ pé Akkadian wà ní lílò fún nǹkan bi Ọdún meji miliniọnu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwọ̀ Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúṣù àríwá ṣi ẹ̀ka. Ti àwọn Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àṣìkò ìgbà ayé àtijọ́ ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wọ́n ń ṣọ lati nǹkan bí Centiuri mẹwa BC. Ṣẹ́yìn. nǹkan bì Centiuri mẹ́fà sẹ́yìn àwọn kirisitẹni Aramaic nìkan ní ó jẹ́ èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilẹ̀ jẹ pé àwọn èdè tí á ń ṣọ ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwọ̀ Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwọn Olùṣo èdè ní Assyrian (200).
|
20231101.yo_2860_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
2. Ẹka arìngbùngbùn Guṣu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí parẹ́ legbẹ èdè ìlà Òòrun gẹ́gẹ́ bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew.
|
20231101.yo_2860_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Àwọn phonecian, ni tòótó wọn ń sọ̀rọ̀ nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwọn keteji (Carthage) níbi tí á tí mọ hàn-án bí puniki.
|
20231101.yo_2860_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Èdè ìgbàlódé ti àwọn Hébérù ń ṣọ ni Isrealis lo ṣe àtúnṣe rẹ (4, 510). Èdè tí àwọn Ras Shamra àti Uguritic ń sọ kàyéfì lo jẹ́. Èdè to ti pẹ́ tí àwọn Quran ń lò láti Centiuri kẹrin AD, lo wà ṣùgbọ́n nígbà tó yá wọ́n padà ṣí tí Centiuri karun BC; ṣùgbọ́n síbẹ̀ wọ́n ko ṣọ mọ́.
|
20231101.yo_2860_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Loni Orísìírìsí ìpínlẹ̀ Arábìkì tí wọ́n ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwọ̀ Afíríkà. Ní Áfíríkà àwọn èdè tó hàn gbegedé wọn ṣi pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti wọn ń ṣọ ní Mauritania àti díẹ̀ lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), wọn ń ṣọ díẹ̀ ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wọ́n ń sọ ní Àríwá Sudan ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn Olùṣọ èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wọ́n ń sọ Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) ṣùgbọ́n wọ́n ń ṣọ èdè yìí díẹ̀ ní Libya àti Egypt.
|
20231101.yo_2860_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Ó dá hàn yàtọ̀ ṣí ẹ̀dá ọ̀rọ̀ aláwomọ èdè oni ti Arabiki ṣùgbọ́n èdè Arabiki ní a ń lò fún ẹ̀kọ́ Ìṣàkóṣo àti Ìgbòòrò Ìbánisòrọ̀ bakan náà a ń lo gẹ́gẹ́ bi èdè kejì ó si jẹ́ èdè ìpìnlẹ̀ àkọ́kọ fún èdè Arábìkì.
|
20231101.yo_2860_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Ìyàtọ̀ ẹ̀dá Ìgbẹ́dègbẹ́yọ̀ wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkọ́kọ́ Ferguson (1959) Maltese (330) wọn ń sọ̀rọ̀ nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlẹ̀ èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki ṣùgbọ́n tí ó tí tàn ka láàrín àwọn Italiàni.
|
20231101.yo_2860_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
(3) Sémítìkì to wa ní Guṣu kún fún àwọn Arabiki Guṣu àti Ethic Semitic Ṣùgbọ́n àwọn ti tẹ́lẹ̀ kún fún Orísìíríṣí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mọ̀ láti ìwọ̀ Òòrùn Guṣu Arábìkì àkọsílè rè tí wà láti Centiuri méjọ BC pẹ̀lú Arábìkì ti Guṣu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Ṣùgbọ́n ki i se gbogbo àwọn Òmòwé to gboye nínú koko isẹ kan lo fara mọ̀.
|
20231101.yo_2860_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Ethic-Semitic kún fún àwọn ará Àríwá Eghiopic àti ẹ̀ka ọ̀rọ̀ aláwòmọ́ àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní ẹ̀ka Guṣu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín.
|
20231101.yo_2860_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%E1%BA%B9%CC%80m%C3%ADt%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Sẹ̀mítíìkì
|
Amharic (20, 000) èdè Ethopia jẹ tí gbogbo gbo ó wà lára ti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Harari (26), O jé ẹni ti ahọ́n rẹ̀ fanimọ́ra tí ó si jẹ tí ìbìlẹ̀ ṣi gbogbo ìlú Harari gbogbo àwọn ẹgbẹ́ atòdefimọ̀ gbárajọ pẹ̀lú àwọn ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gẹ́gẹ́ bí Soddo (104) yàtọ̀ si tí àringbùngbùn tí ìwọ̀ Òòrùn pẹ̀lú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wọ́n jẹ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ (1,856) Orísìírírìsí nǹkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a ṣi ṣe àpínsowoó rẹ̀ ṣi ẹgbé èyí ti o wa láàrín. Ó ṣe pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á ṣi fi hàn gẹ́gẹ́ bi èdè kan.
|
20231101.yo_2861_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
Kí á to lè ri Chustic gẹ́gẹ́ bí ìdílé kan ó ní ṣe pé kí á pápọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ ìsọ̀rí èdè yòókù, díẹ̀ nínú wọn dá hàn yàtọ̀ láàrín ara wọn; Àwọn kan ṣe àfihàn tí ó dádúró tí ó ṣi yàtò láàrín ẹ̀ka egbẹ́. Ó ṣì ṣúnmọ́ atodefimọ èdè. Díẹ̀ laarin àwọn àgbà ẹgbẹ́ odẹ ni Kenya lo ń ṣọ Yaaku. Àwọn ẹgbẹ́ mééfèfà jo ni nǹkan kan to jọ jẹ àjọni lórí ẹ̀kọ́ nípa ayé to dúró lórí aṣàmì tí ó wa ní ìsàlẹ̀, ìlà Òòrùn Cushitic to wà lórí òkè ati èyí to wa ní ìlà Òòrùn to wa nílẹ̀, Dullay àti Yaakuni nǹkan tí wọn fi se àárin dipo kí a ka lábẹ́ ìlà Òòrùn ẹwọ́n Cushitic.
|
20231101.yo_2861_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(1) Cushitic to wa ní Àríwá kún fún èdè eyọkan, Badawi/Beja (1,148), tí á ń ṣọ ní agbègbè to farapẹ́ ìpín ti Sudan, Egypt àti Eriterea.
|
20231101.yo_2861_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(2) Cushitic to wa ní àringbùngbùn jẹ mọ èdè Àgaw, ó jẹ ẹgbẹ́ ti a ṣe atúnmọ̀ rẹ̀ lórísìírìsí ni Àríwá ìlà Òòrùn Ethiopia àti Kwara lápapọ̀ 1,000), Xamtunga (80), Awngi (490), àti díẹ̀ lórìṣìírìsí tó rún
|
20231101.yo_2861_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(3) Ai ba ìgbà mu fún Burji, Cushitic tó wà ní ìlà òòrùn tún mún ìpàdé ìṣùpọ̀ àhánnupè. Àwọn sọ̀rọ̀sọ̀sọ̀ ń gbé ní orí òkè tí wọn ń ṣọ Burji wa ní Àríwá Kenya àwọn ẹgbẹ́ náà ní Burji (87) Sidamo (1,500) àti Kambata Halìyya ẹgbẹ̀rún kan.
|
20231101.yo_2861_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(ii) Àwọn ẹ̀ka ẹgbẹ́ Oromoid kún fún Orísìírìsí Ojúlówó Oromo (13, 960) tí wọ́n tí sọ̀rọ̀ lati Odò Tana ní kenya si ìpààlà sudan àti Tigrai kòkàárí tí Ethiopia àti konsoid, èdè abínibí lo sọ wọn pọ̣̀ ni Gusu ìwọ̀ Òòrùn. Ṣùgbọ́n eyi ti wọn ń ṣọ ni Kanso (200)
|
20231101.yo_2861_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(iii) Àwọn ọmọ Tana wọn jẹ mo ìlà Òòrùn àti ìwọ̀ Òòrùn ti ìpààlà wa láàrìn wọn. Àwọn ará tẹ́lẹ̀ kún fún Àríwá ni Kenyan Rendille (32) Boni(5) Lapapọ iye ti àwọn Somali jẹ (8,335) Sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ ní Somalia, Djiboute, Ila Òòrùn Ethiopia, ati Aríwá ìlà Òòrùn Kẹnya. Ti ìwọ̀ Òòrùn pín tó ṣí ní Daasenech (30) Arbore (1,000-500) àti bóyá èdè Elmọlo.
|
20231101.yo_2861_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
Èkọ́ nípa ìmọ̀ ayé tí ó da wà ní Bayso (500) òhun ní wọ́n ń ṣọ ní agbègbè Abàjà adágún nínú Ethopian Rift Valley tí ó pin ẹya kan pẹlu ìlà Òòrùn atí ìwọ̀ Òòrùn.
|
20231101.yo_2861_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(4) Dually dúró fún gẹ́gẹ́ bi okùn ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ní àgbègbè Wayto Valley ṣí ìwọ̀ òòrùn ti Konsout (of 4(n) soke) èyí to yàtọ̀ l’orisiirisi ni Gusu Tsmay (7) pípàdé ẹgbẹ́ onihun ìsùpọ̀ lójúpọ̀ parapọ̀ ní Ethnologue gẹ́gẹ́ bi Gwwada (65-76).
|
20231101.yo_2861_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kusitiiki
|
Kusitiiki
|
(5) Èdè Cushitic ni Ọ̀pọ̀lọ̀pọ̀ ń sọ ni Tanzania, níbi ti wọn ti dúró fún iraqw gẹ́gẹ́ bí ìsùpọ̀ fún apẹẹrẹ (365), Gorowa (30) Burunge (31) Mbugu/Mana (32) ní wọn ṣábà maa ń lò gẹ́gẹ́ bi ojúlówó àpẹ̀ẹrẹ èdè àmúlùmálà àti alaisi Asax àti fún kw’adza ọmọ ẹgbẹ ti i ki i ṣe ọmọ ìlú Tan zania tó jẹ dahalo (3,000) ó sọ̀rọ̀ ní ìletò to ṣúnmọ́ ẹnu ìlú odò Tana ní Kenya.
|
20231101.yo_2874_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Àkójọpọ̀ èdè tí a mọ̀ sí Niger-Congo dín mẹ́rin ni òjì-lé-légbéje. Grimes (1996) ríi gẹ́gẹ́ bíi èyí tí ó tóbi jùlọ ní àgbáyé àti wí pé àwọn èèyàn tí ó ń sọ ọ̀kan tàbí èkejì nínú. àwọn èdè yìí fọ́n ká orílẹ̀ ayé ju àwọn ìyókù akẹgbẹ wọn lọ.
|
20231101.yo_2874_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní orílè èdè Afíríkà, àwọn èdè tí ó ní èèyàn tí ó pọ̀ jùlọ ni wọ́n jẹ́ èyí tí a lè rí ní abẹ́ àkójọpọ̀ èdè Niger-Congo. Bí àpẹẹrẹ, èdè tí ó tóbi jùlọ ni Senegal, Wolof jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Niger-Congo; Fulfude tí ó tàn káàkirí ìwọ̀ oòrùn àti àárín gbùngùn Afíríkà, ọkan níbẹ̀ ni. Bẹ́ẹ̀ náà ni èdè Manding tí ó gbajú gbajà ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ èdè ní ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé onikaluku ni ó ní orúkọ tí ó ń pe èdè yìí, oun náà sì ni a mọ̀ ṣí Bambara tí ó jẹ́ èdè orílè èdè àti ìjọba Mali àti Dyala, èdè Okòwò gbalé-gboko. A kò gbọdọ̀ gbàgbé Akan ní orílẹ̀ èdè Ghana. Yorùbá àti Igbo náà kò gbẹ́yìn níbẹ̀, èdè pàtàkì ni méjèèjì yìí ní orílẹ̀ èdè Nàìjiria. Ní àárín gbùngbùn Áfíríkà, èdè Sango ni wọ́n ń sọ. Àwọn èdè Bantu bíi Ganda, Gikuyu, Kongo, Lingala, Luba-Kasari, Luyia, Mbundu (Luanda), Northern Sotho, Sukuma, Swahili, Tsonga, Tswana, Umbundu, Xhosa ati Zulu.
|
20231101.yo_2874_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ó tó èèyàn bíi Mílíọ̀nù lọ́nà ọtà-lé-lọ́ọ̀dúnrún sí Mílíònù irínwó tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ tí wọ́n ń sọ èdè Niger Congo ní Áfíríkà, gẹ́gẹ́ bí Grimes (1996) ṣe sọ.
|
20231101.yo_2874_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ọkan gbòógì lára àwọn èdè tí a rí lára ìpín èdè Niger-Congo ni àkójọpọ̀ èdè Bantu jẹ́. Àwọn èdè yìí gbalẹ tààrà ní ilẹ̀ Áfíríkà, wọ́n sì jọra gidi. Ní abẹ́ gírámà rẹ, a ríi wí pé àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ inú àwọn èdè yìí jọra gan-an, èyí ni ó sì mú àwọn onímọ̀ tí ó jẹ́ aláwọ̀ funfun fi ara balẹ̀ ṣe iṣẹ́ ìwádìí ní orí àwọn èdè wọ̀nyí. Koelle àti Bleek sọ wí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà èdè tí àwọn ènìyàn ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ń sọ ni ó ní ọ̀rọ̀ orúkọ tí a sẹ̀dá nípa àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀. Nínú ìwádìí tirẹ̀, Meinhof sa awọn èdè kan jọ tí wọ́n fi ara pẹ́ ara wọn láti ara ọ̀rọ̀ orúkọ wọn ṣùgbọ́n tí gírámà wọn yàtọ̀ díẹ̀. Èyí ni òún pè ní ‘Semi-Bantu’.
|
20231101.yo_2874_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Westerman ṣe iṣẹ́ tí ó jọ mọ́ ti Meinhof díẹ̀. Ní tirẹ̀, ó se ìpìnyà láàrin àwọn èdè tí ó farahàn ní ìlà-oòrùn àti ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Sudan. Ó ṣe àkíyèsi àwọn èdè kan tí a rí ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Sudan; àwọn náà ni ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́fà: Kwa, Benue-Cross, Togo, Gur, Mandingo, àti ti ìwọ̀ oòrùn Àtìláńtíìkì.
|
20231101.yo_2874_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Greenberg yapa díẹ̀ nínú èrò ti rẹ̀. Ó ṣe àtúnpín àwọn èdè wọ̀nyí láàrín ọdún 1949 sí 1954. Ní tirẹ̀, ó pín Bàntú àti ìwọ̀ oòrùn Sudan sí ọ̀nà kan ṣoṣo tí ó pè ní Niger-Congo, ó sì ṣe àdáyanrí ìlà oòrùn Sudan sí ìsọ̀rí mìíràn ọ̀tọ̀, ó pè é ni Nilo-Saharan. Iṣẹ́ rẹ̀ sì fi ara pẹ́ ti Westerman tààrà ní abẹ́ ìsọ̀rí yìí. Àwọn kókó inú iṣẹ́ Greenberg ni ìwọ̀nyí:
|
20231101.yo_2874_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Greenberg fura sí ipe èdè àwọn èdè wọ̀nyí, ó sì tọ́ka síi wí pé /ףּ/. Kordofanian ati /m/ Niger-Congo jọ ara wọn. Èyí sì máa ń jẹyọ dáadáa nínú àwọn àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ọ̀rọ̀ Kòsemánìí kan nínú àwọn èdè yìí.
|
20231101.yo_2874_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Lẹ́yìn Greenberg ni Mukarovsky ṣe àtúpalẹ̀ àti àtúnpín àwọn èdè yìí, Ó yọ Kordofanian, Mande, Wolof-Serer-Fulfulde, Ijoid àti Adamawa kúrò níbẹ̀; àwọn ìyókù ni ó sì pè ní ‘Western Nigritic’. Ayé sí tẹ́wọ́ gba iṣẹ́ yìí gan-an ni láàrín àwọn olùwádìí ìjìnlẹ̀.
|
20231101.yo_2874_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Àtúnṣe gbòógì wáyé láti ọwọ Bennett àti Sterk (1977), Wọ́n fi ojú lámèyítọ́ wo àwọn ọ̀rọ̣̀ orúkọ tí ó fara jọ ara wọn nínú àwọn èdè wọ̀nyí. Ìgbàgbọ́ wọn ni wí pé Kordofanian àti Mande ti yà kúrò lara wọn. Lẹ́yìn èyí ni ìwọ̀ oòrùn Àtìláńtíìkì yà kúrò lára ìsọ̀rí èdè yìí tí a sì fún àwọn tí ó kù ní orúkọ ààrín gbùngbùn Niger-Congo. Ara àwọn wọ̀nyí ni Ila-oòrùn Adamawa, Gur, Kru àti Ijọ wà. Ọ̀kan gbòógì iṣẹ́ lórí ìwádìí yìí ni The Niger-Cong Languages (Bender – Samuel 1989) jẹ́.
|
20231101.yo_2874_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Àgbékalẹ̀ ìsọ̀rí èdè Niger-Congo gẹ́gẹ́ bí a ti mọ lónìí ni a ṣe àtẹ rẹ̀ sí ìṣàlẹ̀ yìí (Boyd 1989) nípa lílò àlàyé fún ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.
|
20231101.yo_2874_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Nínú atẹ yìí a rí, ‘Proto-Niger-Congo’ nínú èyí tó jẹ́ wí pé ‘Kordofanian’ ni ìsọ̀rí àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ yapa. Mande àti iwọ oòrùn Atlantic ni ìsọ̀rí kejì tí ó tún yapa bẹ́ẹ̀, èyí tí wọ́n fi hàn wá lábẹ́ ‘Proto-Mande-Atlantic-Congo’.
|
20231101.yo_2874_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Àwọn èyí tí ó tún dàbí rẹ̀ ni àwọn tí wọ́n pín sí abẹ́ ìsọ̀rí ààrín gbùngbùn Niger-Congo. Láti ara ‘Proto-Ijo-Congo’ ni ‘Ijoid’ ti yapa, lábẹ́ rẹ̀ ni a tí rí Ijọ ati Defaka.
|
20231101.yo_2874_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Lábẹ́ ‘Proto-Dogon-Congo’, a rí ‘Proto-Volta-Congo’ tí ó pín sí ìwọ̀ oòrùn Vota-Congo àti ìlà oòrùn Volta Congo (Proto-Benue-Kwa).
|
20231101.yo_2874_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní a pá ìwọ̀ oòrùn Volta-Congo ni a ti wá rí Kru, Pre, Senufo; ààrin gbùngbùn Gur àti Adawawa (Bikirin, Day, Kam ati Ubangi). A lè pè é ní Gur-Adamawa.
|
20231101.yo_2874_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní apá ìlà oòrùn, ni a ti rí ààrín gbùngbùn orílè èdè Nìjíríà tí òhun náà tún yapa, a sì rí Bantoid Cross lábẹ́ Ìlà oòrùn yìí.
|
20231101.yo_2874_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní agbègbè orí òkè Nuba ní orílẹ̣̀ èdè Sudan ni àwọn ènìyàn tí ó n sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká.
|
20231101.yo_2874_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Nínú àtẹ yìí a rí ‘Proto-Kordofanian’ tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: Heiban, Tahodi, Rashad, Katla.
|
20231101.yo_2874_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Heiban pín sí Ìlà Oòrùn (Ko, Warnang); ààrín gbùngbùn (Koalib, Logol, Laru, Ebang, Utoro); lààrín ‘Central àti west’ a rí shirumba; Ní ìwọ̀ oòrùn (Tiro àti Moro).
|
20231101.yo_2874_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí Sodo sí jùlọ. Àwọn ìhú tí a sì ti rí àwọn tí èdè wọn pẹ̀ka láti ara orí èdè yìí ni Mali, Cote d’Ivoire, Sierra Leone, Liberia, Burkina Faso, Senegal, Gambia, Guinea Bissan, Mauretania, Banin, Ghana, Togo ati Nigeria (Dwyer 1989; Kastenholz 1991/2).
|
20231101.yo_2874_19
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Nínú àtẹ yìíu a rí ‘Proto-Mande’ tí ó pín sí ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. A wá rí ìwọ̀ oòrùn fúnrarẹ̀ tí ó tún wá pín sí ààrín gbùngbùn tàbí Gúúsù-ìwọ̀ oòrùn àti Àríwá ìwọ̀ oòrùn.
|
20231101.yo_2874_20
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Láti ara ààrín gbùngbùn tàbí Gúúsù-ìwọ̀ oòrùn ni a ti rí: Mandaing ati Koranko, Vai àti Kono, Jogo (Ligbi, Nnmu, Atumfuor, Wela) àti Jeri, Sooso àti Yalunka, Kpelle, Loomu, Bandi, Mande ati Loko.
|
20231101.yo_2874_21
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Láti ara àríwá-ìwọ̀ oòrùn ni a ti rí Sorogama àti Tieyaxo, Tiema Cewe, hainyaxo, Soninke (Azer), Bobo (Sya), Dzuun (Samogo-Guan) àti Sembia, Jo (Samogo-Don).
|
20231101.yo_2874_22
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní ìlà Oòrùn a rí : Mano, Dan (Yakuba, Gio) àti Tura (Wen), Guro (Kweni) àti Yanre, Mwa àti Wan (Nwa), Gban àti Beng (Gan). Bákan náà, ni a rí: Bisa, Sane (Samogo-Tongan, Maya) àti San(South Samo, Maka), Busa (Bisa, Boko), Shanga àti Tyenga.
|
20231101.yo_2874_23
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ti fi ara hàn ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà, ní ẹ̀bá òkun Àtìláńtíìkì ni èdè yìí sodo sí jùlo. Ó fọ́nká láti ẹnu odò Senegal títí dé orílẹ̀ èdè Liberia. Díẹ̀ lára àwọn èdè tí ó pẹ̀ka sí abẹ́ orí èdè yìí ni a ti rí: Fulfulde, Wolof, Diola, Serer àti Remne. Sapir (1971) ni ó ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ ìsàlẹ̀ yìí:
|
20231101.yo_2874_24
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní àríwá ni a ti rí Fulfulde àti Wolof, Serer, Cangin, Diola ati Pupel, Balanta, Bassari/Bedik ati Konyagi, Biafada/Pajade, Kobiana/Kasanga àti Banyin, Nalu, Bijago(Proto-Atlantic), Sua, Temne, Sherbro àti Gola, Limba.
|
20231101.yo_2874_25
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria ni a ti rí àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Èdè náà ni a mọ̀ sí Defaka àti Ijọ. Jenewari àti Williamson (1989) ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ isálẹ̀ yìí
|
20231101.yo_2874_26
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Kru, Gur àti Adamawa-Ubangi ni àwọn ẹ̀ka èdè tí a lè rí ní abẹ́ ìsọ̀rí ‘ARIWA VOLTA-CONGO’ bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé àwọn èdè yìí ti fọ́nká orílẹ̀
|
20231101.yo_2874_27
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Orílẹ̀-èdè Cote d’Ivoire àti Liberia ni a ti lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Ó tó ènìyàn bíi mílíọ̀nù kan sí méjì tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Tí a bá wo àtẹ ìsàlẹ̀ yìí, a ó ṣe alábápàdé àwọn èdè bíi Kuwaa, Tiegba, Seme àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lára orí èdè ‘Kru’.
|
20231101.yo_2874_28
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Èdè yìí gbajú gbajà dáadáa àti wí pé ọ̀pọ̀ ènìyàn ni ó ń sọ èdè yìí ní orílẹ̀ ayé. A lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè náà ní orílẹ̀ èdè bíi Cote d’Ivoire Ghana, Togo, Benin, Burkina Faso àti Nigeria. Ó tó èèyàn bíi mílíọ̀nù márùn-ún ati àbàbọ̀ tí wọ́n ń sọ èdè yìí gẹ́gẹ́ bí Manessy 91978) ti ṣe ìwádìí rẹ̀.
|
20231101.yo_2874_29
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Nínú àtẹ yìí a rí ‘Proto Gur’. Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ó pín sí:- Ààrin gbùngbùn Proto; Kulango àti Loron (Proto-Gur); Viemo, Tyefo, Wara-Natioro, Baatonum, Win (Toussian).
|
20231101.yo_2874_30
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Lábẹ́ àríwá, a rí : Kurumfe, Bwamu Buli-Konni, Ìlà-oòrùn Oti-Volta, Iwọ̀-oòrùn Oti Volta, Gurma, Yom-Nawdm.
|
20231101.yo_2874_31
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Lábẹ́ gúúsù, a rí: Lobi àti Dyan, Kirma àti Tyurama, Ìwọ̀-oòrùn Gurunsi, ààrin gbùngbùn Guruusì àti Ìlà-oòrùn Guruusi, Dogose àti Gan.
|
20231101.yo_2874_32
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Èdè tí ó gbòòrò ni èdè Adamawa-Ubangi. Ipẹ̀ka rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti apá Gúsù-Ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà títí dé Àríwá-Ìwọ̀ oòrùn Sudan. Àpapọ̀ iye àwọn tí ó ń sọ èdè Adamawa tó mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀-Crozier àti Blench (1992); Grimes (1996). Mílíọ̀nù méjì lé lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún ni Barreteau àti monino (1978) tọ́ka sí gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń sọ èdè Ubangi. Èyí túmọ̀ sí pé àpapọ̀ àwọn tí ó ń sọ èdè Adamawa-Ubangi ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ jẹ́ mílíọ̀nù mẹ́rindín ní ẹgbàá lọ́nà ọgọ́rùn-ún láì ka àwọ̣n tí ó ń sọ èdè Sango mọ́ ọ.
|
20231101.yo_2874_33
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Adamawa - eléyìí tún pín sí àwọn àwọn ìsọ̀rí mìíràn bíi: Leko, Duru, Mumuye/Yendang ati Nimbari; Ubum, Bua, Kim, Day; Waja, Longuda, Jen, Bikwin, Yungur. Bákan náà ni a rí: Ba (Kwa), Kam, Fali.
|
20231101.yo_2874_34
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Bennett ati Sterk (1977) pe ‘South Volta-Congo ni ààrin gbùngbùn àríwí Niger-Congo. Atọ́tọ́nu wáyé nípa yíyapa tí ó wá yé láàrin Kwa àti Benue Congo nítorí pé wọ́n sún mọ́ ara wọn pékípẹ́kí-Greenberg (1963). Pàápàá jùlọ yíyapa láàrin èdè kwa, Gbe àti Benue –Congo: Bennett àti Sterk (1977) àti síse àtúnṣe.
|
20231101.yo_2874_35
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Kranse (1895) ni ó ṣe ìfihàn orúkọ ‘Kwa’ fún ayé. Bíi mílíọ̀nù lọ́nà ogún ni Grimes (1996) fi yé wa wí pé ó ń sọ èdè náà. Greenbery (1963a) pín-in sí ìsọ̀rí mẹ́jọ, ó sì so àwọn èdè ààrin gbùngbùn Togo pọ mọ ìsọ̀rí tirẹ̀. Stewart 1994 ni o ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ ìsàlẹ̀ yìí.
|
20231101.yo_2874_36
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Nínú àtẹ yìí a rí ‘Proto-Kwa’ tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́fà ni ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. Àwọn ìsọ̀rí náà nìwọ̀n yìí:
|
20231101.yo_2874_37
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìsọ̀rí wọ̀nyí ni o tún jẹ́ àtúnpín sí ìsọ̀rí mìíran bí àpẹẹrẹ :- Potou-Tano, Na-Togo, Ka-Togo, Gbe.
|
20231101.yo_2874_38
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
(e) Guan – O tun pín si Gúúsù níbi ti a ti rí Efutu –Awutu ati Larten-Cherepong-Anum. Bákan náà ni Àríwá Guang.
|
20231101.yo_2874_39
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Na-Togo:- Ó pín sí Lelémi – Lefana, Akapatu-Lolobi, Likpe, Santrokofi; Logba (Na Togo); Basila, Adele.
|
20231101.yo_2874_40
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ka-Togo ;- Ìsọ̀rí eléyìí pín sí Avatime, Nyangbo-Tafi; Kposo, Ahlo, Bowiri (Ka-Togo); Kebu, Animere.
|
20231101.yo_2874_41
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ẹ̀ka méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni èdè yìí ni: Ìwọ̀-oòrùn àti Ìlà oòrùn Benue-Congo. Àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀ ni ó ní àwọn èèyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí, ó sì sodo sí apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria dáadáa. Bẹ́ẹ̀ náà ni ìlú bíi Cameroon, Congo, CAR, DRC, Tonzania, Uganda, Kenya, Mozambique, Angola, Rwanda, Burundi, Namibia, Zambia, Malawi, Zimbabwe, Gabon, Lesotho, Samalia àti àwọn èdè yìí kalẹ̀.
|
20231101.yo_2874_42
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Gẹ́gẹ́ bí Grimes (1996) ṣe wádìí rẹ̀, èdè Yorùbá àti Igbo ni ó tóbi jùlọ nínú ẹ̀ka èdè tí a pè ní Benue-Congo, ìsọ̀rí ìwọ̀ oòrùn Benue-Congo ni ó sì pín àwọn èdè wọ̀nyí sí.
|
20231101.yo_2874_43
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ìwọ̀ oòrùn Benue Congo:- Ó pín sí YEAI (Yoruboid, Edoid, Akokoid, Igboid); Akpes; Ayere-Ahan; NOI (Nupoid, Ọkọ, Idomoid).
|
20231101.yo_2874_44
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
(a) Àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè Nàìjíráà:- Ó pín sí: Kainji, Àríwá-Ìwọ̀ Plateane, Beromic, Àárín gbùngbùn Plateane, Ìlà-oòrùn Gúúsù Plateane, Tarok, Jukunoid.
|
20231101.yo_2874_45
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
(d) Bantoid-Cross:- Lábẹ́ èyí ni Bantoid ti yapa. Nígbà tí a sì rí Cross River ní abẹ́ Bantoid-Cross. Láti ara Cross River ni Bandi ti wá yapa. Nígbà tí a wá rí Delta-Cross lábẹ́ Cross River.
|
20231101.yo_2874_46
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní ìparí, ó fihàn gbangba wí pé èdè Niger-Congo tóbi tààrà àti wí pé orílẹ̀ èdè Áfíríkà ni ó pẹ̀ka sí ọ̀pọ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó gbalẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n a rí lára wọn tí ìgbà ti fẹ́rẹ̀ tan lórí wọn. Àwọn wọ̀nyí ni èdè mìíràn ti fẹ́ máa gba saa mọ lọwọ Àwọn ìdí bíi, òṣèlú, ogun, òlàjú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sì ṣe okùnfà èyí. Ní pàtàkì jùlọ, gbogbo èdè yìí náà kọ́ ni àwọn Lámèyítọ́ èdè fi ohùn ṣe ọ̀kan lé lórí lábẹ́ ìsòrí tí wọ́n wa ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ‘ẹbí’ rẹ fi ojú hàn gbangba.
|
20231101.yo_2874_47
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20Niger-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Niger-Kóngò
|
Ní ìparí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀mọ̀wé ni wọ́n ti ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí rẹ̀ ṣùgbọ́n ààyè sì tún sí sílẹ̀ fún àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ túlẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ ìwádìí àti lámèyítọ́ lórí ẹ̀kà èdè Niger-Congo.
|
20231101.yo_2875_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kodofanianu
|
Kodofanianu
|
Ní agbègbè orí òkè Nuba ní orílẹ̣̀ èdè Sudan ni àwọn ènìyàn tí ó n sọ èdè yìí wọ́pọ̀ sí jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ogun àti ọ̀tẹ̀ ti fọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn yìí ká.
|
20231101.yo_2875_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kodofanianu
|
Kodofanianu
|
Nínú àtẹ yìí a rí ‘Proto-Kordofanian’ tí ó pín sí ìsọ̀rí mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀: Heiban, Tahodi, Rashad, Katla.
|
20231101.yo_2875_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Kodofanianu
|
Kodofanianu
|
Heiban pín sí Ìlà Oòrùn (Ko, Warnang); ààrín gbùngbùn (Koalib, Logol, Laru, Ebang, Utoro); lààrín ‘Central àti west’ a rí shirumba; Ní ìwọ̀ oòrùn (Tiro àti Moro).
|
20231101.yo_2876_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mande
|
Mande
|
Ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ni àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí Sodo sí jùlọ. Àwọn ìhú tí a sì ti rí àwọn tí èdè wọn pẹ̀ka láti ara orí èdè yìí ni Mali, Cote d’Ivoire, Sierra Leone, Liberia, Burkina Faso, Senegal, Gambia, Guinea Bissau, Mauritania, Banin, Ghana, Togo ati Nigeria (Dwyer 1989; Kastenholz 1991/2).
|
20231101.yo_2876_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mande
|
Mande
|
Nínú àtẹ yìíu a rí ‘Proto-Mande’ tí ó pín sí ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. A wá rí ìwọ̀ oòrùn fúnrarẹ̀ tí ó tún wá pín sí ààrín gbùngbùn tàbí Gúúsù-ìwọ̀ oòrùn àti Àríwá ìwọ̀ oòrùn.
|
20231101.yo_2876_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mande
|
Mande
|
Láti ara ààrín gbùngbùn tàbí Gúúsù-ìwọ̀ oòrùn ni a ti rí: Mandaing ati Koranko, Vai àti Kono, Jogo (Ligbi, Nnmu, Atumfuor, Wela) àti Jeri, Sooso àti Yalunka, Kpelle, Loomu, Bandi, Mande ati Loko.
|
20231101.yo_2876_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mande
|
Mande
|
Láti ara àríwá-ìwọ̀ oòrùn ni a ti rí Sorogama àti Tieyaxo, Tiema Cewe, hainyaxo, Soninke (Azer), Bobo (Sya), Dzuun (Samogo-Guan) àti Sembia, Jo (Samogo-Don).
|
20231101.yo_2876_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mande
|
Mande
|
Ní ìlà Oòrùn a rí : Mano, Dan (Yakuba, Gio) àti Tura (Wen), Guro (Kweni) àti Yanre, Mwa àti Wan (Nwa), Gban àti Beng (Gan). Bákan náà, ni a rí: Bisa, Sane (Samogo-Tongan, Maya) àti San (South Samo, Maka), Busa (Bisa, Boko), Shanga àti Tyenga
|
20231101.yo_2877_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80t%C3%ACl%C3%A1%C5%84t%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Àtìláńtíìkì
|
Gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ti fi ara hàn ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà, ní ẹ̀bá òkun Àtìláńtíìkì ni èdè yìí sodo sí jùlo. Ó fọ́nká láti ẹnu odò Senegal títí dé orílẹ̀ èdè Liberia. Díẹ̀ lára àwọn èdè tí ó pẹ̀ka sí abẹ́ orí èdè yìí ni a ti rí: Fulfulde, Wolof, Diola, Serer àti Remne. Sapir (1971) ni ó ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ ìsàlẹ̀ yìí:
|
20231101.yo_2877_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80t%C3%ACl%C3%A1%C5%84t%C3%AD%C3%ACk%C3%AC
|
Àtìláńtíìkì
|
Ní àríwá ni a ti rí Fulfulde àti Wolof, Serer, Cangin, Diola ati Pupel, Balanta, Bassari/Bedik ati Konyagi, Biafada/Pajade, Kobiana/Kasanga àti Banyin, Nalu, Bijago(Proto-Atlantic), Sua, Temne, Sherbro àti Gola, Limba
|
20231101.yo_2878_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ij%E1%BB%8Didi
|
Ijọidi
|
Apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria ni a ti rí àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Èdè náà ni a mọ̀ sí Defaka àti Ijọ. Jenewari àti Williamson (1989) ni wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ àtẹ isálẹ̀ yìí
|
20231101.yo_2879_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Dogon
|
Dogon
|
Àwọn ènìyàn bíi ìdajì mílíọ̀nù tí a bá pàdé ní ilẹ̀ Mali àti Burkina Faso ni wọ́n n sọ èdè yìí. Bendor-Samuel àti àwọn ìyókù (1989) ni ó gbé àtẹ yìí kalẹ̀.
|
20231101.yo_2879_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Dogon
|
Dogon
|
Iye àwọn tí ó ń sọ èdè yìí jẹ 100,000. (Ọ̀kẹ́márùn-ún) Orílẹ̀ èdè tí wọn tí ń sọ èdè yìí ni Mali, ati Burkina Faso
|
20231101.yo_2881_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Krumen
|
Krumen
|
Orílẹ̀-èdè Cote d’Ivoire àti Liberia ni a ti lè rí àwọn ènìyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Ó tó ènìyàn bíi mílíọ̀nù kan sí méjì tí wọ́n ń sọ èdè yìí. Tí a bá wo àtẹ ìsàlẹ̀ yìí, a ó ṣe alábápàdé àwọn èdè bíi Kuwaa, Tiegba, Seme àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lára orí èdè ‘Kru’.
|
20231101.yo_2883_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ad%C3%A1m%C3%A1w%C3%A1-Ubangi%20I
|
Adámáwá-Ubangi I
|
Èdè tí ó gbòòrò ni èdè Adamawa-Ubangi. Ipẹ̀ka rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti apá Gúsù-Ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà títí dé Àríwá-Ìwọ̀ oòrùn Sudan. Àpapọ̀ iye àwọn tí ó ń sọ èdè Adamawa tó mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀-Crozier àti Blench (1992); Grimes (1996). Mílíọ̀nù méjì lé lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún ni Barreteau àti monino (1978) tọ́ka sí gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń sọ èdè Ubangi. Èyí túmọ̀ sí pé àpapọ̀ àwọn tí ó ń sọ èdè Adamawa-Ubangi ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ jẹ́ mílíọ̀nù mẹ́rindín ní ẹgbàá lọ́nà ọgọ́rùn-ún láì ka àwọ̣n tí ó ń sọ èdè Sango mọ́ ọ.
|
20231101.yo_2883_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ad%C3%A1m%C3%A1w%C3%A1-Ubangi%20I
|
Adámáwá-Ubangi I
|
Adamawa - eléyìí tún pín sí àwọn àwọn ìsọ̀rí mìíràn bíi: Leko, Duru, Mumuye/Yendang ati Nimbari; Ubum, Bua, Kim, Day; Waja, Longuda, Jen, Bikwin, Yungur. Bákan náà ni a rí: Ba (Kwa), Kam, Fali.
|
20231101.yo_2885_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
Ẹ̀ka méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni èdè yìí ni: Ìwọ̀-oòrùn àti Ìlà oòrùn Benue-Congo. Àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀ ni ó ní àwọn èèyàn tí wọ́n ń sọ èdè yìí, ó sì sodo sí apá gúúsù ilẹ̀ Nigeria dáadáa. Bẹ́ẹ̀ náà ni ìlú bíi Cameroon, Congo, CAR, DRC, Tonzania, Uganda, Kenya, Mozambique, Angola, Rwanda, Burundi, Namibia, Zambia, Malawi, Zimbabwe, Gabon, Lesotho, Samalia àti àwọn èdè yìí kalẹ̀.
|
20231101.yo_2885_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
Gẹ́gẹ́ bí Grimes (1996) ṣe wádìí rẹ̀, èdè Yorùbá àti Igbo ni ó tóbi jùlọ nínú ẹ̀ka èdè tí a pè ní Benue-Congo, ìsọ̀rí ìwọ̀ oòrùn Benue-Congo ni ó sì pín àwọn èdè wọ̀nyí sí.
|
20231101.yo_2885_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
Ìwọ̀ oòrùn Benue Congo:- Ó pín sí YEAI (Yoruboid, Edoid, Akokoid, Igboid); Akpes; Ayere-Ahan; NOI (Nupoid, Ọkọ, Idomoid).
|
20231101.yo_2885_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
(a) Àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè Nàìjíráà:- Ó pín sí: Kainji, Àríwá-Ìwọ̀ Plateane, Beromic, Àárín gbùngbùn Plateane, Ìlà-oòrùn Gúúsù Plateane, Tarok, Jukunoid.
|
20231101.yo_2885_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
(d) Bantoid-Cross:- Lábẹ́ èyí ni Bantoid ti yapa. Nígbà tí a sì rí Cross River ní abẹ́ Bantoid-Cross. Láti ara Cross River ni Bandi ti wá yapa. Nígbà tí a wá rí Delta-Cross lábẹ́ Cross River.
|
20231101.yo_2885_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
Ní ìparí, ó fihàn gbangba wí pé èdè Niger-Congo tóbi tààrà àti wí pé orílẹ̀ èdè Áfíríkà ni ó pẹ̀ka sí ọ̀pọ̀ nínú àwọn èdè yìí ni ó gbalẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n a rí lára wọn tí ìgbà ti fẹ́rẹ̀ tan lórí wọn. Àwọn wọ̀nyí ni èdè mìíràn ti fẹ́ máa gba saa mọ lọwọ Àwọn ìdí bíi, òṣèlú, ogun, òlàjú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ni ó sì ṣe okùnfà èyí. Ní pàtàkì jùlọ, gbogbo èdè yìí náà kọ́ ni àwọn Lámèyítọ́ èdè fi ohùn ṣe ọ̀kan lé lórí lábẹ́ ìsòrí tí wọ́n wa ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ‘ẹbí’ rẹ fi ojú hàn gbangba.
|
20231101.yo_2885_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A8d%C3%A8%20B%E1%BA%B9%CC%81n%C3%BA%C3%A9-K%C3%B3ng%C3%B2
|
Àwọn èdè Bẹ́núé-Kóngò
|
Ní ìparí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀mọ̀wé ni wọ́n ti ṣe iṣẹ́ ìwádìí lórí rẹ̀ ṣùgbọ́n ààyè sì tún sí sílẹ̀ fún àwọn ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ túlẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ ìwádìí àti lámèyítọ́ lórí ẹ̀kà èdè Niger-Congo.
|
20231101.yo_2892_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mangbetu
|
Mangbetu
|
Àwọn ènìyàn yìí wà ní abala àríwá Congo, wọ́n sì tó ọ̀kẹ́ méjì ni iye. Èdè mangbetuti ni wọ́n ń sọ, wọ́n sì múlé gbe àwọn Azande, Mbuti àti Momvu. Ọ́ jọ pé orílẹ̀ èdè Sundan ni wọ́n ti sẹ̀ wá; àgbẹ̀, ọdẹ àti apẹja sì ni wọ́n. Òrìṣà Kilima tàbí Noro ni wọ́n ń bọ gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́dàá, wọn a sì máa bọ Ara náà.
|
20231101.yo_2897_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Lunda
|
Lunda
|
Àwọn ẹ̀yà yìí wà ní orílẹ̀ èdè Congo, Zambia àti Angola, èdè wọn sì jẹ́ ẹ̀yà ti Bantu. Wọ́n dín díẹ̀ ní ọ̀kẹ́ mẹ́sàn-án wọ́n sì múlé gbe ẹ̀yà Yaka, Suku, Chokwe abbl. A rí àgbẹ̀, apẹja àti onísòwò tààrà ni orílẹ̀ èdè yìí. Mwaat Yaav ni ọba wọn, àwọn ìjòyè náà sì wà. Baálẹ̀ kọ̀ọ̀kan náà sì sà ṣùgbọ́n ìsákọ́lẹ̀ pọn dandan. Wọ́n máa ń dífá alágbọ̀n ṣùgbọ́n wọ́n gbàgbọ́ nínú nzambi.
|
20231101.yo_2899_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Luwaluwa%20%28Lwalwa%29
|
Luwaluwa (Lwalwa)
|
Àwọn ènìyàn yìí tó bíi ọ̀kẹ́ kan ní iye, ẹ̀yà èdè Bantu sì ni wọ́n ń sọ. Àdúgbò Congo ni wọ́n wà, wọ́n sì múlé gbe Salampasu, Mbagani, Kete, Lunda, Luba àti Chokwe. Wọn a máa ṣe àgbẹ̀ àti ọdẹ wọn a sì máa ṣe iṣẹ́ ọnà. Wọ́n ní ìgbàgbọ́n nínú Olódùmarè (Mvidie Mukulu) àti ẹlẹ́dàá (Nzambi) ṣùgbọ́n wọ́n máa ń wárí fún àwọn alálẹ̀.
|
20231101.yo_2900_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Maasai
|
Maasai
|
Maasai je eya awon eniyan ni Apailaoorun Afrika. Wọ́n wà ní àdúgbò orílẹ̀ èdè Tanzania àti Kenya, wọ́n sì fẹ́ẹ̀ tó ọ̀kẹ́ mẹ́tàdínlógún ààbọ̀ ní iye. Èdè wọn ni OI Maa wọ́n sì múlé gbe Samburu, Kikuyu, Kamba, Chaga, Meru abbl. Darandaran tààrà ni wọ́n. wọn a sì máa sín ìlẹ̀kẹ̀ gan-an. Ọjọ́ orí ni wọ́n máa fi ń ṣe ìjọba ní ilẹ̀ yìí, obìnrin wọn kìí sìí pẹ́ ní ọkọ ṣùgbọ́n ọkùnrin gbọ́dọ̀ ní owó lọ́wọ́ kí ó tó fẹ́ aya. Ní àsìkò ayẹyẹ pàtàkì, màálù ni wọ́n máa ń fi rúbọ.
|
20231101.yo_2901_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mahafali
|
Mahafali
|
Mahafali Àwọn ènìyàn yìí lé ní mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀, wọ́n ń gbé ní apá Gúúsù ìwọ̀ oòrùn Madagascar. Àgbẹ̀ àti darandaran sì ni wọ́n; wọ́n gbajú gbajà fún fínfín àti kíkun ibojì/sàréè. Wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú òrìṣà àkúnlẹ̀bọ, asòdì sí ẹ̀kó kristiẹni ni ìjọba wọn tẹ́lẹ̀, wọn kò ní àǹfààní láti gbọ́ nípa orúkọ Jesu. Nísisìyí ẹ̀sìn òmìnira ti wà ṣùgbọ́n ojú ọ̀nà tí kò dára ń pa ìtànkálẹ̀ ìhìnrere lára.
|
20231101.yo_2903_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Makonde
|
Makonde
|
Èdè Bàntú ni wón ń so, wón sì wà ní Tanzania àti Mozambique. Àwon Mwera, Makua àti Mabia ni àwon alámùúlégbé won. Isé won sì ni àgbè, ode àti igbá fínfín. Abúlé kòòkan ni ó sì ní baálè tirè, àwon alálè ni wón sì máa ń bo bíi Olórun ti won.
|
20231101.yo_2904_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mambila
|
Mambila
|
Mambila Àwọn ènìyàn yìí wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ati Kamẹrúùnù, wọ́n tó ẹgbẹ̀rún lọ́na mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, wọ́n sì múlé ti àwọn ènìyàn bíi kaka, Tikong àti Bafum. Èdè Mambila, ẹ̀yà Bantu ni wọ́n sì ń sọ. Àgbẹ, ọde,̣ apẹja àti ọ̀ṣìn ẹran ni ìṣe wọn. Ẹ̀sìn Mùsùlùmí àti ti ìbílẹ̀ ni wọ́n ń ṣe papọ̀.
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.