_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_2904_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mambila
Mambila
Àwọn wọnyi wa ni Orílẹ́ èdè Nàìjíríà àti Kamẹrúùnù. wọn jẹ ẹya Bantu. Àwọn kaka, Tikong ati Bafun ni wọn jọ pààlà. Ẹsin ibilẹ ati ẹsin musulumi ni wọn n sin.
20231101.yo_2905_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
je olori ijoba Nigeria gege bi ologun lati odun 1975 si 1976. Igba ti awon ologun egbe re fe gba ijoba ni won pa. Ogagun Obasanjo ti o je igbakeji re ni o bo si ori oye gege olori ijoba lati 1976 si 1979.
20231101.yo_2905_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
A bí ògágun Murtala Ramat Muhammed ni ojó kéjo, osù kejì odún 1938 (8/2/1938). Olórí ológun ní ó jé. Ó di alákòso ológun orílè èdè Nàígíríà ní 1975 títí di odún Feb 13, 1976 Murtala Mohammed jé elésìn Mùsùlùmí, Hausa ni pèlú láti (òkè oya apá gúúsù. Ó kékò ológun ní British Academy, Sandhurst.
20231101.yo_2905_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Murtala kò faramó ìjoba ológun Johnson Aguiyi Ironsi tí ó fipá gbà joba ni osù kìíní odún 1966 nínú èyí tí wón pa òpòlopò olórí Nàíjíríà tó jé omo apá gúúsù lónà tó burú jáì! Fún ìdí èyí ó kópà nínú ìfipá - gbà ijòba tó wáyé ni July 21, 1966. Wón fipá gba papakò òfurufú ìkejà; èyí tí wón ti yí orúko rè sí Murtala Mohammed International Airport làti fi yé. Ó kókó fé fi ìfipá gbà ijoba yìí gégé bíi igbésè fún àwon ara gúúsù láti ya kúrò lára Nàíjíríà sùgbón ó da àbá yìí nù nígbèyìn.
20231101.yo_2905_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Ìfipá gbajoba yìí ló mú ògagún (lieutenant-colonel) Yakubu Gowon jé alákòso orílè èdè Nàígíríà. Ní July/29/1975 àwon ologun tó jé òdò
20231101.yo_2905_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
fi ògágun Murtala je alákoso orílè èdè yìí láti jé kí Nàígíríà padà sí ìjoba alágbádá Democracy. Omo odún méjìdínlógójì ni Murtala Ramat Muhammed nígbà tí àwon ológun fi je alákoso rópò Gowon. Murtala kó pa pàtàkì nínú ogun abélé. Ó jé òkan nínú adarí omo ogun Nàígíríà nígbà tí ogun náà dójú iná tán po. Òun ló fà á tí ikojá òdò oya (River Niger) àwon omo ogun Biyafira Biafra se já sí pàbó. Murtala ò lówó sí bí ìfipá-gbà-joba tó mu gorí oyè.
20231101.yo_2905_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Lógán tí Murtala gbàjòba, ara ohun tó kókó se ni; ó pa ètò ìkani [[Census]] ti odún 1973 re, eléyìí tó jé pé ó fì jù sí òdò àwon gúúsù nípa ti ànfàní. Ó padà sí ti odún 1963 fún lílò nínú isé.
20231101.yo_2905_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Murtala Mohammed yo òpòlopò àwon ògá ise ijoba tí ó ti wà níbè láti ìgbà ìjoba Gowon. Ó tún mú kí àwon ará ìlú ni ìgbèkèlé nínú ìjòba alápapò. Ó lé ni egbàárùn (10,000) òsísé ìjoba tí Murtala yo lénu isé nítorí àìsòótó lénu isé, àbètélè, jegúdú-jerá, síse ohun ìní ìjoba básubàsu, àìlèsisé-lónà-tó ye tàbí ojó orí láìfún won ní nkankan. Fífòmó Murtala kan gbogbo isé ìjoba pátápátá, bí àwon olópàá, amòfin, ìgbìmò tó n mójútó ètò ìléra, ológun, àti Unifásitì. Àwon olórí isé ìjòba kan ni wón tún fi èsùn jegúdú jerá kàn, tí wón sì báwon dé ilé ejó. Murtala tún fó egbàárùn owo-ogun sí wéwé. Ó fún àwon alágbádá ni méjìlá nínú ipò méèdógbòn ti amojútó ìgbìmò isé ìjoba. Ìjoba àpapò gba àkóso ilé isé ìròyìn méjì tí ó tóbi jù lo lórílè èdé yìí. Ó jé kí gbígbé ìròyìn jade wa làbé ìjoba àpapò nìkan. Murtala mú gbogbo Yunifasiti tó wà lábé ìjoba ìpínlè sí abé àkoso ìjoba àpapò.
20231101.yo_2905_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Mélòó lafé kà nínú eyín adépèlé ni òrò àwon ohun ribi-ribi tí Murtala gbése nígbà ti re. Ara won tún ni dídá ìpínlè méje mó méjìlá tó wà tèlé láti di mókàndínlógún. Murtala se àtúnyèwò ètò ìdàgbàsókè elekéta orílè èdè. Ó rí ìgbówólórí (inflation) gégé bí ìdàmú nlá tó n se jàmbá fún òrò ajé e wa. Fún ìdí èyí, ó pinnu láti dín owó tó wà lode pàápàá èyí tí wón n ná le isé ìjoba lórí ku. Ó tún gba àwon onísé àdáni níyànjú láti máa sesé tí àwon òsìsé gbogbo-o-gbo ti je gàba lé lórí. Murtala tún se àtúnyèwò òye ise ìtójú ìlú tó ní se pèlú ìlú mìíràn tí àwon egbé ìlú tí ó n sèdá epo ròbì lágbàáyé (OPEC). Ó jé kí Nàíjíríà je ohun kìíní tí ó kà sí nípa ti ànfàní àti iye tí wón dálé epo ròbì.
20231101.yo_2905_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Murtala%20Muhammad
Murtala Muhammad
Láìrò télè, ògágun Murtala dèrò òrun ni ojó ketàlá osù kejì, odún 1976. Wón da lónà nínú mótò rè, nígbà tí òun ti mósálásí bò nínú ìfipá-gbà-joba tí ó jé ìjákulè nígbèyìn. Owó te àwon òlòtè tó pa á, sùgbón kì lé tó pa òsìkà ohun rere á tí bà jé. Murtala Ramat Mohammed ti fayé sílè. Èpa kò bóró mó. Ká tó rérin ó digbó, ká tó rèfon ó dò dàn, ká tó réye bí òkín Murtala Ramat Mohammed ìyén di gbére.
20231101.yo_2906_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Muhammadu%20Buhari
Muhammadu Buhari
Muhammadu Buhari (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ ketàdínlógún, Oṣù Kejìlá Odún 1942) olóṣèlú tí ó jẹ́ Ààrẹ orílè-èdè Nàíjíríà láàrin ọdún 2015 sí ọdún 2023. Ó lo ṣáà àkọ́kọ́ rẹ̀ láàrin odún 2015 sí 2019 àti kejì láàrin ọdún 2019 sí 2023. Buhari tí fìgbà kan jẹ́ ogágun Méjọ̀ Gẹ́nẹ́rà àti pé ó j̣e olórí orílẹ̀ èdè Nàíjíríà lati 31st Oṣù kejìlá odún 1983 sí Oṣù kẹjó odún 1985, léyìn tí ó fi kúùpù ológun gbàjọba.
20231101.yo_2906_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Muhammadu%20Buhari
Muhammadu Buhari
A bí Muhammadu Buhari sí ìdílé Fulani ní ọjọ 17 Kejìlá 1942, ní Daura, Ìpínlè Katsina, baba rẹ ni Hardo Adamu, ẹni tí ó jẹ́ olori Fulani, orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Zulaihat, ẹni tí ó Hausa. Òun ni ọmọ kẹtalelogun bàbá rẹ̀. Ìyá Buhari ni ó tọ dàgbà, bàbá rẹ̀ fi ayé sílè nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rinrin.
20231101.yo_2906_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Muhammadu%20Buhari
Muhammadu Buhari
Buhari dara pò mó Nigerian Military Training College (NMTC) ní ọdun 1962, ó jẹ́ omo odun kan dínlógún nígbà náà. Ní oṣù kejì ọdún 1964, a yí orúkọ ilé-ìwé ológun náà padà sí Nigerian Defence Academy (NDA).
20231101.yo_2906_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Muhammadu%20Buhari
Muhammadu Buhari
Ní àárín 1962 sí 1963, Buhari kó nípa ìmò ogun ní Mons Officer Cadet School ní ìlú Aldershot, England. Ní oṣù kínní ọdún 1963, nígbà tí Buhari jẹ́ ọmọ ọdún ogún, a sọ́ di lieutenanti kejì.
20231101.yo_2907_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Chuba%20Okadigbo
Chuba Okadigbo
Chuba Okadigbo (17 December, 1941 - 25 September, 2003) je oloselu omo ile Naijiria lati eya Igbo ti a bi ni odun 1941 ti o si ku ni odun 2003. Okadigbo je Aare awon Alagba ile Igbimo Asofin Naijiria lati 1999 titi de 2000.
20231101.yo_2925_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Oríṣìíríṣìí àwọn onímọ̀ ní ó ti gbìnyànjú láti fún èdè ní oríkì kan tàbí òmíràn, ṣùgbọ́n kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn oríkì wònyìí, kí èdè túmọ̀ sí?
20231101.yo_2925_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Èdè níí ṣe pẹ̀lú ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò ní àwùjọ yálà fún ìpolówó ọjà, ìbáraẹni sọ̀rọ̀ ojoojúmó, ètò ìdílé tàbí mọ̀lẹ́bí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
20231101.yo_2925_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ, ó ní: Èdè jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìrú kan gbòógì tí àwùjọ àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara ẹni sọ̀rọ̀.
20231101.yo_2925_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
“Èdè ni ariwo tí ń ti ẹnu ènìyàn jáde tó ní ìlànà. Ìkíní lè ní ìtumọ̀ kí èkeji maa ní. Èdè máa ń yàtọ̀ láti ibìkan sí òmíràn. Ohun tó fà á ni pé èdè kọ̀ọ̀kan ló ní ìwọ̀nba ìrú tó ń mú lò. Èdè kankan ló sì ní ìlànà tirẹ̀ to ń tèlé.”
20231101.yo_2925_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Wardlaugh sọ nínú Ogusiji et al (2001:10) wí pé: “Èdè ni ni àwọn àmì ìsọgbà tí ó ní ìtumọ̀ tí o yàtọ̀ tí àwọn ènìyàn ń lò láti fi bá ara wọn sọ̀ọ̀.”
20231101.yo_2925_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Àwọn Oríkì yìí àti ọ̀pọ̀lọpọ oríkì mìíràn ni àwọn Onímọ̀ ti gbìyànju láti fún èdè, kí a tó lè pe nǹkan ní èdè, ó gbọ́dọ̀ ní àwọn èròja wọ̀nyí: èdè gbọ́dọ̀ jẹ́:
20231101.yo_2925_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
(3) Agbára Ìbísí (Productivity) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lo. Gbogbo Ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ mìíràn yàtọ̀ láàrín èdè ènìyàn àti ti ẹranko kì í ṣe ohun tí ó rorùn rárá.
20231101.yo_2925_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Nǹkan àkọ́kọ́ nip é a gbọ́dọ̀ wá oríkì èdè tó ń ṣiṣé lórí èyí tí a ó gbé ìpìnlè àfiwé wa lè. Ṣùgbọ́n ṣá, kò sí oríkì tí ó dàbí ẹni pé ó ṣàlàyé oríkì èdè tàbí tí ó jẹ́ ìtéwógbà fún gbogbo ènìyàn. Charles hocket ṣe àlàyé nínú Nick Cipollone eds 1994 wípé:
20231101.yo_2925_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Ọ̀nà kan gbòógì tí a fi lè borí ìṣòro yìí nip é, kí a gbìnyànjú láti ṣe ìdámọ̀ ìtúpalẹ̀ àwọn àbùdá èdè ju kí a máa gbìnyànjú láti fún ẹ̀dá rẹ̀ tí ó ṣe pàtàkì ní oríkì.
20231101.yo_2925_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Torí náà, a lè pinu bóyá èdè ẹranko pàápàá ni àwọn abida yìí pẹ̀lú… Ohun tí a mọ̀ nípa èdè ẹranko ni pé, kò só èdè ẹranko kọ̀ọ̀kan tí ó ní àwọn àbùdá èdè ènìyàn tí a ti sọ síwájú. Èyí ni ó mú kí á fẹnukò wípé àwọn èdà tí kìí ṣe àwọn ènìyàn kì í lo èdè. Dípò èdè, wọn a máa bá ara wịn sọ̀rọ̀ ní ọ̀nà tí ń pè ní ẹ̀nà,
20231101.yo_2925_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Pẹ̀lú gbogbo àwọn nǹkan tí mo ti sọ nípa ìyàtọ̀ tó wà láàrín èdè ènìyàn àti ẹranko, Ó hàn gbangba wípé a kò le è fi èdè ẹranko àti ti ènìyàn wé ara wọn.
20231101.yo_2925_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Yorùbá bì wọ́n ní “igi ímú jìnà sí ojú, bẹ́ẹ̀ a kò leè fi ikú wé oorun. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni èdè ènìyàn àti ẹranko rí. Nínú èdè ènìyàn lati rí gbólóhùn tí ènìyàn so jáde tí a sì leè fi ìmò ẹ̀dá èdè fó sí wéwé. Àtiwípé àǹfàní káfi èdè lu èdè kò sí ní àwùjọ ẹranko gẹ́gẹ́ bí i ti ènìyàn. Fún bí àpẹẹrẹ.
20231101.yo_2925_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Olú nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀-Orúkọ ní ipò Olùwá, rà jẹ́ Ọ̀rọ̀-ìṣe nígbà tí ísu jẹ́ ọ̀rọ̀ orúkọ ní ipò ààbọ̀.
20231101.yo_2925_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Fatusin, S.A (2001), An Introduction to the Phonetics and Phonology of English. Green-Field Publishers, Lagos.
20231101.yo_2925_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8
Èdè
Ogunsiji, A and Akinpẹlu O (2001), Reading in English Languag and Communication Skills. Immaculate-City Publishers, Oyo.
20231101.yo_2933_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Merina
Merina
Àwọn ti won n so ede wọ̀nyí jẹ́ ará Malayo-Indonesian. Wọ́n ní ìtàn tó gbọ̀ọ̀rìn nípa ìsẹ̀dá wọn ati nipa àṣà àtí ètò òsèlú won láàrin orisi awọn ènìyàn Madagascar.
20231101.yo_2934_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mende
Mende
Ede Mende jọ ede awọn Mande. Àwọn wọ̀nyí wá lati Sudan si apá àríwá. Eya Menda jẹ ẹ̀yà ti o tobi ni Afirika wọn lé ni ọ̀kẹ́ méjì.
20231101.yo_2935_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mossi
Mossi
Mossi (tabi Moaaga) Àwọn ènìyàn Mossi jẹ jagunjagun. Olóyè Moro Naba ni Olórí wọn. Àwọn tó kọ́kọ́ da Mossi àkọ́kọ́ sílẹ̀ wá lati Gbana. Awọn ló tóbi ju ni Burkina Faso
20231101.yo_2937_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ngbaka
Ngbaka
Awọn wọnyi jẹ awon to ń gbé ìlú Ngbaka, kò sì sí agbára kan to da wọn pọ, ńṣe ni olukuluku n se bi o ti fẹ láàrin ìlú.
20231101.yo_2952_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Láti ayébáyé, èdè Yorùbá wa lábé ìpínsí sòrí tí ọ̀gbẹ́nì thamstrong (1964) se fún àwọn èdè gbogbo èdè Yorùbá bọ́ sí abẹ́ ìpín èdè “KWA”. Èyí sì jẹ́ bẹ́ẹ̀ nítorí pé èdè olóhùn (tonalanguage) ni Yorùbá jẹ́.
20231101.yo_2952_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Gẹ́gẹ́ bí a se mọ̀ pé tẹ́lẹ̀-tẹ́lẹ̀ rí, a kì í kọ èdè Yorùbá sí lẹ̀, sí sọ nìkan ni a ń sọ ọ́ lẹ́nu. Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun dé tí òwò ẹrú si bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹ wọ́n bèrè sí ní í kó àwọn ọmọ bíbí ilẹ́ Yorùbá lẹ́rú lọ sí òkè-òkun. Èyí tẹ̀síwájú fún ìgbà pípẹ́ kán-fin-kése títí di àsìkò tí ìjọba àpapọ̀ àgbáyé gbìmọ̀ pọ̀ ti òpin sí òwò ẹrú yìí.
20231101.yo_2952_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Fún ìdí eléyìí, ó di òranyàn kí á dá àwọn ẹrú wònyí padà sí ibi tí wọ́n ti sẹ̀ wá. Èyí ló mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹní tí wọ́n jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá padà sí ilẹ̀ wọn. ṣùgbọ́n ní ọwọ́ àsìkò ti wọ́n fi wà ní oko ẹrú yíì ni wọ́n ti ń se ẹ̀sìn jíjẹ́-ọmọ-lẹ́yìn-kírísítì (chiristanity) Àwọn òyìnbó amúnsìn yìí sí rí i ní ọ̀ranyàn pẹ̀lú láti se agbára lórí i bí ẹ̀sìn yí yóò se máa tẹ̀síwájú láàrin wọn.
20231101.yo_2952_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Ẹ̀yí gan-an ló mú kí wọn se akitiyan lórí bí wọn yóò se se àyípaà ìwé-mímọ́ nì –Bíbélì sí èdè Yorùbá. Nínú sí se eléyìí ó se pàtàkì láti rí i dájú pé ọmọ bíbí ilẹ̀ Yorùbá tó sì jẹ́ gbédè-gbijọ̀ èdè náà wà ní bẹ̀ àti kí ó sì kó ipa takuntakun nínú sí se àyẹ̀wò, àfikún, àyokúrò àti afótónu tó yaarantí ló rí iṣẹ́ náà.
20231101.yo_2952_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Àwọn ènìyàn bíi Humnah Kilham (1891) John Rahar, Gollmer and Bowdich (1817) àti Àjàyí Growther (1815) ló bẹ̀rẹ̀ isẹ́ lórí kí kó lẹ́tà àti àwọn òǹkà jọ.
20231101.yo_2952_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Okùnrin kan tí ń jẹ́ Bowdich ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ si ṣẹ́ lórí i àwọn òǹkà Yorùbá bí i, óókan, ééjì, ẹ́ẹ́ta títío do ri i ẹ́ẹ́wà-á ó sì se àwọn isẹ́ yìí í ní odún (1817).
20231101.yo_2952_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Hamah Kilhar ní (1828) náà sísẹ́ lórí kíkọ sí lẹ̀ èdè tí à ń mẹ́nu bà yìí. Ó fún wa ní ìlànà méjì tí ó se pàtàkì jù nínú isẹ́ rẹ̀.
20231101.yo_2952_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Lẹ́yìn Crowther, a ò gbọdọ̀ gbàgbé àwọn yeekan-yeekan bi, Henny Venn (ijo CMS), Àlùfáà Charle Andrew Gollmer (German), Alufa Heny. Townsend, Samuel Johnson abbl. Tí wọ́n se akanse iṣẹ takun-takun lórí bí èdè Yorùbá se di kí ko sèle.
20231101.yo_2952_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Akiyesi pàtàkì kan ti a lee se nínú gbogbo atotonu lórí bi èdè Yorùbá se di kiko silẹ yin i pe nínú gbogbo àwọn to siṣe yi ti wọn jẹ àwọn oyinbo atohun rinwa alawọ dúdú kan ni a timenu ba, ṣùgbọ́n èyí ko fi bẹ́ẹ ri bẹ.
20231101.yo_2952_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Ct%C3%A0n%20%C3%A0k%E1%BB%8D%E1%BB%8D%CC%81l%E1%BA%B9%CC%80%20Yor%C3%B9b%C3%A1
Ìtàn àkọọ́lẹ̀ Yorùbá
Àwọn dúdú ti wọn ko pa nínú iṣe yìí naa po jojo ṣùgbọ́n fún ìdí kan tàbí òmíràn ti a ko ni lee sòro nípa wọn.
20231101.yo_2960_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80y%C3%A0n
Àyàn
Iṣẹ́ ìlù lílú ni a n pe ni ìṣẹ́ àyàn, àwọn ti o n sẹ iṣẹ yii ni a n pe ni “Aláyàn tàbí ‘Àyàn’. Iṣe àtìrandíran ni èyi, nitori iṣẹ afilọmọlọwọ ni. Gbogbo ọmọ ti Onílù bá bí sí ìdi Àyàn Agalú ni o ni láti kọ ìlù lílù, paapaa akọbi onílù. Dandan ni ki àkọ́bí onílù kọ iṣẹ ìlù, ko si maa ṣe e nitori àwọn onìlu ko fẹ ki iṣẹ́ náà parun.
20231101.yo_2960_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80y%C3%A0n
Àyàn
Yàtọ̀ si àwọn ti a bì ni ìdile onìlu tabi awọn o ọmọde ti a mu wọ agbo ifa, Ọbàtálá, Eégún tàbí Ṣàngó ti wọn si n ti pa bẹ́ẹ̀ mọ oriṣiiriṣii ìlù wọn a maa n rì awọn to ti ìdílé miíran wa láti kọ ìlù lìlú lọwọ awọn onìlu. Àwọn Yorùbá bọ wọn ni “àtọmọde dé ibi orò ń wò fínní-fínní, àtàgbà dé ibi orò ń wò ranran” Òwe yìi tọka si i pe ko si ohun ti a fi ọmọdé kọ ti a si dàgbà sínú rẹ̀ ti a ko ni le se dáadáa.
20231101.yo_2960_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80y%C3%A0n
Àyàn
Láti kékeré làwọn Yorùbá ti n kọ orìṣiiriṣi ìlù lìlú. Nígba ti ọmọde ba ti to ọmọ ọdún mẹ́wàá sí méjìlá ni yóò ti máa bá baba rẹ ti o jẹ onílù lọ òde aré. Láti kékeré yìí wá ni yóò ti máa foju àti ọkàn si bi a ti n lu ìlù. Àwọn ọmọdékùnrin tí ń bẹ nínú agbo àwọn tí ń bọ̀ Ọbàtálá yóò máa fojú síi bi a ti ń lu ìgbìn, àwọn tí n bẹ lágbo àwọn onífá yóò máa kọ bi a ti ńlu Ìpèsè. Ọ̀nà kan náà yii làwọn tí ń bẹ lágbo àwọn Eléégún àti onísàngó ń gbà kọ́ bi a ti ńlu Bàtá.
20231101.yo_2962_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cp%C3%A8s%C3%A8
Ìpèsè
Ìlù tí àwọn babaláwo ńlù lọjọ ọdún ifá ni Ìpèsè. Awọn mìíran npe e ni Ìpẹ̀sì. Yatọ̀ si ọjọ ọdun ifa, a tun nlù Ipese lọjọ̀ ti a ba n ṣe isinku tabi ijade oku ọkan nínú àwọn asaaju nibi Ifa. Mẹrin ni ọ̀wọ́ ìlù ti a papọ se Ìpèsè:-
20231101.yo_2962_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cp%C3%A8s%C3%A8
Ìpèsè
(a) Ìpèsè:- Ìlù yi funra rẹ lo tóbi jù nínú mẹ́rèẹ̣́rin. Igi la fi n gbẹ ẹ. Ó sì gbà tó ẹsẹ bata ti a fi bo o loju mọ ara igi ti a gbẹ ti a si da ìho sinu rẹ.
20231101.yo_2962_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cp%C3%A8s%C3%A8
Ìpèsè
(b) Àféré:- Ìlù yìí lo tobi tẹle Ipese. Igi la fi n gbẹ àféré, ṣùgbọ́n o lẹgbẹ ti o fẹ jù ipese ko ga to ipese, ẹsẹ mẹta ni o fi dúró nilẹ.
20231101.yo_2962_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cp%C3%A8s%C3%A8
Ìpèsè
(e) Agogo:- Ohun kẹ́rin ti a n lù si Ìpese ni agogo. Irin la fi ńrọ agogo. Abala ìrìn meji ti a papọ, ṣùgbọ́n ti a da ẹnu rẹ si lapa kan ni agogo.
20231101.yo_2963_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A8r%C3%A8
Àgèrè
A nlù agẹrẹ lọjọ ọdun awọn ọdẹ. Idi niyi ti a fi n pe Agẹrẹ ni ìlù ogun. Bi ọlọ́ọ́dẹ tàbí olórí ọdẹ kan bá ku ni a n lù agẹrẹ. Ọ̀wọ́ ìlù mẹta la papọ̀ se àgẹ̀rẹ̀ ògún.
20231101.yo_2963_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80g%C3%A8r%C3%A8
Àgèrè
(a) Àgẹ̀rẹ̀:- Eyí ni ìlù to tobi ju pátápátá. Igi la fi ngbẹ agẹrẹ. Oju meji Ọgbọọgba lo sì nì. Ìlù yi dabi ìbẹ̀mbẹ́. Awọ la fin bòó lójú ọ̀nà méjèèjì, okun la si nfi wa awọ ojú rẹ lọ́nà méjèèjì ki o le dún.
20231101.yo_2964_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%E1%BA%B9%CC%80du
Gbẹ̀du
Pàtàkì ni Gbẹ̀du jẹ̀ nínú àwọn ìlù ìbílẹ̀ Yorùbá. Ìlù yii kan naa lawọn kan n pen i àgbà. Ìyàńgèdè ni ìlẹ̀ Yorùbá.
20231101.yo_2964_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%E1%BA%B9%CC%80du
Gbẹ̀du
(a) Aféré:- Ìlù nla ni afẹrẹ. Ó ga tó iwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà mẹ́rin ó sì gùn gbọọgì. Géńdé ti ko ba dara rẹ loju ko le gbe nìlẹ. Oùn rẹ̀ máa n rìnlẹ dòdò. Ìkeke ni a fi maa nlù.
20231101.yo_2964_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%E1%BA%B9%CC%80du
Gbẹ̀du
(b) Apéré tabi Opéré: Ìlù yii lo tobi tẹle afẹrẹ labẹ ọmọ ìlù ti a n pe ni Gbẹdu. Igi la fi gbẹẹ, ṣùgbọ́n ko ga, ko si fẹ lẹnu to aféré.
20231101.yo_2964_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%E1%BA%B9%CC%80du
Gbẹ̀du
(d) Ọbadan: Ìlù yii lo kere ju nínú ọ̀wọ́ ìlù Gbẹdu. Igi la fi gbẹẹ bi ti awọn yooku. Ko sit obi to apẹẹrẹ rara.
20231101.yo_2964_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gb%E1%BA%B9%CC%80du
Gbẹ̀du
Gbẹdu se patakì pupọ nitori pe o jẹ ìlù ọba. A kii dede n lu u. Ìlù yi wa fun ìyẹ̀sì awọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá. Bi ọba ba gbesẹ tabi ijoye nla kan tẹri gbaso wọn n lù Gbẹdu lati fi tufọ.
20231101.yo_2965_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cgb%C3%ACn
Ìgbìn
(a) Ìyá-nlá: Igi la fi n gbẹ́ ìlù yìí. Ihò ìnu ìgi naa si dọ́gba jálẹ̀. Awọ lafi ńbo oju ìgi ìlù yi lójù kan.
20231101.yo_2965_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cgb%C3%ACn
Ìgbìn
(e) Aféré: Ìlù yii lo kere jù nínú awọ ìlù mẹrẹẹrin ti a le tọka si nínú ọwọ ìlù igbin. Igi náà ni a fi n gbẹ ẹ bi i ti awọn mẹta yooku. Awọn ti n gbẹ ìlù yii máa n sojú àti ìmú sára ìgi ìlù yii.
20231101.yo_2969_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Gangan
Gangan
Ìlù yii lo tẹle kẹrikẹri. Ó kéré ju àwọn méjèèjì ìsaájú lọ. Igi la fi ń gbẹ́ òun náà bí i ti àwọn tóókù. Kò sí ohun ti kẹríkẹrì ní tì gangan ò ní.
20231101.yo_2971_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/K%C3%A0nn%C3%A0-n-g%C3%B3
Kànnà-n-gó
Igi ti a fi se kànnàngó kéré jù igi ti a fi se ìsaaju. Ṣùgbọ́n gbogbo ohun ti ìsaájú ni náà ni kannango ni. Bì a ba tẹ kọ̀ngọ́ bọ kànnàngó, o n dun leti kerekere ju ìsaájú.
20231101.yo_2972_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/G%C3%BAd%C3%BAg%C3%BAd%C3%BA
Gúdúgúdú
Gúdúgúdú Ìlù yi gan an là bá máa pè ní omele dùndún. Igi la fi n gbẹ́ ẹ, ṣùgbọ́n ojù kansoso lo nì. O fi èyí yatọ si awọn bi ìyá-ìlù, kẹrikẹri, Gangan, ìsaájú ati kànnàngó ti wọn ni ojù méjìméjì.
20231101.yo_2972_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/G%C3%BAd%C3%BAg%C3%BAd%C3%BA
Gúdúgúdú
Ìlù yìí kò se gbé kọ́ apá bi ti àwọn yòókù ọrùn la máa ń gbé e kọ́ nígbà tí a bá ń lùú. Bí o ti kéré tó ipa tí ó ń kó nínú ìlù dùndún kò kéré. Kerekere ní ń dún nígbà gbogbo nítorí pé awọ ojú ìlù náà kò dẹ̀ rárá.
20231101.yo_2974_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80p%C3%ADnt%C3%AD
Àpíntí
(a) Iya-ìlù: Igi ti a gbẹ ti a si da iho sìnu rẹ la fi nṣe ìya-ìlù. Oju kan ṣoṣo lo ni. Oju kan ṣoṣo yi la n fi awọ bo. Iho ìnu ìgi yi jade si isalẹ rẹ, ko si ni awọ. Iya-ìlù yi ni okun tẹẹrẹ ti a so mọ ara rẹ. Okun náà la fi ngbe e kọpa.
20231101.yo_2975_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%E1%BA%B9%CC%80k%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BA%B9%CC%80
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò amúlùúdùn ní ilẹ̀ Yorùbá. Jákè jádò ìlẹ Yorùbá la ti ń lù sẹ̀kẹ̀rẹ̀, pàá pàá jùlọ níbí àṣeyẹ oríṣiríṣi.
20231101.yo_2975_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%E1%BA%B9%CC%80k%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BA%B9%CC%80
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
"Sèkèrè" jé òkan. làra oh un tí ó n mú ìdàgbàsókè àti ìdánilárayá wá fún àwon ènìyàn ní àwùjo .Sèkèrè yi jé òkan lára ohun ìlù tí wón n lòní apá ìwò oòrùn nd orílè èdè Nàìjíríà tí a so ìlèkè mó lára igbá tí a sì fi àwòn so ara rè. Sèkèrè jé irinsé ìlù tí ó wópò níìwò oòrùn Áfíríkà àti láàárín àwon aláwò funfun. Nígbàtí a bá n korin ni a máa n mìí.
20231101.yo_2975_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%E1%BA%B9%CC%80k%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BA%B9%CC%80
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
Orísirísi ònà ni àwon ìlú kankam n pe sèkèrè ìlú Cuba n peé ní "chekere" wón sì tún pèé ní "aggué(abwe). Bákan náà Brazil n pèé ní"xequerê".
20231101.yo_2975_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%E1%BA%B9%CC%80k%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BA%B9%CC%80
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
Kósó: Kósó ni ìlù tí a fi igi ṣe. Awọ la fi ń bo orí igi tí a gbẹ́ náà. O gùn gbọọrọ tó ìwọ̀n ẹṣẹ̀ bàtà méjì àbọ̀. Ó sì tóbi lórí níbí tí a fi awọ bò ju ìsàlẹ̀ lọ, ó ní ọ̀já tẹ́ẹ́rẹ́ tí a lè fi gbé e kọ́ apá.
20231101.yo_2975_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%E1%BA%B9%CC%80k%E1%BA%B9%CC%80r%E1%BA%B9%CC%80
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
Bẹ́mbẹ́: jẹ́ ìlù tí a fi awọ bo lójú méjèèjì, tí wọ́n sì tún fi awọ tẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ bí Òkun ṣòkòtò kọ lójú kí ohùn rẹ̀ ó lè dun yàtọ̀ létí. Awọ tẹ́ẹ́rẹ́ bí okùn ṣòkótò yí náà ni wọ́n fi ma ń fà tí wọ́n sì ń fọwọ́ kan ojú ìlù náà kí olè mú Ohun tí onílù náà bá fẹ́ jáde lásìkò tí ó bá ń lùú.
20231101.yo_2976_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80p%C3%AD%C3%ACr%C3%AC
Àpíìrì
Aré yi wọ́pọ̀ lágbègbẹ̀ Èkìtì. Ó yàtọ̀ sí ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ti a kọ́kọ̣́ sàlàyé rẹ̀ nítorí pé a kìí lu aro, koso, àti bẹ̀mbẹ́ síi. Kìkì ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ là ń lù nìbi ti a ba nsere apíìri. Orìṣii ṣẹ̀kẹ̣̀rẹ̀ mẹ́ta là ń lù si apiiri.
20231101.yo_2976_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80p%C3%AD%C3%ACr%C3%AC
Àpíìrì
(a) Ìya-àjẹ́: Àgbe to tobi díẹ̀ la fi n ṣe Iya-aje. E so igi kan bayi la n ṣe sara owu ti a ran. Bi a ba ti seetan, a o fi owu ti a se eso si yi kọ ara agbe náà lọwọọwọ titi de ọrun rẹ̀. Eso ara agbe yi ni n dun lara rẹ nìgba ti a ba n luu.
20231101.yo_2976_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80p%C3%AD%C3%ACr%C3%AC
Àpíìrì
(b) Emele-ajè: Emele-aje meji la n lu si apiiri. Agbe la fi n ṣe e bi ti iya-aje. Agbe ti a fi n se emele-aje ko tobi to eyi ti a fi n se iya-aje. Ìdi niyi ti didun wọn ko fi fẹ dodo bi ti Ìya-aje.
20231101.yo_2979_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Bwa
Bwa
Bwa tabi Bwaba (lọ́pọ̀) je eya kan ni arin ile The places left unconquered were raided by the Bamana, which led to a weakening of the Bwa social and political systems. Burkina Faso ati Mali. Iye àwon ènìyàn eya yi je je 300,000 lapapo.
20231101.yo_2980_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%E1%B9%A2%C3%B3k%C3%BAw%C3%A9
Ṣókúwé
Ṣókúwé je eya eniyan ni Apa Arin Afrika. Ìran àwọn tí o ń sọ èdè yìí wá ní orílẹ̀ èdè olómìnira Congo àti Portuguese. Àwọn alábàgbéé wọn ni Luba-Lunda. Orílẹ̀ èdè Angola ni á tí ń sọ èdè yìí. Iye àwọn ènìyàn tí ó ń sọ èdè yìí jé 455, 88. Lára ẹbí Niger-Cong0 ni èdè yìí wa, ẹka rẹ si ni Bantu.
20231101.yo_2983_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ekeeti
Ekeeti
Èdè Bantu ni èdè yìí. Gusu Ìlà oòrùn orílẹ̀ èdè Nigeria ni wọn ti ń sọ èdè yìí. Ẹya àwọn ti ó ń sọ èdè Ibibio ni wọn, wọ́ wà ní Ìpínlẹ̀ Akwa-Ibom ni orílẹ̀ èdè Nigeria. Wọn ń sọ èdè yí náà ni Benue Congo.
20231101.yo_2988_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20Bijago
Èdè Bijago
Èdè Bijago tabi Bidyogo jẹ́ ọkan pàtàkì lára àwọn orisìírísìí èdè bí i mẹ́ẹ́dógbọ̀n tí wọ́n ń sọ láti ilẹ Guinea-Bissau, orúkọ mìíràn tí a tún mọ èdè yìí sí ni: Bigogo, Byougout. Bijuga, Budjago, Bugago. Bákan náà ni a mò wọ́n mọ àwọn. Ẹ̀ka Èdè bíi: Anhaki, kagbaaga, Kajoko, Kamọna àti Orango wọ́pọ̀ nínú èdè Bidgogo.
20231101.yo_2988_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20Bijago
Èdè Bijago
Gbogbo àwọn èdè náà ni wọn sì tì ń sọ títí di àkókò yìí. Àwọn Niger-Congo tó jẹ́ ẹya Bijago ló máa ń ṣọ èdè náà.
20231101.yo_2989_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Bobo%20Madare
Bobo Madare
Èdè yìí jẹ mọ́ èyí tí wọ́n máa ń sọ ní ìwọ̀ oòrùn Africa. Orúkọ mìíràn tí a tún mọ èdè yìí sí ní: Balck bobo, Bobo Bobo Bobo fing. Àwọn èdè Adugbo wọn ni Benge Bobo, Dioula Bobo, Jula Sogokire Sya Syabere voré Zara.
20231101.yo_2989_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Bobo%20Madare
Bobo Madare
Àwọn àmì ẹ̀ka wọn ni N.C. B B A B A. A tun rí èdè Bobo mìíràn tó jẹ mo ti Gusu ní: Burkina Faso, Mali. Wọ́n sì tì ń sọ àwọn èdè wọ̀nyí titi di òní.
20231101.yo_2990_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Busoogi
Busoogi
Bushoog ni a mọ èdè yìí sí. Bákan náà ni wọ́n tún ń jẹ́. Bamong, Bushong, Bushongo, Busoong, Ganga, Kuba Mbale, Mongo Shongo.
20231101.yo_2990_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Busoogi
Busoogi
Wọ́n jẹ mọ ẹka èdè ti Djeenbe, Ngende, Ngombe, Ngombia, Ngongo, panga, Pianga, Shoba, Shobuia ìsobwa.
20231101.yo_2990_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Busoogi
Busoogi
Èdè náà tì wà títí dí oni lápá ijọba onimira ilẹ Congo. Bakan náà ni wọ́n jẹ́ ẹbi Niger-Congo ní ọ̀wọ́ ti Bushong. Awọn èèyàn tó n ṣọ wọ́n sì ju ẹgbàágbèje lọ.
20231101.yo_2991_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cdom%C3%A0
Ìdomà
A lè rí Ìdomà ní ààrin gùngùn orílẹ̀ èdè Náígíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ igba méjì ati àádọ́ta ẹgbẹ̀rún. Àwọn aládùgbóò rẹ̀ ni Ibibo, Igbo, Mama àti Mumuye. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Idoma ni wọ́n jẹ agbẹ. Wọ́n si máa ń se àpọ́nlé àwọn baba ńlá wọn tí wọ́n ti kú.
20231101.yo_3016_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Mumuye
Mumuye
Àwọn wọ̀nyí jẹ ara ènìyàn Naijiria, wọn kere niye, wọn si da dúró tẹlẹ ni. Ipinle Taraba ni wọn n gbe ni Jalingo. Wọn le lẹ́gbẹ̀rún lọ́nà irínwó. Isẹ́ Lagalagana ni wọn ń ṣe.
20231101.yo_3017_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80%E1%B9%A3%C3%A0%20Nok
Àṣà Nok
Àṣà Nok yo jade ni arin ile Naijiria ni bi odun 1000 SK o si pare lai nidi ni bi odun 200 LK. A ko mo ohun ti awon ènìyàn náà pe ara won, nitori náà oruko àsà náà ni won fi so ilu won. Àsà Nok wa lati ariwa Afrika ni ipinlè Niger.
20231101.yo_3052_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20%C3%8Cgb%C3%ACr%C3%A0
Èdè Ìgbìrà
Èdè Igbìrà tàbí Ebira tàbí Egbira jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Kwárà àti Ẹdó àti Násáráwá). Èdè Igbìrà Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Naìjírìà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan. Wọn wà ní àgbègbè Èbìrà ní ìpínlè Kogi, Kwara, Edo, àti béè béè lo. Àwon èka èdè tí ó wà ní abẹ́ rẹ̀ ni Okene (Hima, Ihima) ìgbàrà (Etunno) Èbìrà ní ìsupò èka èdè, wón ń lò ó ní ilé ìwé.
20231101.yo_3053_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cgb%C3%ACr%C3%A0
Ìgbìrà
Èdè yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Náíjíríà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù kan. Wọn wà ni àgbègbè Ebira ní ìpínlẹ̀ Kwara, Edo, Okene àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ẹ̀ka èdè tí ó wà ní abẹ́ rẹ̀ ni Okene (Hima, Ihima) igbara (Etunno) Ebira ní ìsupọ̀ ẹ̀ka èdè, wọ́n ń lò ó ní ilé ìwé.
20231101.yo_3058_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Koin
Koin
Orúkọ àdúgbò tí wọ́n ń pè é ni Itajikan. Àwọn ènìyàn koin ní wọ́n sì ń sọ ọ́. Ó kún fún àlàyé kíkún lórí gírámà èdè. Ilè Cameroon ni wọ́n ti ń sọ ọ́. Àwọn ti wọ́n ń sọ èdè yìí jẹ́ àádọ́jọ ẹgbẹ̀rún. Àwọn mọ̀lẹ́bí èdè koin ni Niger-Congo, Atlántic-Congo, Volta-Congo àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
20231101.yo_3059_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20K%C3%B3ng%C3%B2
Èdè Kóngò
Èdè tí àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń sọ ni Kitumba, òun ta ń pè ní Kongó ní n ǹkan ṣe pẹ̀lú àpapọ̀ àwọn èdè Bantu. Àwọn ibi tí ati n sọ èdè yìí ni: Angola, Congo, Crabon ati Zoure.
20231101.yo_3059_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20K%C3%B3ng%C3%B2
Èdè Kóngò
Ní àarin odún (1960) sí Ọdún (1996) àwọn tí ó n sọ èdè yìí dín díẹ̀ ni mílíọ̀nù mọ́kànlá. Àkọtọ́ èdè wọn muná dóko; ṣùgbọ́n wọn kìí lo àmì ohùn lórí gbogbo ọ̀rọ̀ wọn. Àkọtọ wọn tó wuyì yìí lo mú kí ohun èdè wọn dín kù ní lílò.
20231101.yo_3059_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%88d%C3%A8%20K%C3%B3ng%C3%B2
Èdè Kóngò
Kongo tàbí Kikongo – ó jẹ́ èdè Bantu, àwọn ènìyàn Bakongo ni wọn ń sọ ọ́. Ààrin ilẹ̀ Afíríkà ni ó wà. Àwọn tí wọ́n ń sọ ọ́ jẹ́ mílíọ̀nù méje ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọ́n kó ní ẹrú ní ilẹ̀ Afíríkà tí wọ́n sì tà wọ́n fún America ni wọ́n ń sọ èdè yìí. Àwọn bí i mílíọ̀nù ni wọ́n ń lo èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè méjì.
20231101.yo_3061_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
John R. Watters túmọ̀ sínńtààsì sí bí ìró àti ọ̀rọ̀ se ń so papọ̀ di gbólóhùn, àti bí àwọn ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan se hun ara wọn papọ̀ ní ìpele, ìpele di gbólóhùn.
20231101.yo_3061_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Gbogbo èdè ni wọ́n ní ju ọ̀nà kan lọ ti wọn ń gba hun ọ̀rọ̀ wọn. tí a bá ń kọ nípa èdè kan, àfojúsùn wa ni láti se àfìwé ìdí tí ìhun wọn fi pé orísìírísìí. Ní ilẹ̀ Afirika, ó fẹ́ẹ̀ jẹ́ pé gbogbo èdè ni wọn ń lo Olùwà, àbò àti ọ̀rọ̀ ìṣe.
20231101.yo_3061_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Ètò ọ̀rọ̀ (Word categories) Àwọn ọ̀rọ̀ tí a máa ń tò pọ̀ di gbólóhùn ni OR, IS, Apọnle, Eyan àti Atókùn. Iwájú ọ̀rọ̀ orúkọ ni atọ́kùn máa ń wà Post Position máa ń wa lẹ́yìn ọ̀rọ̀ orúkọ.
20231101.yo_3061_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Nínú èdè Afirika, OR ati Is se iyebíye. Àwọn èdè Africa máa ń lo Is dáadáa ju àwọn èdè Gẹ̀ẹ́sì àti èdè àwọn European.
20231101.yo_3061_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Ẹ̀wẹ̀, a lè lo ọrọ ìṣe ní ibi tí àwọn elédè Gẹ̀ẹ́sì bá ti ń lo àpọ́nlé (e.g. frequently, not yet, still, again) ati ọ̀rọ̀ àsopọ̀
20231101.yo_3061_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Àwọn Èdè Africa kò ní Atókà púpọ̀ bí Europeans. Èdè Afíríka jẹ́ èdè olóhùn, èyí ni a sì fi máa ń dá wọn mọ̀ yàtọ̀.
20231101.yo_3061_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Svo ni o gbajúmọ̀ ní ilẹ̀ Afroasiatic àti ní Niger-Congo yàtọ̀ sí Mande, Senufo àti Ijo, Ní ilè Khoisan – Khoe náà yàtọ̀ fún àpẹẹrẹ:
20231101.yo_3061_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
Ìkẹta ni VSO, òhun kò gbajúmọ̀ ní ilè Afirika. A máa ń rí i ní Berber Chadic ni Afroasiatic, Nilotic Surmic ní ilẹ̀ Eastern Sudamic. Fún àpẹẹrẹ: