_id
stringlengths 17
21
| url
stringlengths 32
377
| title
stringlengths 2
120
| text
stringlengths 100
2.76k
|
---|---|---|---|
20231101.yo_3061_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Nínú àwọn èdè tí ń lo V S O àbọ̀ kìíní àti ìkejì máa ń tẹ̀lé Is á wá fùn wa ní VSOO Turkana bí àpẹẹrẹ:
|
20231101.yo_3061_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Àwọn èdè SOV lè lo SOVX fun afikun (adjuncts) bí a se ríi ní Menade, pẹ̀lú atọ́kún Instrumental prepositional a bó a ti o túmọ̀ sí with a knife.
|
20231101.yo_3061_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
gbé yèwò. Èyí ibeere ni tàbí bẹ́ẹ̀ kọ (i) (Yes or no question) (2) Information word question (3) Indirect question.
|
20231101.yo_3061_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Nínú èdè Africa Yes/no question most commonly involve only a question marker or morpheme at the end or the beginning of the sentences. Nínú èdè Africa ìbéèrè oní bẹẹni tàbí bẹ́ẹ̀kọ́ máa ń ni àmì ìbéèrè ní ìbẹ̀rẹ̀ tàbí ìparí
|
20231101.yo_3061_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Linda is typical of many Niger-Congo and other langs, that use a question marker at the edge of the sentence. Linden i Ogidi nínú àwọn Niger Congo ti o n lo ìbéèrè alámì ni opìn gbólóhùn.
|
20231101.yo_3061_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Nínú èdè bíi silte wọ́n máa ń lo ohùn gbigbe sókè ní ìparí gbólóhùn, á lè lò ó gẹ́gẹ́ bíi yes/no question. Fun àpẹẹrẹ:
|
20231101.yo_3061_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Nínú èdè àwọn konni, Gur ní ilè Ghana, vowel or nasal is lengthened and has a slow fall in pitch. Èyí túmọ̀ sí pé nínú èdè Konni fáwẹ̀lì tàbí aránmúpè wọn máa ń falẹ̀.
|
20231101.yo_3061_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
go to Accra? Nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì tí a bá dáhùn bẹ́ẹ̀ni, ohun tí à ń sọ ni pé ò lọ sí Accra. Ìdàkejì rẹ̀ ni ó tọ̀nà ní ilẹ̀ Africa.
|
20231101.yo_3061_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Twó different kinds of negation should be distinguishes. Túmọ̀ sí pé orísìí àyísódì méjì ni a máa gbé yèwò. Àkọ́kọ́, A lè yí gbogbo gbólóhùn sí òdì. Ìkejì, ó sì lè jẹ́ àpólà kan nínú gbólóhùn bí àpólà orukọ ni a máa yí sódì.
|
20231101.yo_3061_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Ọ̀nà tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n fi máa ń yi gbólóhùn sódì ni síse àtúnrọ àwọn ọ̀rọ̀ ìse. A yi kúrò ni ipò ìṣe lọ sí ìse aláyìísódì. Gbogbo ilẹ Benue-Congo ni wọn tí máa ń lò ó. Fún àpẹẹrẹ.
|
20231101.yo_3061_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/S%C3%ADn%C5%84t%C3%A0%C3%A0s%C3%AC%20%C3%88d%C3%A8%20Aaf%C3%ADr%C3%ADka
|
Sínńtààsì Èdè Aafíríka
|
Àfojúsùn jẹ́ ohun pàtàkì tàbí information abẹ́nú nínú gbólóhùn. Ó jẹ́ ohun ti olùsọ gbà pé Oùgbọ́ kò gbọdọ̀ bá òun sọ. Èdè Africa máa ń lo ohùn nígbà mìíràn. Ṣùgbọ́n ohun ti wọ́n sabàá máa ń lò ni (i) yíyí padà kúrò ni ọ̀rọ̀ ìse tàbí kí wọ́n lo AUX àsèrànwọ́ ìṣe (2) use of special words (particles) (3) use of cleft-types constructions fún àpẹẹrẹ nínú èdè Ejaghan.
|
20231101.yo_3070_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Zosso
|
Zosso
|
‘Zosso’ jẹ Òrìṣà àdáyé bá, tó jẹ pé tí wọ́n bá tí bí ọmọ Àjara-Tọpá, ìyá ọmọ náà kò ní jẹ iyọ̀ títí oṣù afi yọ lókè. Tí oṣù yìí bá ti yọ, wọn á gbé ọmọ náa bọ́ sí ìta láti fi osù han ọmọ náà wí pé kí ọmọ náà wo oṣù tí ó wá sáyé. Ní ọjọ́ náà ìyá ọmọ náà yòó gbé ọmọ náà bó sí ìta láìwọ aṣo àti ọmọ náà pàápàá tí òun àti ọmọ rẹ̀ yóò sì jẹ iyọ̀ pèlú ẹja, wọn yóò sì tún fọ́ èkùrọ́ sórí ẹ̀wà láti fún ìyá ọmọ náà jẹ nígbà méje tó bájẹ́ obìnrin, ẹ̀mẹ́sàn-án to ba jẹ ọkùnrin.
|
20231101.yo_3070_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Zosso
|
Zosso
|
Léyìn tí wón bá ti se èyí tán, ìyá ọmọ yóò gbé ọmọ rẹ̀ lọ sí ìdí Òrìsà ‘Zosso’ láìwọ asọ ní ọjọ́ kejì, tí yóò sì ra otí dání láti sure fún ọmọ náà gẹ́gẹ́ bí àṣà. Wọn á sì padà sílé.
|
20231101.yo_3070_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Zosso
|
Zosso
|
Nígbà tí ìyá ọmọ náà bá dé ilé yoò fá irun orí ọmọ rè, yóò sì lọ ra igbá àti ìkòkò tuntun. Igbá yìí ni yóò fi bo ìkòkò náà lọ sí odò ‘Zosso’. Omi odò yìí ni ìyá àti ọmọ yóò fi wẹ̀ títí omi yóò fi tàn.
|
20231101.yo_3077_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
2. Bà: v. (i) to ferment: Kòkó náà ti bà; The cocoa has fermented (ii) to perch: Ẹyẹ náà bà; The bird perched (iii) to foment: Mo ba egbò rẹ̀; I fomented his ulcer (iv) to hit: Òkúta tí ó sọ bà mí; The stone he threw hit me. (v) to be afraid: Ẹ̀rù bà mí; I was afraid. (vi) settle: Ẹyẹ náà bá sórí ẹ̀ka igi ka; The bird settled on a branch.
|
20231101.yo_3077_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
3. Bẹ́: v. (i) to burst: Ó bẹ́ pẹ̀ẹ́; It bursts (ii) to cut: Ó bẹ́ ẹ ní orí; He cut his head off (iii) to jump: Ọmọ náà bẹ́; The child jumped (iv) to buy a little quantity of a commodity: Ó bẹ́ tábà; He bought a little quantity of tobacco (vi) to crack: Orógbó náà bẹ́; The bitter cola cracked when it was eaten (vii) to start: Òràn ti bẹ́; Trouble has started (viii) to puncture: Táyà náà bẹ́; The tyre punctured (iv) to spat: Ó bẹ́ itọ́; He Spat.
|
20231101.yo_3077_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
4. Bẹ: v. (i) to be bright: Ó bẹ; It is bright (ii) to peel: Ó bẹ iṣu náà; He peeled the yam (iii) to speak cheekily: Ó bẹ si mi; He spoke cheekily to me (iv) to exist: Ó ń bẹ; It exists (v) to be forward/to be screwed: Ọmọkùnrin yẹn bẹ; That boy is too forward.
|
20231101.yo_3077_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
5. Bẹ̀: v. ‘beg’: Ó bẹ̀ mí; He begged me (ii) apologize: O ti ṣẹ Olú. Bẹ́ ẹ̀ ‘You have offended Olú. Apologize to him. (iii) implore: Ó bẹ olè náà kí ó máà kó gbogbo owó wọn lọ; He implored the robber not to take all their money (iv) ask: Ó bẹ̀ wà lọ́wẹ̀; He asked us for communal help.
|
20231101.yo_3077_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
6. Bí: v. (i) to give birth to: Ó bímọ; She gave birth to a baby (ii) to be annoyed: Ó ń bínú; He is annoyed (iii) If: Bí o lù mi n ó lù ọ́; If you hit me I will hit you. (iv) Question marker: Ó lọ bí?; Did he go? (v) how: Ó kọ́ mi bí mo ti máa se é; He taught me how to do it (vi) that: Ó ní àfi bí òun pa á; He says there is nothing but that he will kill him (vii) When/after: Bí ó ti rí mi, inú rè dùn; When he saw me, he was happy (viii) like: Ó rí bí Olú; He is like Olú (ix) as: Ṣe bí mo ti wí; Do as I say (x) bear: Obìnrin yẹn ti bí ọmọ mẹ́wàá; That woman has borne ten children (xi) born: Ọdún tí ó kọjá ni wọ́n bí Olú; Olú was born last year (xii) just: Adé wole bí mo se jádé; Adè entered just as I left (xiii) more: Ènìyàn bí ogbọ̀n ló wà nílé rẹ̀; There were thirty people in his house, more or less (xiv) reproduce: Ológbò máa ń bí ní ẹ̀ẹ̀méjì lọ́dún; Cats reproduce twice a year (xv) such: Wọ́n ń fẹ́ èso tí ó kún fún omi bí i osàn; They want some juicy fruit such as orange (xvi) whether: Nò mọ̀ bí ó máa wá tàbí kò níí wá; I don’t know whether he will come or not’.
|
20231101.yo_3077_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
8. Bì: v.(i) to vomit: Ó bì; He vomited (ii) Ó bì mí; He pushed me (iii) to change colour: Aṣọ náà máa ń bì; The cloth always changes its colour(s) (iv) sick: Olú bì nígbà tí ó jẹ iyán ní àjẹjù; Olú was sick when he ate too much pounded yam.
|
20231101.yo_3077_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
Bò: v. (i) to cover: Ó bo abọ́ náà; He covered the plate (ii) to roof: A bo ilé wa; We roofed our house (iii) to have plenty of leaves: Igi ìrókò náà bò; The ìrókò tree is dense with leaves (iv) smoother: Eruku bò mí ‘I was smothered in dust.
|
20231101.yo_3077_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
1. Dán: v. to be smooth: Ó dán; It is smooth (ii) glitter: Òrùka náà ń dán ní ìka ọwọ́ rẹ̀; The ring glittered on her finger (iii) sparkle: Dáyámọ́ǹdì náà ń dán bí iná tí ó mọ́lẹ̀ náà ṣe tàn sí i; The diamond sparkled in the bright light.
|
20231101.yo_3077_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
2. Dẹ: v.to hunt: Ó dẹ ìgbẹ́; He hunted for animals in the bush (ii) to incite: Mo dẹ wọ́n sí i; I incited them against him.
|
20231101.yo_3077_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
3. Dí: v. (i) to block: Ó dí ihò; He blocked the hole (ii) stuff up: Imú mi dí; My nose is stuffed up (iii) bar: Wọ́n dí ònà tí ó lọ sí ilé-ìwé náà; They barred the way to the school.
|
20231101.yo_3077_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
4. Di: v. for: Ó múra sílẹ̀ di ọjọ́ náà; He made himself ready for the day (ii) to be deaf: Etí rẹ̀ di; He is deaf (iii) run: Omi náà ti di gbígbẹ; The river has run dry (iv) bandage: Dótítà di ọwọ́ tí Olú fi pa; The doctor bandaged Olú’s cut hand.
|
20231101.yo_3077_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
5. Dín: v. (i) to fry: Ó dín ẹran; he fried meat (ii) to reduce: Ó dín owó ọjà; He reduced the price of the good (iii) discount: A ó dín ọ ní náírà mẹ́wàá; We shall give you a discount of ten naira. (iv) decline: Iye ọmọ ilé-ìwé tí ó wà níbí ti dín; There had been a decline in the number of students here.
|
20231101.yo_3077_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
6. Dó: v. (i) to settle: Ó dó sí Ìbàdàn; He settled at Ìbàdàn (ii) a vulgar language for to have sexual intercourse with: Ó dó o; He had sexual intercourse with her.
|
20231101.yo_3077_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
7. Dú: v. to slaughter: Ó dú u; He slaughtered it (ii) to darken/to blacken: Ó rẹ ẹ́ dú; he dyed it to a dark colour.
|
20231101.yo_3077_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
9. dù: v. (i) to compete for/to scramble for: Wọ́n du ipò náà; They compete for the post (ii) to deny: Ó fi ipò mi dù mí; He denied me of my post (iii) vie: Wọ́n ń du ẹ̀bùn ipò kìíní; They were vying for first prize.
|
20231101.yo_3077_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
10. Dún: v. (i) to give forth a sound: Ó dún bí ìbọn; It sounds like a gun; Ìbọn náà dún; The report of the gun was audible (ii) squeak: Ilẹ̀kùn náà dún nígbà tí mo ṣí i; The door squeaked when I opened it. (iii) ring: Fóònù ń dún; The telephone is ringing.
|
20231101.yo_3077_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
1. Fá: v. to shave: Ó fá irun rẹ̀; He shaved his hair, Ó fá ọbẹ̀ dànù; He scrapped out the remaining of the soup and threw it away.
|
20231101.yo_3077_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
2. Fẹ̀: v. (i) to expand/to enlarge: Ó ń fẹ̀; It is expanding, Ó fẹ ihò náà; he enlarged the hole (ii) to be extensive: Ó fẹ̀; It is extensive (iii) to sit relaxedly: Ó fẹ̀; He sat relaxedly (iv) broad: Èjìká rẹ̀ fẹ̀; He has a broad shoulder (v) deep: Ohùn rẹ̀ fẹ̀; He has a deep voice.
|
20231101.yo_3077_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
3. Fi: v. (i) to whirl something round: Mo fi apa mi; I swung my arm round and round (ii) to dangle: Ó ń fi dorodoro; he is dangling and oscillation to and fro (iii) to be too much: Náírà kan fi í lọ́wọ́ láti ná fún mi; Even a naira is irksome to him to spend for me (iv) wave: Ó fi agboòrùn rẹ̀; He waved his umbrella.
|
20231101.yo_3077_19
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
4. Fín: v. (i) Ó fi Sheltox fin yàrá ná; He sprays the room with Sheltox (ii) to blow: Ó fin iná; He blew the fire to make it burn up (iii) to be acceptable. Ẹbọ á fin; The sacrifice would be accepted by the deities, e.g. good-luck (iv) to cut patterns on something: Ó fín igbá; He carved patterns on the calabash.
|
20231101.yo_3077_20
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
5. Fó: v. (i) to be clear: Ilẹ̀ ti fó; The ground is clear (ii) to float: Ó fó lórí omi; It floated on the river.
|
20231101.yo_3077_21
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
6. Fun: v.(i) to blow: Ó fun fèrè; He blows the whistle (ii) to play: Wọ́n fun fèrè; They played a wood wind.
|
20231101.yo_3077_22
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/At%C3%BAm%E1%BB%8D%CC%80-%C3%88d%C3%A8%20%28Yor%C3%B9b%C3%A1-G%E1%BA%B9%CC%80%E1%BA%B9%CC%81s%C3%AC%29%3A%20Ba
|
Atúmọ̀-Èdè (Yorùbá-Gẹ̀ẹ́sì): Ba
|
3. Gẹ̀: v. (i) to cut: Ó gẹ irun; He cut his hair (ii) to pet: Ó gẹ̀ mí; He petted me (iii) to put something on in a jaunty way: Ó gẹ gèlè’ She puts on her head-kerchief in a jaunty way.
|
20231101.yo_3085_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Zangbet%E1%BB%8D
|
Zangbetọ
|
Zangbeto jẹ́ Òrìṣà àwọn ẹ̀yà Ògù ní Àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Badagry, tí wọ́n gbàgbọ́ pé ìran Yorùbá, ṣùgbọ́n tí wọ́n ṢẸ̀ wá láti orílẹ̀ èdè Olómìnira Benin àti orílẹ̀-èdè Togo. Zángbétọ́ lè jade nígbà kúgbàà tí wọ́n bá fẹ́ ṣe ọdún Òrìsà tàbí aỵẹyẹ ìbílẹ̀. ‘Zangbetọ’ jẹ́ Òrìsà tó mò n pa idán ní ọjọ́ ayẹyẹ láti yẹ́ àwọn ènìyàn sì. ‘Zangbetọ’ sì tún jẹ ààbò fún ìlú kí àwọn ọlọ́sà máa ba wọ̀lú ní òru. Tí ọ̀rọ̀ kan bá sí se pàtàkì, ‘Zangbetọ’ kan náà ni wọn yóò ran láti lọ jẹ́ irú isẹ́ bẹ́è. Tí ẹnìkan bà sì sẹ̀ tàbí lódí sí ofin ìlú, àrokò ‘Zangbetọ’ ni wọn yóò fí síwájú ilé e rẹ̀. Ẹníkẹ́ni tí wọ́n bá sì fi irú àrokò yìí síwájú ilé rẹ̀ yóò ní láti dé aàfin Ọba kí ó sì san ohun kóhun tí wọn bá ni kò san ki ó to lè wo ilé rẹ̀.
|
20231101.yo_3085_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Zangbet%E1%BB%8D
|
Zangbetọ
|
Àgbálo gbábọ̀ ọ̀rọ̀ nii ni pé àwọn ẹ̀sìn àtọ̀hunrìnwá wà ṣùgbọ́n ẹ̀sìn àbáláyé kò lè parun, nítorí pe, gbogbo àwọn Òrìsà wọ̀nyí ṣì wà síbẹ̀.
|
20231101.yo_3086_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Aye mẹ́jọ míràn bíi’rú ti wa lo n yi po káàkiri òòrùn. Àwa la ṣìkẹta táa jìnà sóòrùn, awọn méjì wà níwájú. Àwọn mẹ́fà wà lẹ́yìn wa. Mo ni òòrùn tí à ń wò lókè taa rò pé ó kéré mo ló tóbi lọ́pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà ju gbogbo ilé ayé lọ báyé yìí ṣẹ́ ń yípo òòrùn, bẹ́ẹ̀ náà lòsùpá ń yípó ayé Mo tún sọ fún wa wípé jínjìn ilé ayé sí òṣùpá tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́ọ̀rún mẹta, ó lé ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún kìlómítà 320, 000 kin. Bíi kéèyàn ó máa rin Èkó sí Ìbàdàn bíi ọ̀nà ẹgbẹ̀rún méjì bẹ́ẹ̀ náà lòṣùpá ṣe jìn sílé ayé tó téèyàn bá kúrò lórí ilẹ̀ ayé àlàfo tí ń bẹ láàrin Ilé-ayé àti òṣùpá, láàrin ilé ayé àti òòrùn láàrin ilé-ayé àti àwọn ayé mẹ́jọ tó kù lèèyàn ó kàn o, téèyàn bá ń fò lọ sókè sínú òfurufú àlàfo yìí làwọn olóyìnbó ń pè ní space ṣee mọ̀ pé bí ìgbà téèyàn bá to ǹkan ka lẹ̀ tálàfo wá wà níbẹ̀, bí Olódùmarè ṣe tàlàfo sáàrin ilé ayé àtàwọn ayé tókù, àtòòrìn àtòṣùpá rèé. Àlàfo tí à ń sọ yìí, bíi ojú sánmọ̀, ojú òfurufú ló ṣe rí ṣùgbọ́n ǹkan tí ó fi yàtọ̀ díẹ̀ ni pé kò sí atẹ́gùn nínú àlàfo yìí, kò sí kùrukùru òfuru jágédo lásán ni.
|
20231101.yo_3086_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Àjá ni wọ́n kọ́kọ́ rán sínú àlàfo tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí lọ́dún 1957 Làíkà lórúkọ tájá yìn ń jẹ́, nigba tájá yi padà tí ò kú ní wọ́n bá rán ẹnìkan ta n pe ni Yuri Gagarin lọ sínu àlàfo yìí, láti orílẹ̀èdè Russia láti mọ̀ bálàfo yì sẹ rí Yuri Gagarin lẹni àkọ́kọ́ tó kọ́kọ́ fò kúrò lórí ilẹ̀-àyé pátápátá lọ sinu àlàfo ta n pe ni space to wà láàrin Ilé ayé àtòṣùpá.
|
20231101.yo_3086_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Lẹ́yìn èyí orílẹ̀ èdè America náà bẹ̀rẹ̀ sí ní rìnrìnàjò yii Ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín orílẹ̀èdè America lọ́ sínú òṣùpá lọ́dún 1969 Neil Armstrong ati Edwin Aldrin si lẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ wọnú ọ̀sùpá. Mo sọ fun wa wipe òǹfà kan nbẹ́ ninú ilé ayé tó má n fa gbobgo ǹkan tó bá ti wà lórí ilé-ayé tàbí súnmọ́ ilé ayé mọ́ra,
|
20231101.yo_3086_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Téèyàn á bá wá kúrò lórí ilẹ̀-ayé pátápátá èàyàn gbọdọ̀ jára rẹ̀ gbà kúrò lọ́wọ́ òǹfà yìí, mọ́to téèyàn á bá lọ ó gbọ́dọ́ lágbára gidi kò sì tún lè sáré láti bori agbára ̣ òǹfà yìí, tóò ọkọ̀ tí wọ́n gbé lọ inú òṣùpá, Rọ́kẹ́ẹ̀tì ló ń jẹ́ o, Aeroplane, ò lè rin irú ìrìnàjò yí o, e wòó iṣẹ́ ọpọlọ ni wọ́n fi se rọ́rẹ́ẹ̀tì yìí, Ìpéle mẹ́ta ni wọ́n ṣe éńjínnì mọ́to yí o, Ìpéle kínní, ìpéle kejì, ìpóle kẹta lọ sókè ibi tí àwọn èèyàn dúró sí núnú rẹ̀, ó wà lórí ìpéle kẹta lókè téńté bí wọ́n ṣe to àwọn éńjìnnì yìí bíi àgbá rìbìtì léra wọn rèé tó dúró lóòró tó wá kọjú da sánmọ̀ wọ́n tún wá jẹ́ ki ọkọ yìí ṣẹnu ṣómu ṣómú ko le máa wọnú atẹ́gùn lọ sọ̀ọ̀, Orúkọ tí wọ́n fún rọ́kẹ́ẹ̀tì yìí ni wọn n pè ni Apollo 11, Apollo 11 yìí ga lọ sókè ní ìwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà ọgọ́run mẹ́ta Ààbọ̀ ó lé díẹ̀, bíi ká sọ pé ilé alája ogóji epo tí ọkọ yìí ń jẹ kèrémí kọ́ o. Kò ṣéé fẹnu sọ.
|
20231101.yo_3086_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Bíi ìgbà tèèyàn bá yin ọta ìbọn, bi wọ́ń ṣé, má n yìn-ín nuu torí ó gbọdọ̀ le sáré dáadáa kío le jára rẹ̀ gbà kúro lọ́wọ́ ̣ òǹfà tí ń bẹ lórí ilẹ̀ aye, tí wọn á bá si yin mọ́to yìí kìí séèyàn kankan ní sàkání ibẹ̀, torí ooru, èéfín àti iná nló má ń jáde ní ìdí Rọ́kẹ̀ẹ̀tì yìí.
|
20231101.yo_3086_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Àwọn tó lọ inú òṣùpá, ti wọ́n wà nínú mọ́to yìí. wọ́n dera wọn mọ́ àgá ni Àwọn tó yin rọ́kéẹ̀tí yìí sókè, wọ́n jìnnà pátápátá sí ibi tí Rọ́kẹ̀tì yìí wà, ẹ̀rọ̀ kọ̀mpútà ni wọ́n fí yìn ín bi wọ́n sẹ gbéná lé Rókẹ́ẹ̀tí yìí tí à ń pè ní Apollo 11 ni 1969 dó bá dún gbòà? lọkọ̀ bá ṣí, Ó dòkè lójú sán mọ̀ Eré burúkú kí ọkọ̀ máa sáré ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá kìlómítà láàrín wákàtí kan. 10,000km/hr irú eré tí àwọn móto má ń sá lọ́nà ẹ́spùrẹ̀sì irú eré yìí lọ́nà ẹgbẹ̀rún kan leré tí rọ́kẹ́ẹ̀tì yìí bá lọ sínú òfurufú lọhun. Láàrin ìṣẹ́jú méjì ààbọ, éńjìnnì tìpéle àkọ́kọ́ ti gbé ọkọ̀ yìí rin kìlómità ọgọrun mẹ́fà 600km. lọ sínú òfunrufú.
|
20231101.yo_3086_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Lẹ́yìn iṣẹ́jú méjì ààbọ̀ éńjìnnì tó wà ní ìpéle àkọ́kọ́ ti jó tán ó jábọ́ kúrò lára ọkọ̀ yìí, éńjìnnì tì péle kejì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ó sì gbé wọn rin ẹgbẹ̀rún méji, ó lé ni ọgọrun mẹta kìlómítà 2,300 kilometres láàrin ìṣẹ́jú mẹ́fà lọ́ sí nú òfururú lọ́ùnlọ́ùn, ẹńjìnnì ìpéle kejì jó tán òhun náà jábọ́, tipéle kẹta bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Ẹ́njìnnì tìpéle kẹta ló wá jáwọn gbà kúrò lọ́wọ́ òǹfà tí ń bẹ nínú ayé pátápátá, wọ́n sì bọ́ sínú àlàfo tí ń bẹ láàrin ilé-ayé àtoṣùpá. Nínú àlàfo yìí, ̣ òǹfà ayé ò ní pa púpọ̀ mọ́ lórí wọn Wọ́n wá sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ni rìnrìnàjò wọn lọ́ sínú òṣùpá ní ìrowọ́ ìrọsẹ̀. Nínú àlàfo tí a ńpè ní space yìí, béèyàn bá ju ̣ ǹkan ókè kìí padà wá lẹ̀ yíó dúró pa sókè ni, kó dà gan béèyàn gan fò sókè èèyàn ò ní tètè padà wálẹ̀ tórí kò sí ̣ òǹfà kan tí ó fààyàn padà nínú àlàfo yìí ṣùgbọ́n béèyàn bá dẹ́nú òṣùpá, ̣ òǹfà ń bẹ nínú òṣúpá ṣùgbọ́n àmẹ́ kò tó tayé béèyàn bá ju ǹkan sókè nínú òṣùpá naa kìí tètè padà walẹ, ẹ má gbàgbé àti nínú àfìfo tí ń bẹ láàrin ilé-ayé àtọ̀ṣùpá àti nínú òṣùpa gan-an kò sí atẹ́gùn níbẹ̀ o báwo wá làwọn tí wọ́n ń lọ inú òṣùpá ṣé má ń mí, wọ́n má ń gbé atẹ́gùn pamọ́ sínú àpò kan ni, kí wọn o le rátẹ́gùn fi mí. Tòò wọ́n dénú òṣùpá lógúnjọ́ oṣù kẹfà lọ́dún 1969 lọ́jọ̀ Sunday ọjọ ìsinmi ló bọ́ sí ẹ̀yin tẹ́ẹbá ní kàlẹ́ńdà 1969 lọ́wọ́ ẹ wòó ọjọ́ márùn-ún ni wọ́n fi rin ìrìn ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọrun mẹ́ta , ó lé ní ọgọrun lọ́nà ogún kìlómítà 320,000km lọ sí nú òṣùpá, Neil Armstrong lórukọ fẹẹ̀ ẹní tó kọkọ fi ẹsẹ tẹnú òṣùpá bó sẹ́ ń sòkalẹ̀ láti inú ọkọ̀ tí wọ́n gbé lọ óní bí ó ti lẹ̀ jẹ́pé ìgbéṣẹ̀ ti òhun gbé wọnú òṣùpá ó kéré óní ìgbésẹ̀ ńlá ni fún ìran ọmọ ènìyàn. Edwin Aldrin tí wọ́n dìjọ lọ náà sọ̀kalẹ̀ sínú òṣùpá wọ́n bá ààrẹ oríléèdè Amerika Nígbànáà ààrẹ Richard Nixon sọ̀rọ̀ pé tò àwọn tí dé nú òṣùpá o. Àwọn méjéèjì bẹ̀rẹ̀ ìwádí ti wọ́n bá lọ sínú òṣùpá wọ́n fìdíẹ̀ múlẹ̀ pé erùpè, òkúta àtàwọn òkè ń bẹ nínú òṣùpá ṣùgbọ́n kò sí ẹ̀dá alàyè tàbí ohun abẹ̀mí kan níbẹ̀.
|
20231101.yo_3086_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Inu òṣùpa tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí ọjọ́ méjì ti è oṣù kan ti wa ni ọ̀ sẹ̀ méjì gbáko lòòrùn á fi ràn. Tí gbogbo ǹkan á sì gbóná lọ́nà méjì ju omi tó ń hó lọ, ọ̀sẹ̀ méjì ni lẹ̀ tún fí má ń ṣú, gbogbo ǹkan á tún tutu lọ́nà méjì ju ice block yìnyín lọ.
|
20231101.yo_3086_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Àsìkò ìgbà tóòrùn ń ràn ni wọ́n dé bẹ̀ àmọ́ aṣọ tiwọ́n wọ̀ dábòbò wọn tóoru ò fi mú wọn pa torí wọ́n dọ́gbọ́n éńjìnnì amára tutu sínú aṣọ yìí, àwọn méjéèjì lo wákàtí méjì àtìṣẹ́jú mẹ́ta dínláàádọ́ta nínú òṣùpá wọ́n ṣàwọn ìwáàdí kéèkèè ké wọ́n ri àsìá orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà síbẹ̀, wọ́n bu yèèpè inú òṣùpá àtòkúta díẹ̀ lọ́wọ́, wọ́n sì padà, tòò àti lọ sínú òṣùpá ló le àti kúrò níbẹ̀ ò le, wọn yin ra wọn kúrò níbẹ̀ ni bi wọ́n ṣe yin ra wọn kúrò lórí ìlẹ̀ aye.
|
20231101.yo_3086_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cr%C3%ACn%C3%A0j%C3%B2%20l%E1%BB%8D%20s%C3%ADn%C3%BA%20%C3%92%E1%B9%A3%C3%B9p%C3%A1
|
Ìrìnàjò lọ sínú Òṣùpá
|
Ọjọ́ méjì ààbò ni wọ́n fi rìn padà sórílẹ̀ ayé bi wọ́n tún ṣe súnmọ́ ilé-ayẹ́ lòǹfà inú ayé bá tún bẹ̀rẹ̀ sí ní fàwọ́n, eré ni awọ́n si n bá bo láti inú òṣùpá tẹ́lè leré yìí bá tún pọ̀ si, báwo lọkọ̀ se fẹ́ bà sórí ilẹ̀ pẹ̀lú eré burúkú yìí íápọọ̀tì òtì wo ló fẹ́ bà sí wọ́n sá ṣètò kí mọ́tò yí balẹ̀ sínú òkun alagbalúgbú omi ṣẹẹ mọ̀ pé okún jìn lọ ìsàlẹ̀, omi inú òkun tún dá mọ́tò yìí dúró bíi búrèkì, tòò bi wọ́n se lọ sínú òṣùpá rèé o. Lọ́jọ́ kẹrìndínlógún oṣù keje ọdún 1969 16-7-1969 tí wọ́n sì padà sórí ilẹ̀ ayé lọ́jọ́ kẹrìnlélógún, oṣù keje kannáà lọ́dún 1969, 24-7-1969.
|
20231101.yo_3150_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Baṣọ̀run Gáà jẹ́ ìwé ìtàn eré-oníṣe tí gbajúmọ̀ oǹkọ̀wé nì, Adébáyọ̀ Fàlétí kọ. Ó dá lórí ìtàn olóyè Baṣọ̀run tí ìlú Ọ̀yọ́ tí wọ́n ń pè ní Baṣọ̀run Gáà. Ó jẹ́ afọbajẹ ní ìlú Ọ̀yọ́ láyé àtijó. Kókó inú ìwé ìtàn eré oníṣe yìí ni wípé kí a má ṣe ìkà. Ìjìnlẹ̀ èdè Yorùbá ni ònkọ̀wé náà fi kọ ìwé náà, tí ó sì gbé ìtàn rẹ̀ lé orí ìtàn gidi tí ó sì jẹ́ ojúlówó ìtàn ilé Yorùbá.
|
20231101.yo_3150_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
fi ye wa pe, Basọrun Gaa ni olori igbimọ Ọyọmesi, eyi to dabi Olootu ijọba laye ode oni, lẹyin Alaafin, tii se oriade ilu Ọyọ́, Basọrun Gaa lo tun ku.
|
20231101.yo_3150_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Ko si sẹni to le e sọ pe ti Basọrun Gaa ko jẹ eeyan gidi, wọn yoo fi jẹ oye Basọrun, to jẹ olori igbimọ lọbalọba fun Alaafin, tii se Ọyọmesi.
|
20231101.yo_3150_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Basọrun Gaa ni olori ogun Ọyọ ile ati gbajumọ ilu ni saa onka ẹgbẹrun ọdun kẹtadinlogun si ikejidnlogun, 17th/18th century
|
20231101.yo_3150_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Basọrun Gaa se gudugudu meje ati ya a ya mẹfa lati rii daju pe Ọyọ ile akọkọ di ilu nla, o lagbara, to si fẹ de ọpọ ilu ati orilẹ-ede lode oni
|
20231101.yo_3150_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Lọdun 1750 ni Alaafin Labisi yan Gaa gẹgẹ bii Basọrun, olootu ijọba ati olori igbimọ lọbalọba ẹlẹni meje fun Alaafin nilu Ọyọ ile, ti agbara si n pa Gaa bi ọti
|
20231101.yo_3150_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Ilu Ọyọ ile roju, o tuba, o tusẹ lasiko ti Basọrun Gaa joye, ti Ọyọ si maa n gba isakọlẹ lati ọpọ ilu àmọ́nà to wa labẹ rẹ
|
20231101.yo_3150_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Tọmọde-tagba nilu Ọyọ lo n bẹru, ti wọn si n bọwọ fun Basọrun Gaa, tori pe o ni oogun abẹnu gọngọ, ti asẹ rẹ si mulẹ ni aarin ilu ju Alaafin Labisi to yan an sipo lọ
|
20231101.yo_3150_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Itan sọ pe Basọrun Gaa ni oogun pupọ, to si maa n parada di ẹranko to ba wu u, to fi mọ Ẹkun, Kiniun, Igala, Ọya ati bẹẹ bẹẹ lọ
|
20231101.yo_3150_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Ni kete ti Gaa di Basọrun ni Ọyọ ile lo pa meji ninu awọn ọrẹ imulẹ Alaafin Labisi, eyi to dun ọba naa de egungun, to si gba ẹmi ara rẹ lọdun 1750 naa
|
20231101.yo_3150_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Alaafin Awọnbioju lo jẹ Alaafin lẹyin Labisi, sugbọn niwọn igba toun naa kọ lati gba itọni lọdọ Basọrun Gaa, aadoje ọjọ pere lo lo lori itẹ ti Gaa fi ni ki wọn yẹju rẹ
|
20231101.yo_3150_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Alaafin Agboluaje to jẹ lẹyin Awọnbioju tiẹ ri ijọba se n tiẹ, tori o n gbọrọ si Basọrun Gaa lẹnu, sugbọn ọwọ Basọrun Gaa naa ni ẹmi rẹ papa bọ si
|
20231101.yo_3150_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Lọdun 1774 ni Alaafin Abiọdun gori itẹ, to si n wọna bi yoo se rẹyin Basọrun Gaa, ko lee roju se aye, sugbọn Gaa pa ọmọbinrin Alaafin Abiọdun, Agbọrin, nigba to nilo ẹranko Agbọnrin, to si ni orukọ wọn jọra
|
20231101.yo_3150_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Ọrọ naa dun Abiọdun to bẹẹ, to si beere fun atilẹyin Onikoyi, ati aarẹ Ọna Kakanfo to jẹ nigba naa, Ọyalabi lati ilu Ajasẹ ipo, ki wọn lee tete rẹyin Basọrun Gaa
|
20231101.yo_3150_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Alaafin Abọdun kọkọ yọ ibẹru Gaa kuro lọkan awọn araalu, to si jẹ ki ibinu rẹ maa ru jade ni inu wọn, titi ti Basọrun Gaa fi rọ lapa, rọ lẹsẹ
|
20231101.yo_3150_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Lọdun 1774, ẹgbẹlẹgbẹ awọn eeyan Ọyọ ile ya bo agboole Basọrun Gaa, ti wọn si wọ ọ lọ si ọja Akẹsan, ki wọn to sun un nina gburugburu, bẹẹ ni wọn pa a tọmọtọmọ, wọn jẹ ile Gaa run patapata
|
20231101.yo_3150_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Sugbọn ori ko akọbi rẹ, Ojo Aburumaku yọ ninu wahala yii, to si sa lọ si ilẹ Ibariba, eyi to fopin si aye fami lete ki n tutọ ti Basọrun Gaa ati idile rẹ n jẹ
|
20231101.yo_3150_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Sugbọn iku Basọrun Gaa se akoba nla fun ijọba Ọyọ akọkọ, tori lẹyin iku Gaa ni ẹdinku ba bi awọn ọmọ ogun rẹ ti dangajia si ati agbara ilu naa, tawọn ilu kan si n sa kuro labẹ rẹ, titi ti Ọyọ ile akọkọ fi tu lọdun 1836.
|
20231101.yo_3150_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/Ba%E1%B9%A3%E1%BB%8D%CC%80run%20G%C3%A1%C3%A0
|
Baṣọ̀run Gáà
|
Adebayo Faleti (1972), Basorun Gaa. Ibadan, Nigeria: Onibon-oje Press and Book Industries (Nig) Ltd. Oju-iwe = 149.
|
20231101.yo_3157_0
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nàìjíríà () jẹ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà (Nigeria ni èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ olómìnira tí ó ní ìjọba ìpínlẹ̀ mẹ́rindínlógójì tó fi mọ́ Agbẹ̀gbẹ̀ Olúìlú Ìjọba Àpapọ̀. Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wà ní apá Iwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Áfríkà. Orílẹ̀-èdè yí pààlà pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Benin ní apá ìwọ̀ Oòrùn, ó tún pààlà pẹ́lú orílẹ̀-èdè olómìnira ti Nijẹr ní apá àríwá, Chad àti Kamẹróòn ní apá ìlà Oòrùn àti Òkun Atlantiki ni apá gúúsù. Abuja ni ó jẹ́ Olú-Ìlú fún orílẹ̀-èdè náà. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Nàìjíríà ní ẹ̀yà púpọ̀, àwọn ẹ̀yà mẹ́ta ni wọ́n hànde tí wọ́n tóbi jùlọ, tí wọ́n sì pọ̀ jùlo, tí a sì kó àwọn ẹ̀ka ìsọ̀rí ìsọ̀rí èyà tókù sí abẹ́ wọn. Àwọn wọ̀nyí ni Ẹ̀ya Hausa, Ẹ̀ya Ìgbò ati Yorùbá.
|
20231101.yo_3157_1
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìtàn fífẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹ̀rí ìmọ̀-aíyejọ́un fihàn pé àwọn ìgbé ènìyàn ní agbègbè ibẹ̀ lọ sẹ́yìn dé kéré pátápátá ọdún 9000 kJ. Agbegbe Benue-Cross River jẹ́ rírò gẹ́gẹ́ bí ile àkókó àwọn Bantu arókèrè ti wón fán káàkiri òpó ààrin àti apágúúsù Áfríkà bí irú omi ní ààrin ẹgbẹ̀rúndún akoko àti ẹgbẹ̀rúndún kejì.
|
20231101.yo_3157_2
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Orúkọ Nàìjíríà wá láti Odò Ọya, tí a tún mọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Odò Náíjà, èyí tó sàn gba Nàìjíríà kọjá. Flora Shaw, tí yíò jẹ́ ìyàwó lọ́jọ́ wájú fún Baron Lugard ará Britan tó jẹ́ alámójútó àmúsìn, ló sẹ̀dá orúkọ yìí ní òpin ọdún 1897.
|
20231101.yo_3157_3
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nàìjíríà ni orílẹ̀-èdè tó ní èèyàn púpò jùlọ ní Ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú, ikejo ni agbaye, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ orílẹ̀-èdè tó ní àwọn eniyan alawodudu jùlọ láyé. Ó wà lára àwọn orílẹ̀-èdè tí a ń pè ní "Next Eleven" nítorí okòwò wọn, ó sì tún jẹ́ ọ̀kan nínú Ajoni àwọn Ibinibi. Okòwò ilẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn èyí tó ń dàgbà kíákíá jùlọ lágbàáyé pẹ̀lú IMF tó ń gbèrò ìdàgbàsókè 9% fún 2008 àti 8.3% fún 2009. Ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 2000 sókè, ogunlọ́gọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà gbé pẹ̀lú iye tó dín ní US$ 1.25 (PPP) lójúmọ́. Nàìjíríà ní okòwò rẹ̀ tóbi jùlọ ní Áfíríkà, ati alágbára ní agbègbè Iwoorun Afirika.
|
20231101.yo_3157_4
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Àwọn ará Nok ní ààrin Nàìjíríà se ẹ̀re gbígbẹ alámọ̀ tí àwọn onímọ̀ ayéejọ́un tí wárí. Ère Nok tó wà ní Minneapolis Institute of Arts, júwè é ẹni pàtàkì kan mú "Ọ̀pá idaran" dání ní owó ọ̀tún àti igi ní owó òsì. Ìwònyì ní àmì-ìdámọ̀ aláse tó jẹ́ bíbásepọ̀ mò àwọn fáráò ilè Egypti ayéejọ́un àti òrìṣà, Oṣíriṣ, èyí lo n so pé irú àwùjọ, idimule, bóyá àti ẹ̀sìn ilè Egypti ayeijoun wà ní agbẹ̀gbẹ̀ ibi tí Nàìjíríà wà lónìí ní ìgbà àwọn Fáráò.
|
20231101.yo_3157_5
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní apá àríwá, Kano àti Katsina ní ìtàn Àkọsílè tí ọjọ́ wón dẹ́yìn tó bí ọdún 999 kJ. Àwọn ìlú-ọba Haúsá àti Ilé-ọba Kanem-Bornu gbòòrò gẹ́gẹ́ bí ibùdó ajẹ́ láàrin Àríwá àti Ìwọ̀ọòrùn Áfríkà. Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún 19sa lábé Usman dan Fodio àwọn ará Fúlàní di àwọn olórí Ilé-ọba Fúlàní lójúkan èyí tó dúró bayi títí di 1903 nígbàtí wọn jẹ́ pínpín láàrin àwọn àlámùúsìn ará Europe. Láàrin 1750 àti 1900, ìdá kan sí ìdá méjì nínú meta àwọn oníbùgbẹ́ àwọn ìlù Fúlàní jẹ́ eru nítorí ogun.
|
20231101.yo_3157_6
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Àwọn Yorùbá ka ọjọ́ tí wọ́n ti wà ní agbègbè Nàìjíríà, Benin àti Togo ayéòdeòní sẹ́yìn dé bí ọdún 8500 kJ. Àwọn Ìlú-ọba Ifẹ̀ àti Ọ̀yọ́ ní apá Ìwòòrùn Nàìjíríà gbalẹ̀ ní 700-900 àti 1400 ní sísẹntẹ̀lé. Síbẹ̀síbẹ̀, ìtàn àríso Yorùbá gbàgbọ́ pé Ilé-Ifẹ̀ ni orísun ẹ̀dá ènìyàn pe bẹ́ẹ̀ sì ni ó síwájú àsà-ọ̀làjú míìràn. Ifẹ̀ sẹ̀sọ́ ère alámọ̀ àti onítánganran, Ìlú-ọba Ọ̀yọ́ si fẹ̀ de ibi tí Togo wà loni. Ìlú-ọba míìràn tó tún gbalẹ̀ ní gúúsù apáìwòọ̀rùn Nàìjíríà ní Ìlú-ọba Benin láti ọ̀rúndún 15ru 19sa. Ìjọba wọn dé Ìlú Èkó kí àwọn ara Portugal ó tó wá sọ ibẹ̀ di "Lagos."
|
20231101.yo_3157_7
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní apá gúúsù ìlà-oòrùn Nàìjíríà, Ìlú-ọba Nri tí àwọn Igbo gbòòrò láàrin ọ̀rúndún 10wa títí de 1911. Eze Nri ni ó jọba Ìlú-ọba Nri. Ilu Nri jẹ́ gbígbà gẹ́gẹ́ bí ìpilèsè àsà ígbò. Nri àti Aguleri, níbi ti ìtàn àrísọ ìdá Igbo ti bẹ̀rẹ̀, wà ní agbẹ̀gbẹ̀ ìran Umueri, àwọn tí wọ́n sọ pé ìran àwọn dé ilẹ̀–ọba Eri fúnra rẹ̀.
|
20231101.yo_3157_8
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Àwọn Portuguese Empire ni wọ́n jẹ́ ará Europe àkọ́kọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ìsòwò ní Nàìjíríà tí wọ́n sì sọ èbúté Eko di Lagos tí wọ́n mú látara orúkọ ìlú Lagos ní Algarve. Orúkọ yìí lẹ̀ mọ́bẹ̀ bí àwọn ará Europe míìràn náà ṣe bẹ̀rẹ̀ síní sòwò níbẹ̀. Àwọn ará Europe ṣòwò pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà abínibí ní ẹ̀bá–odò, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ owo eru níbẹ̀, èyí tó pa ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀yà abínibí Nàìjíríà lára. Lẹ́yìn tí ogun Napoleon bẹ̀rẹ̀, àwọn ará Britani fẹ ìsòwò dé àárín Nàìjíríà.
|
20231101.yo_3157_9
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ni 1885, ìgbẹ́sẹ̀lé Ìwọ̀oòrùn Áfríkà látọ́wọ́ àwọn ará Britain gba ìdámọ̀ káríayé. Nígbà tó sì di ọdún tó tẹ̀lé e, ilé-iṣẹ́ Royal Niger Company jẹ́ híháyà lábẹ́ Sir George Taubman Goldie. Ní 1900, àwọn ilẹ̀ tí ilé-iṣẹ́ yìí ní di ti ìjọba Britain.
|
20231101.yo_3157_10
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ni January 1901, Nàìjíríà di sísọ–di–ọ̀kan gẹ́gẹ́ bíi ìlànà àláàbò. Nàìjíríà sì di ara Ilẹ̀–ọbalúayé Britain tó wà lára alágbára nígbà náà.
|
20231101.yo_3157_11
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní 1914, àgbègbè náà di sísọ-di-ọ̀kan gẹ́gẹ́ bíi Ìmúsìn àti Aláàbò ilẹ̀ Nàìjíríà (Colony and Protectorate of Nigeria). Fún àmójútó, Nàìjíríà di pínpín sí ìgbèríko apá-àríwá, apá-gúúsù àti Ìmúsìn Èkó. Okòwò ayé òde òní tẹ̀̀ síwájú ní wàrànsesà ní gúúsù ju ní àríwá lọ, ipa èyí hàn nínú ayé olóṣèlú Nàìjíríà òde òní. Ní ọdún 1936 ni òwò ẹrú ṣẹ̀ṣẹ̀ di fífòfin lù.
|
20231101.yo_3157_12
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Lẹ́yìn Ogun Agbaye Eleekeji gẹ́gẹ́ bíi èsì fún ìdàgbà isonibinibi Nàìjíríà àti bíbéèrè fún òmìnira, àwọn ìlànà–ìbágbépọ̀ tó rọ́pò ara wọn tí wọ́n jẹ́ sísọdòfin látowọ́ Ìjọba Britain mú Nàìjíríà súnmọ́ Ijoba-ara-ẹni tó dúró lórí aṣojú àti àpapọ̀. Nígbà tó fi di àárín ọ̀rúndún 20ji, ìjàgbara fún òmìnira jà káàkiri Áfríkà.
|
20231101.yo_3157_13
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní ọjọ́ kìíní, oṣù Ọ̀wàrà, ọdún un 1960, Nàìjíríà gba òmìnira lọ́wọ́ orílè-èdè Sisodokan Ilu-oba. Ilẹ̀ Olómìnira tuntun yìí mú kí ọ̀pọ̀ nínú àwọn ọmọ orílè-èdè kí ẹ̀yà tiwọn ó jẹ́ èyí tó lágbára jù lọ. Ìsèjọba àwa-ara-wa Nàìjíríà tuntun jẹ́ àjọ̀sepọ̀ àwọn ẹgbẹ́.
|
20231101.yo_3157_14
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nigerian People's Congress ni ẹgbẹ́ tí àwọn ará Àríwá tí wọ́n tún jẹ́ Mùsùlùmí ń darí.smi ti Ahmadu àello ati Abubakar Tafawa Bewa to di Alakosoàkọ́kọ́ ẹ́yì òmìnira. Àti ẹgbẹ́ èyítiAlákòóso Àgbà ti awon tíỌmọ Ígbòwọ́n jẹ́ ẹlẹ́sìn Kìrìstẹ́nì ń jẹ́ ìdarí National Council of Nigeria and the Cameroons , NíNC) ti Nnamdi Aie, to di Gomina-bínibíaàkọ́kọ́ ní ko ni 1960,órí olí i.òNi átakòlataẹgbẹ́iìlọsíwájúsiwaju Action Groupwà,Ati àwọn Yorùbá ti Obafemi Awṣe woórí olori.
|
20231101.yo_3157_15
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ìpinnu ọdún 1961 fún Apáagúúsù Kameroon láti darapọ̀ mọ́ orílè-èdè Kameroon nígbàtí Apáàríwá Kameroon dúró sí Nàìjíríà fa àìdọ́gba nítorí pé apá àríwá wá tóbi ju Apáagúúsù lọ gidigidi. Nàìjíríà pínyà lọ́dọ̀ Britani pátápátá ní 1963 nípa sísọ ara rẹ̀ di ilẹ̀ Apapo Olominira, pẹ̀lú Azikiwe gẹ́gẹ́ bi Aare àkọ́kọ́. Rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ ní Agbegbe Apaiwoorun lẹ́yìn ìbò 1965 nígbà tí i Nigerian National Democratic Party gba ìjọba ibẹ̀ lọ́wọ́ ọ AG.
|
20231101.yo_3157_16
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Àìdọ́gba yìí àti ìbàjẹ́ ètò ìdìbòyàn tí olóṣèlú fà ní 1966 dé àwọn ìfipágbajọba ológun léraléra. Àkọ́kọ́ ṣẹlẹ̀ ní Oṣù Ṣẹrẹ ti àwọn ọ̀dọ́ olóṣèlú alápáòsì lábẹ́ ẹ Major Emmanuel Ifeajuna àti Chukwuma Kaduna Nzeogwu. Ó kù díẹ̀ kó yọrí sí rere - àwọn olùfipágbàjọba pa Alákòóso Àgbà, Sir Abubakar Tafawa Balewa, Asolórí Agbègbè Apáàríwá Nàìjíríà, Sir Ahmadu Bello, ati Asolórí Agbègbè Apáìwọ̀oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, Sir Ladoke Akintola. Bó tilẹ̀ jẹ́ báyìí, síbẹ̀síbẹ̀, àwọn olùfipágbàjọba náà kò le bẹ̀rẹ̀ síní ṣe ìjọba nítorí ìṣòro bí wọn yíó ti ṣé, nítorí èyí Nwafor Orizu, adelédè Ààrẹ jẹ́ mímú dandan láti gbé ìjọba fún Ile-ise Ologun Adigun Naijiria lábẹ́ ẹ Apàṣẹ Ọ̀gágun JTY Aguyi-Ironsi.
|
20231101.yo_3157_17
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Òfin Ṣẹ̀ríà; tó wá láti inú òfin Ẹ̀sìn Islam, tí wọ́n sì ń lò láwọn Ìpínlẹ̀ tó wà lápá Àríwá Nàìjíríà.
|
20231101.yo_3157_18
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní kété tí ó gba òmìnira ní 1960, Nàìjíríà sọ Ìsọ̀kan Áfríkà di ààrin-gbùngbùn òfin òkèèrè rẹ̀, Ó sì kópa ńlá nínú u ìgbógun ti ìjọba Ìyàsọ́tọ̀-Ẹlẹ́yàmẹ̀yà ní South Africa. Ìyapa kan kúrò ni ìbáṣepọ̀ pẹ́kípẹ́kí tí Nàìjíríà bá Israel ṣe yípo gbogbo 1960s. Israel sonígbọ̀wọ́ àti àmójútó fún kíkọ́ àwọn ilé asòfin Nàìjíríà.
|
20231101.yo_3157_19
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Òfin Òkèère Nàìjíríà rí ìdánwò ní 1970s lẹ́yìn tí orílẹ̀-èdè náà jáde kúrò nínú Ogun Abẹ́lé nísọ̀kan. Ó dúró ti àwọn akitiyan tó lòdì sí ìjọba àwọn òyìnbó péréte ní ẹkùn Gúúsù Áfríkà. Nàìjíríà dúró ti ẹgbẹ́ ẹ African National Congress pẹ̀lú u bó ṣe pọkàn pọ̀ nínú ìpinnu rẹ̀ nípa ìjọba South Africa àti àwọn ipa ológun wọn ní Gúúsù Áfríkà. Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀dádáálẹ̀ ẹgbẹ́ ẹ Organisation for African Unity (tó di African Union) Ó sì ti ní ipa tó kàmọ̀nmọ̀ ní Ìwọ̀oòrùn Áfríkà àti ní Áfríkà lápapọ̀. Nàìjíríà ṣe akitiyan ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní Ìwọ̀oòrùn Áfríkà, ó sì tún ṣe aṣáájú fún Economic Community of West African States (ECOWAS) àti ECOMOG (pàápàá nígbà ogun abẹ́lé ní Liberia àti Sierra Leone) – tí wọ́n jẹ́ ẹgbẹ́ ọrọ̀-ajé àti ti ológun ní sísẹntẹ̀lé.
|
20231101.yo_3157_20
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Pẹ̀lú ìdúró tó so mọ́ Áfríkà yí, Nàìjíríà rán àwọn ikọ̀ lọ sí Congo ní ìtẹ̀lé àṣẹ Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè kété lẹ́yìn òmìnira (ó sì ti jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ láti ìgbà náà). Nàìjíríà tún ṣe ìtìlẹyìn fún orísìírísìí ẹgbẹ́ ẹ Áfríkà àti àwọn ìdìde fún ìjọba tiwa-n-tiwa ní àwọn 1970s, tó fi mọ́ kíkó ìtìlẹyìn jọ fún MPLA ní Angola àti SWAPO ní Namibia, àti ṣíṣe ìtìlẹyìn fún àtakò sí àwọn ìjọba eléèyan pérété ti àwọn Potogí ní Mozambique àti Rhodesia. Nàìjíríà sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Non-Aligned Movement. Ní ìparí oṣù Belu ní 2006, Nàìjíríà ṣe àkójọ ìpàdé e Áfríkà àti Gúúsù Amẹ́ríkà ní Abuja láti fi gbé nǹkan tí àwọn olùkópa kan pè ní ìbáṣepọ̀ "Gúúsù–Gúúsù" lórísirísìí ọ̀nà lárugẹ. Nàìjíríà tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ilé-Ẹjọ́ Ìwàọ̀daràn Káríayé àti Àjọni àwọn Orílẹ̀-èdè . Wọ́n yọọ́ kúrò nínú u tàsọgbẹ̀yìn fún ìgbà díẹ̀ ní 1995 nígbà ìṣèjọba Abacha.
|
20231101.yo_3157_21
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nàìjíríà ti jẹ́ olùkópa takuntakun nínú ọjà epo àgbáyé láti 1970s,ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹ OPEC, èyí tó darapọ̀ mọ́ ní 1971. Ipò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òǹtà epo gbòógì jẹyọ nínú àwọn ìbáṣepọ̀ mímì pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tó ti dàgbà sókè, pàápàá Amẹ́ríkà, àti pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tó ṣì ń dàgbà sókè.
|
20231101.yo_3157_22
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Láti 2000, ìsòwò láàrin Ṣáínà-Nàìjíríà ti ga sókè sí i. Ìpọ̀síi nínú u òwò ti lé ní mílíọ̀nù 10,384 dọ́là láàrin orílẹ̀-èdè méjèèjì láàrin 2000 sí 2016. Àmọ́, òwò láàrin Sáínà àti Nàìjíríà ti di ọ̀rọ̀ òṣèlú ńlá fún Nàìjíríà. Èyí jẹyọ nínú u pé ìtàjáde àwọn Sáínà jẹ́ ọgọ́rin nínú u ọgọ́rùn-ún gbogbo òwò. Èyí mú àìdọ́gba wá, pẹ̀lú u bí Nàìjíríà ṣe ń kó ọjà ìlọ́po mẹ́wàá wọlé ju ti Sáínà lọ. Bẹ́ẹ̀, ọrọ̀-ajé Nàìjíríà ti ń farati àwọn ìkówọlé ọjà olówó-pọ́ọ́kú láti fi gbéra, èyí sì mú ìdínkù wá nínú u Ìsòwò Nàìjíríà lábẹ́ irú ètò bẹ́ẹ̀.
|
20231101.yo_3157_23
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ní ìtẹ̀síwájú pẹ̀lú u òfin òkèèrè tó so mọ́ Áfríkà, Nàìjíríà mú àbá wá fún níná owó kan náà ní Ìwọ̀oòrùn Áfríkà tí á máa jẹ́ Eco lábẹ́ ẹ èrò pé náírà ló máa wò ó dàgbà ṣùgbọ́n ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù Ọ̀pẹ, 2019; Ààrẹ Alassane Ouattara ti Ivory Coast pẹ̀lú u Emmanuel Macron àti púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè UEMOA, kéde pé àwọn kàn máa yí orúkọ CFA franc padà ní kàkà kí àwọn rọ́pò rẹ̀ bí wọ́n ṣe rò tẹ́lẹ̀. Ní 2020, wọ́n ti gbé ètò owó o Eco náà tì di 2025.
|
20231101.yo_3157_24
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ojúṣe àwọn ológun Olómìnira Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà ni láti dáàbò bo ilẹ̀ Nàìjíríà, gbígbésókè ìjẹlógún àbò Nàìjíríà àti ìtìlẹyìn ìtiraka ìgbèrò àlàáfíà àgàgà ní Ìwọ̀oòrùn Áfríkà.
|
20231101.yo_3157_25
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Iṣẹ́ ológun Nàìjíríà ní Ilé-Isẹ́ Ológun Akogun,Ilé-Isẹ́ Ológun Ojú Omi, àti Ilé-Isẹ́ Ológun Ojú Afẹ́fẹ́.
|
20231101.yo_3157_26
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà,Ilé-Isẹ́ Ológun Nàìjíríà ti kópa nínú Ìgbèrò Àlàáfíà ní Áfríkà. Ilé-Isẹ́ Ológun Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí i ìkan nínú ECOMOG ti kópa gẹ́gẹ́ bí i olùfbèrò àlàáfíà ní Liberia ní 1990, Sierra Leone ní 1995, Ivory Coast àti Sudan.
|
20231101.yo_3157_27
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nàìjíríà wà ní apá Ìwọ̀oòrùn Áfríkà ní Ikun-omi Guinea, àpapọ̀ ilẹ̀ ẹ rẹ̀ sì fẹ̀ níwọ̀n 923,768 km2 (356,669 sq mi), èyí jẹ́ kó jẹ́ orílẹ̀-èdè 32ji tó tóbi jù lọ lágbàáyé lẹ́yìn in Tanzania. Ibodè rẹ̀ pẹ̀lú Benin tó 773 km, ti Niger tó 1497 km, ti Chad tó 87 km àti ti Kamẹrúùnù tó 1690 km; bákan náà àlà etí-odò rẹ̀ tó 853 km. Ibi tó ga jù lọ ní Nàìjíríà ni Chappal Waddi ní 2419 m (7936 ft). Àwọn odò gbangba ibẹ̀ ni Odo Oya àti Odo Benue tí wọ́n já pọ̀ ní Lokoja, láti ibi tí wọ́n ti sàn lọ sínú Okun Atlantiki láti Delta Naija.
|
20231101.yo_3157_28
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Bákan náà, Nàìjíríà jẹ́ gbọ̀ngán pàtàkì fún orísìírísìí ẹranko àti nǹkan abẹ̀mí pàtàkì. Agbègbè tó ní àwọn orísìírísìí labalaba jùlọ láyé ni agbègbè Calabar ní Ipinle Cross River. Àwọn ọ̀bọ agbélẹ̀ ń gbé ní Gúúsù-Ìlà-oòrùn Nàìjíríà àti Kamẹrúùnù nìkan.
|
20231101.yo_3157_29
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ojúilẹ̀ Nàìjíríà jẹ́ orísìírísìí. Ní Gúúsù, ojú-ọjọ́ jẹ́ ti ojoinuigbo amuooru níbi tí òjò ọdọọdún tó 60-80 inches (1,524 — 2,032 mm) lọ́dún. Ní apá gúúsù-ìlà-oòrùn ní Àwọn Ìwúlẹ́ Obudu wà.
|
20231101.yo_3157_30
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Nàìjíríà jẹ́ pípín sí mẹ́rìndínlógójì ipinle 36 pọ̀mọ́ Agbègbè Olúìlú Àpapọ̀ kan; àwọn wọ̀nyí náà jẹ́ pípín sí agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ 774.
|
20231101.yo_3157_31
|
https://yo.wikipedia.org/wiki/N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
|
Nàìjíríà
|
Ìlú mẹ́fà ní Nàìjíríà ni àwọn oníbùgbé tó tó ẹgbẹẹgbẹ̀rún kan tàbí púpọ̀ jùlọ: Èkó, Kano, Ibadan, Kaduna, Port Harcourt àti Benin.
|
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.